Ekiti Wives and Daughters

Ekiti Wives and Daughters PROUDLY EKITI. Connecting and Uniting Ekiti Wives & Daughters Worldwide. šŸ’ƒ
Follow, tag & mention Ekiti Wives and Daughters
for Adverts send DM or Whatsapp.

Ero Dam And Its Past Glory. Ero dam is located at Ikun Amure one of the most hospitable town in Ekiti State. You can har...
23/10/2025

Ero Dam And Its Past Glory.

Ero dam is located at Ikun Amure one of the most hospitable town in Ekiti State. You can hardly recite the oriki of the place without mentioning the beauty of the river that gave birth to the dam. The dam supplies portable water to many communities in Ekiti state.

The hope of those who constructed the dam might have been dashed. The place is now a far cry from what the founders had in mind for putting the dam there We were told that the place was to be a smart settlement with a stadium or rather, a football pitch as part of its features. It was meant to be fully residential. If the place was growing at the rate it was when we were at home, a polling booth or two would have been given to them by now thereby expanding it's electoral values. These are the dreams that have not come to reality.

As things stand today, it appears a lot has really gone missing in the dam. Life seems to have been taken away from it. The bloom of modernization of those days has gone away. The place is now almost deserted.


Othe than the effort of the government, what can we do as a people to bring back the lost glory and realise the dream of those sited the dam?

Aworere
The lover of the equity
He who seeks equity must come with clean hands.

OrúkoĢ£ AĢ€woĢ£n AkoĢ£ni tó bá Ogun EĢ€kiĢ€tiĢ€ Parapọ̀ loĢ£1. Aare Momodu Obadoke LĆ”tóòṣà (Aare Latoosa) — Aare Ona Kakanfo...
22/10/2025

OrúkoĢ£ AĢ€woĢ£n AkoĢ£ni tó bá Ogun EĢ€kiĢ€tiĢ€ Parapọ̀ loĢ£

1. Aare Momodu Obadoke LĆ”tóòṣà (Aare Latoosa) — Aare Ona Kakanfo, leader of Ibadan forces

Death: 1885 (died at his camp during the Kiriji campaign; Samuel Johnson reports he ā€œtook poisonā€).

Note: His death removed Ibadan’s principal field commander and was a turning point toward peace.

Source: Kiriji War summary; Aare Latoosa biography; Samuel Johnson narrative.

2. Balógun Ajayi (Ajayi Ogboriefon / Ajayi Jegede Ogboriefon) — Balógun and leader of the Ibadan army during Jalumi (Ikirun) operations

Death: 7 April 1879 (reported to have died of illness soon after the Jalumi/Ikirun fighting).

Note: His death is reported as a significant event in 1879 and affected Ibadan’s field command structure.

Source: Kiriji / Jalumi accounts; local historical summaries.

3. Prince Adeyale (of Ila) — Military leader on the Ila / Igbomina side at Jalumi

Death: Killed during the Jalumi / Ikirun fighting (1878).

Note: Several accounts of the Jalumi battle record Prince Adeyale’s death in that fighting; Ila-Orangun local histories also record his loss and the town’s suffering afterward.

Source: Jalumi (Ikirun) battle article; Ila-Orangun historical notes.

4. Afomodi — Balógun of Ijero (named in contemporary narratives of the Jalumi theatre)

Death: Captured at Ikirun and later died (captured and taken to Ibadan where he later died, per campaign narratives).

Note: Records say he was captured in the Jalumi operations and subsequently died in Ibadan custody. Exact date uncertain.

Source: Jalumi / Kiriji narrative summaries.

5. Albert (Alfred) Labinjo / Labinjo — leader associated with the Confederate Rifle Corps (Imesi-Ile / Ekiti-Parapo side)

Death: Wounded 13 July 1885 and died about five days later (1885).

Note: Labinjo is described in multiple summaries as an important rifle-corps leader; his wounding/death occurred in the final intense months of the war before Latoosa’s death. (Name sometimes given as Albert or Alfred Labinjo.)

Source: Kiriji War article / folk histories citing Imesi-ile collections.

