Eya Yoruba World TV

Eya Yoruba World TV Ẹ káàbọ̀ sí Ìkànnì Ẹ̀yà Yorùbá World TV fún ìgbélárugẹ àwùjọ Yorùbá. E ó ní àǹfàní láti mọ́ nípa àṣà Yorùba.

OGUN ÌDÍLÉ LÓ PA TAIWO HASSAN OGOGO — Obìnrin tó jẹ́ mọ̀lẹ́bí rẹ̀ sọ ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ìdílé wọnNínú fídíò yìí, a gbé ọ...
26/08/2026

OGUN ÌDÍLÉ LÓ PA TAIWO HASSAN OGOGO — Obìnrin tó jẹ́ mọ̀lẹ́bí rẹ̀ sọ ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ìdílé wọn

Nínú fídíò yìí, a gbé ọ̀rọ̀ kan tó ń fa ìjíròrò jáde nípa Taiwo Hassan Ogogo kalẹ̀. Obìnrin kan tó sọ pé ó jẹ́ mọ̀lẹ́bí rẹ̀ ṣe àlàyé nípa ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ìdílé wọn àti àwọn ọ̀rọ̀ tó yí ìṣẹ̀lẹ̀ náà ká.

Kí ni ó ṣẹlẹ̀ gan-an? Kí ni obìnrin náà sọ nípa ìdílé wọn? Ṣé òtítọ́ ni gbogbo ohun tó ń lọ káàkiri?

Wo fídíò náà títí dé òpin láti gbọ́ gbogbo àlàyé náà, kí o sì fi èrò rẹ sílẹ̀ nínú àpótí ìdáhùn.

https://youtu.be/WuiMzAYAbUk

25/08/2026

ÌRÒYÌN NÍ ṢÓKÍ
Kí ló dé tí ìjọba àpapọ̀ yọwọ́ Makinde kúrò níbi ìfilọ́lẹ̀ òpópónà Ibadan sí Ijebu-Ode? Ohun tí a mọ̀ rèé

A ki gbogbo ẹ̀yin olólùfẹ́ Ẹya Yoruba World Tv  to jẹ Mùsùlùmí ku ọjọ́ ibi Anabi Muhammad.
25/08/2026

A ki gbogbo ẹ̀yin olólùfẹ́ Ẹya Yoruba World Tv to jẹ Mùsùlùmí ku ọjọ́ ibi Anabi Muhammad.

25/08/2026

Ọjọ ti asiri mi fẹ tu, Ogogo Bomi Lasiri - Agba Osere Yemi Elesho

ÌWÚRE                                         Ègún ìdílé kòní borí wa 💬 Tẹ “Àmín” tí o bá gbàgbọ́.
25/08/2026

ÌWÚRE
Ègún ìdílé kòní borí wa 💬 Tẹ “Àmín” tí o bá gbàgbọ́.

25/08/2026

Ki Ọlọhun tẹ Alhaji Hassan Ogogo si afẹfẹ rere.

25/08/2026

Asiko ti wọn n bu yepe si saare Hassan Ogogo

Aworan nibi isinku Agba Osere to doloogbe Taiwo Hassan Ogogo  📷
25/08/2026

Aworan nibi isinku Agba Osere to doloogbe Taiwo Hassan Ogogo
📷

25/08/2026

Asiko ti Awọn Ọdẹ ibile n yin Ibọn
nibi isinku Ogogo.

Address

1 Thanes Villa, Sister's Road, Finsbury Park
London
N77PH

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Eya Yoruba World TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share