Oloburo Kayefi Tv

Oloburo Kayefi Tv Oloburo Afopina Tv is an indigenous broadcasting organization for the promotion, retention and preservation of Yoruba language, culture, history and heritage.

This page doesn’t support violence or vulgar languages.. Thank You!

23/08/2026

Aboruaboye fun gbogbo babalawo odun isese 2026 ni ipinle ogun egbe sorosoro aladani fiban pe apero lori oro esin asa ati awon eto toromo labe afin baba elebuibon komisona olopa ni ipinle ogun ati agbejoro ton imole topo si awon eto toromo oro esin ati asawa nile kootuojire

13/08/2026

Idibo sipo gomina ni ipinle osun aare tinubu o ron enikeni nise lati lo daluru, efi gbogbo awon onipolongo ibo pakaleke jofin eyin odo esorayin kemabaadero ekwon

03/08/2026

Ominu aiye nkomi eru aye nbami eje ka gbeleaiye se rere odaaro saint janet Romans 14:8

03/08/2026

Egun oloolu sebebe nilubadan arabinbinrin to sesi deja san iyebiye o esora fun etanje awon alaimokon mokon tiwon npe kosi isese mo igboran san ju ekbo riru

25/07/2026

Owo tun te awon gidigonku ajinigbe emin ni ipinle yobe bi ile ejo giga kon tokale sabuja se so meta ninu awon tiwon kopa ninu ijinigbe ipinle oyo sewon k*gbere.

24/07/2026

Ebo keekeeke ningba alaikula ema lo ogban atinuwa nigba min emin o laaro

04/06/2026

Ogbe ti foun foloun alagba yemi Johnson ti kowo towa lowoe sile o, adupe lowo gbogbo eyin ololufe wa teebawa dasi eti togbo alo oye kogbo abo eyin tinu si nbi ejebure o

20/05/2026

Ijafara lewu eyin ijobawa ejigiri nkon nbo nile yoruba ijinigbe di toro fonkale awon olopa ipinle ogun tun rowoto awon ajinigbe emin ni oju popona Ijebu ode ati orile ilugun nilu Abeokuta

16/05/2026

Kayefi nla part2 yemi Johnson kashogi to paro nla fun awon to da owo fun lati fun molebi eniwa to kjadelaye ni koba tun mun adeun se o beeke re adiye irana kiise oun ajegbe o ogbefoun foloun

14/05/2026

Kayefi nla , alagba yemi Johnson ti awon eeyon tun mosi kashogi lu gbajugbaja agboun safefe kan nilu Abeokuta ni jibiti owo bantabanta leyin to dagbere faye ton nilu Abeokuta omase o aiye nika

Address

Abeokuta
Abeokuta

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Oloburo Kayefi Tv posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share

Category