6. Alli Laluwoye (Otun Balogun) — senior Ibadan chief/Balogun in Latoosa’s time

Death: Reported to have died at Kiriji in 1882 (local biographical rounds claim Alli Laluwoye died in the war period).

Note: This is drawn from local lists of chiefs who ā€œruled with Latoosaā€; sources are local historical writeups rather than single primary archival citations.

Source: Yorubafacts / local compendia of Latoosa’s chiefs.
(C) Aroni ede

OGUN EĢ€KIĢ€TIĢ€ PARAPỌ̀ (KÍRIĢ€JIĢ€ ) July 30,1887- March 14,1893 Ogun EĢ€kiĢ€tiĢ€ parapọ̀ jẹ́ ogun láaĢ€rin iĢ€wọ̀ ooĢ€ruĢ€n...
22/10/2025

OGUN EĢ€KIĢ€TIĢ€ PARAPỌ̀ (KÍRIĢ€JIĢ€ ) July 30,1887- March 14,1893

Ogun EĢ€kiĢ€tiĢ€ parapọ̀ jẹ́ ogun láaĢ€rin iĢ€wọ̀ ooĢ€ruĢ€n ilẹ̀ YoruĢ€bá (Western YoruĢ€bá Region) aĢ€ti IĢ€laĢ€ OoĢ€ruĢ€n ilẹ̀ YoruĢ€bá (Estern YoruĢ€bá Region)

Lábẹ́ iĢ€wọ̀ OoĢ€ruĢ€n lati rí - IĢ€baĢ€daĢ€n , IĢ€wó , IĢ€gbájoĢ£ , Ọ̀yọ́ aĢ€ti agbeĢ€gbeĢ€ eĢ£ , Ọ̀ffaĢ€ aĢ€ti Modákẹ́kẹ́ .

AĢ€woĢ£n IĢ€lú tó waĢ€ lábẹ́ iĢ€laĢ€ ooĢ€ruĢ€n ni - Ijesha ,Ekiti , Akure ,Akoko ,Yagba aĢ€ti Eruku ,Egba(Abeokuta)
,IĢ€jẹ̀bú, IĢ€lá aĢ€ti gbogbo iĢ€gbómiĢ€naĢ€ , IĢ€loĢ£rin Emirate aĢ€ti Ilé Ifẹ̀ Kingdom.

Gẹ́gẹ́ bí Ọ̀yọ́ Ilé sĢ£e ní iĢ€gbiĢ€mọ̀ tó ngba iĢ€sákọ́lẹ̀ nígbaĢ€kan tí a mọ̀ sí Ajẹ́lẹ̀ , bẹ́ẹ̀ náaĢ€ ni IĢ€baĢ€daĢ€n gbé iĢ€gbiĢ€mọ̀ Ajẹ́lẹ̀ kalẹ̀ láti máa gba iĢ€sákọ́lẹ̀ ní aĢ€woĢ£n iĢ€lú tó kuĢ€ .

IĢ€baĢ€dán fẹ́ iĢ€joĢ£a iĢ€sọ̀kan kí gbogbo ilẹ̀ YoruĢ€bá waĢ€ l'ábẹ́ IĢ€baĢ€daĢ€n gẹ́gẹ́ bí Ilẹ̀ YoruĢ€bá sĢ£e waĢ€ laĢ€bẹ́ Ọ̀yọ̀ nígbaĢ€ kan . SĢ£uĢ€gbọ́n EĢ€kiĢ€tiĢ€ fẹ́ iĢ€joĢ£ba oníléjilé tí EĢ€kiĢ€tiĢ€ ti nsĢ£e láti oĢ£jọ́ pípẹ́ . Bí gbogbo iĢ€lú tó kuĢ€ ní ilẹ̀ iĢ€jẹ̀bú se waĢ€ lábẹ́ IĢ€jẹ̀bú oĢ€de , bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni gbogbo ilẹ̀ EĢ€kiĢ€tiĢ€ waĢ€ lábẹ́ Adó EĢ€kiĢ€tiĢ€.

