Iwe Iroyin Atijo/ oldest News Papers

Iwe Iroyin Atijo/ oldest News Papers Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Iwe Iroyin Atijo/ oldest News Papers, Media/News Company, Abeokuta, Abeokuta.

Ohun Ako sile koni tanOro taba foni so n bo wa di itan
06/01/2025

Ohun Ako sile koni tan
Oro taba foni so n bo wa di itan

Osimhen Agbabolu se oore fun Akanda laija lole ara, o kole funSe eleyi ose re, Amo Pedepede towa ja Akanda lole Ara lais...
14/11/2024

Osimhen Agbabolu se oore fun Akanda laija lole ara, o kole fun
Se eleyi ose re,
Amo Pedepede towa ja Akanda lole Ara laise nkan Kobo fun, teni ta gboju okunle ti kowa Jo eni agba, awon mejeji ta ladura tosi

14/03/2024
AFRICAN DEMOCRACY:    MYTH OR REALITYDAILY TIMES, SATURDAY, 13TH, MARCH, 1979, PRICE: 10KOBO----------------------------...
14/03/2024

AFRICAN DEMOCRACY:
MYTH OR REALITY
DAILY TIMES, SATURDAY, 13TH,
MARCH, 1979, PRICE: 10KOBO
--------------------------------------------------------
Chief Obafemi Awolowo the Federal Opposition leader in the first Republic of Nigeria said
What are the criteria that determine the existence of a healthy democracy within the state?
Firstly: there must be an assurance of the freedom of speech of the person and of public meeting, albeit within the framework of the law. In general, there needs be in existence the fundamental human rights.

Secondly: Decisions and policies must be formed by appeal to reason in open details.

Thirdly: Political sovereignty of the masses is essential; that is administration must be accountable to the people. A government which prolongs it's terms in office kills the political consciousness of the governed. Then totalitarianism is enthroned.

If you want full details go and check it. The full details is inside the holdest news paper page 19, of Daily times Saturday March 13th 1976.
My people try to do something good today because of next tommorow when people come to use your words.

Do you like this 🛏️ Bed
12/03/2024

Do you like this 🛏️ Bed

Gorgeous 😍

BOLARINWA YO LOWO IKU OJIJIIWE IROYIN IMOLE OWURO 20/11/1965---------------------------------------------------------Loj...
12/03/2024

BOLARINWA YO LOWO IKU OJIJI
IWE IROYIN IMOLE OWURO 20/11/1965
---------------------------------------------------------
Lojo (Thursday) tise ojo kejidinlogun osu kokanla odun 1965 ni oriko Adajo S. B. Bolarinwa ti Ile ejo Grade B, Mapo, ni ibadan yo nibiti janduku egbe kan nigba naa i ba ti fi ibon pa Adajo yii si inu Ile ejo naa lapafon.

Gege bi iroyi ti iwe Iroyin Imole Owuro gbe jade lojo naa se koo
Oni Ogbeni Peter Ige omo ogun odun je okan ninu awon janduku egbe oselu kan ti awon olopa ko ni Moor Plantation, Ibadan ninu ose tokoja, larin ose naa ni won kowon lo si Ile ejo ki won to duro fun won

Lojo kejidinlogun ti igbejo bere leni toduro fun ogbeni Peter ba fa owo re yo pe oun koduro mo, eyi lomu ki Adajo Bolarinwa fun arufin yii laaye lati wa oniduro miran.
Amo larin ibi ti odaran yii ti n wa oniduro nibe loti n dogbon ti owo bo apo, sugbon ti olopa CPL 96 Y. to tele nwo pe irin re ti n yato, o teju mo, bi arufin yi ti n mu owo Jade ijafara lewu fifa tio fa ibon yo ki ina dun lori Adajo ni olopa yi ba sare dii lowo mu, ti osi lo lowo seyin, eyi ti won fi gba ibon owo re.

Eyi lomu ki Adajo pase pe ki won lo so odaran Peter Ige si inu Ogba ewon Agodi. Lojo naa ni ofin ati ase pe ki awon olopa ma sayewo gbogbo ara arufin ki won to mu wo Ile ejo. Eo ri pe o gbenu tan
Ohun te se lano, itan ni loni o, eje ka sora wa o.

Mo ki gbogbo eyin ololufe Baba olomiogbon 1 pe eku aduroti mi nigba gbogbo. Eledumare koni kodi aimose siyin be leo ni w...
12/03/2024

Mo ki gbogbo eyin ololufe Baba olomiogbon 1 pe eku aduroti mi nigba gbogbo.
Eledumare koni kodi aimose siyin be leo ni wa owo ti. Ejo ebami gbaruku ti ikanni yi tape ni Iwe iroyin Atijo.
Nibi taoti ma lo mu awon isele togbenu tan abi eyi tarope kolesele sugbon toti sele seyin wa fun yin..... Koko oun tafe fi ikanni yii fayo nipe kasora pelu iwa wa tori iwa taba hu ti iwe Iroyin ba tigbe boje iro abi ododo kole pare o. Ema bawa dasi kalejo mo pe ise lanse katori awon iwe iroyin Yi. O ya eje kalo

Address

Abeokuta
Abeokuta

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Iwe Iroyin Atijo/ oldest News Papers posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share