LáiĢ€ fa ọ̀rọ̀guĢ€n , iĢ€waĢ€ burúkú pọ̀juĢ€ fún aĢ€woĢ£n Ajẹ́lẹ̀ yí , iĢ€sĢ£ekúsĢ£e ni wọ́n maa nsĢ£e aĢ€woĢ£n EĢ€niĢ€yaĢ€n , ẹ̀ruĢ€ siĢ€ má nba aĢ€woĢ£n ará iĢ€lú láti kojú woĢ£n .

SĢ£uĢ€gbọ́n aĢ€woĢ£n aĢ€gbaĢ€ soĢ£ wípé má koĢ£já ní aĢ€aĢ€laĢ€ mi , oĢ£jọ́ kan ni oĢ€pin máa báa . Ní oĢ£dún 1876 , Ọ̀dọ́modé kan tó jẹ́ OĢ£moĢ£ OĢ£ba ní OĢ€keĢ€ IĢ€mẹ̀sí gbéná wojú aĢ€woĢ£n Ajẹ́lẹ̀ yí . Oun aĢ€ti aĢ€woĢ£n akeĢ£gbẹ́ rẹ̀ lu aĢ€woĢ£n Ajẹ́lẹ̀ yí ní aĢ€luĢ€bami , kódaĢ€ ẹ̀mi méjiĢ€ bọ́ nínú aĢ€woĢ£n Ajẹ́lẹ̀ náaĢ€.

IĢ€roĢ€yiĢ€n dé IĢ€lú IĢ€baĢ€daĢ€n l'ọ́dọ̀ AĢ€aĢ€reĢ£ LátóoĢ€saĢ€ . AĢ€aĢ€reĢ£ oĢ€ beĢ€suĢ€ bẹ̀gbaĢ€ , ó paĢ€sĢ£eĢ£ ogun láti jeĢ£ IĢ€mẹ̀sí Ilé run .
Oun tí a peĢ€ ní gọ̀biĢ€ padaĢ€ di gọ́bigọ̀bi . Gbogbo EĢ€kiĢ€tiĢ€ bá parapọ̀ , aĢ€woĢ£n IĢ€lú tí woĢ£n jẹ́ orogún sí iĢ€lú IĢ€baĢ€daĢ€n náaĢ€n diĢ€de láti ran EĢ€kiĢ€tiĢ€ l'ọ́wọ́ .

Ní oĢ£dún 1887 , IĢ€baĢ€daĢ€n lu IĢ€luĢ€ ogun , aĢ€woĢ£n AkoĢ£ni bí
Obadoke Latoosa, Aare Ona Kakanfo
Balógun AĢ€jaĢ€yí OĢ£súngbẹ̀kuĢ€n
Ajayi Ogboriefon
Babalola Ajayi Kupolu
Balogun Ali Iwo
Atbbl ṣa ara wọn jọ .

EĢ€kiĢ€tiĢ€ parapọ̀ náaĢ€ oĢ€ beĢ€suĢ€ bẹ̀gbaĢ€ , wọ́n dá orin sí iĢ€luĢ€ ogun tí IĢ€baĢ€daĢ€n luĢ€ . AĢ€woĢ£n akoĢ£ni káaĢ€kiri ilú loĢ£ bí rẹ́rẹ́ . Lára woĢ£n ni

Fabunmi of Okemesi, tó padaĢ€ jeĢ£ OĢ£ba OĢ£wá OoĢ€yeĢ€ ti IĢ€mẹ̀sí-Ilé
Ogedengbe ti IlésĢ£aĢ€
OĢ€dú ti Ọ̀gbagi-AĢ€kókó
OĢ€gúnmódeĢ£dé ti Ilẹ̀ IĢ€jẹ̀sĢ£aĢ€
Karara ti IĢ€lú Ilorin
Adéyalé ti IĢ€lá ( IĢ€gbómiĢ€naĢ€)
OlúgbósuĢ€n ti OĢ€yeĢ€
ErínfoĢ£lámí AgbénijaĢ€bíogun FákuĢ€ádé ti Oye
Ọ̀naĢ€fowókaĢ€n ti IĢ€jẹ̀bú
Ológun ti IĢ€lú Ọ̀wọ̀
OĢ€gúnbuĢ€luĢ€ ti IĢ€lú Aisegba

OĢ£moĢ£ ogun tí IĢ€baĢ€daĢ€n aĢ€ti aĢ€woĢ£n ikọ̀ tó kú kó joĢ£ jẹ́ OĢ£gọ́saĢ€n-án eĢ£gbẹ́ruĢ€n (180,000 sodiers)

OĢ£moĢ£ ogun EĢ€kiĢ€ti parapoĢ£+IĢ€gbómiĢ€naĢ€ jẹ́ AĢ€ádọ́saĢ€n-aĢ€n eĢ£gbẹ́ruĢ€n (170,000 soldiers)
Ifẹ̀ niĢ€kan kó OĢ£moĢ£ ogun oĢ£gbọ̀n eĢ£gbẹ̀rún (30,000 soldiers) sílẹ̀ láti sĢ£e aĢ€tiĢ€leĢ£yiĢ€n fún EĢ€kiĢ€ti parapọ̀ .

Tí a bá sĢ£e iĢ€siroĢ€ aĢ€woĢ£n OĢ£moĢ£ ogun tí a kaĢ€ sílẹ̀ yí , eĢ£ó ri wípé káni iĢ€sọ̀kan bá waĢ€ láaĢ€rin OĢ£moĢ£ YoruĢ€bá ni iĢ€gbaĢ€ náaĢ€ ni , Amalgamation tó wáyé ní oĢ£dún 1914 koĢ€ bá má ti wáyé rárá nítorí aĢ€woĢ£n OĢ€yínboĢ€ oĢ€ bá tí leĢ€ rí iĢ€ran YoruĢ€bá mú siĢ€n débi tí woĢ£n ó soĢ£ wá pọ̀ mọ́ iĢ€ran kankan.

Báwo ni ogún kíriĢ€jiĢ€ sĢ£e rí nígbaĢ€ tó bẹ̀rẹ̀ , aó maa tẹ̀ síwájú .

Ā©2025 AĢ€rọ̀niĢ€ EĢ€deĢ€

22/10/2025

O ga ju🄱
22/10/2025

O ga ju🄱

21/10/2025

or
Who won?😁

15/10/2025

Are you from Ekiti?
If yes,
Follow Ekiti Wives and Daughters

15/10/2025

Hin okun o Ekiti kete lule loko, Ekiti a gbe a o.

Imisioluwa and her Ekiti men šŸ˜‚Congratulations to imisi and imistars šŸŽŠšŸŽ‰šŸŽ‰šŸŽ‰šŸŽŠšŸŽŠDo you still need a reminder to grab the Ekiti...
07/10/2025

Imisioluwa and her Ekiti men šŸ˜‚

Congratulations to imisi and imistars šŸŽŠšŸŽ‰šŸŽ‰šŸŽ‰šŸŽŠšŸŽŠ

Do you still need a reminder to grab the Ekiti men you have been overlooking 😁

Ekiti kete.South West Fashion Week/Ekiti Fashion Exhibition 2025 Award Categories is here.Here is the PHOTOGRAPHY STUDIO...
07/10/2025

Ekiti kete.

South West Fashion Week/Ekiti Fashion Exhibition 2025 Award Categories is here.

Here is the PHOTOGRAPHY STUDIO OF THE YEAR category.

To Nominate, Mention, Tag and write the phone number of Your preferred Photography Studio operating within the stated region in the comments section and Please be sure the studio or representative will be available for the event if won.

Note: Nomination ends by November 14th, 2025.

*Are u In Ado Ekiti or u know someone there? Join us for another Empowerment program on Thursday 9th October 2025**Free ...
06/10/2025

*Are u In Ado Ekiti or u know someone there? Join us for another Empowerment program on Thursday 9th October 2025*

*Free Chicks & Free fish for everyone*
*From 8am till everyone is empowered*
*CEO Cares*

Address

Ogbon Ado Street
Ado-Ekiti

Telephone

+2348146246535

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ekiti Wives and Daughters posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Ekiti Wives and Daughters:

Share