Bólújí Radio

Bólújí Radio Bólújí Radio is an indigenous Yoruba music & Lifestyle Radio. Promoting the Yoruba tradition, culture and heritage to the world.

12/01/2025

Yoruba lo kan lati di olori gbogbo eya lagbaye.

Esu laaroye ki nse SataniKo de lowo ninu laburu to nja omo eda.Ohun kohun ti eda ba gbin nipa iwa lo ma jere.Eda keda ti...
12/01/2025

Esu laaroye ki nse Satani

Ko de lowo ninu laburu to nja omo eda.

Ohun kohun ti eda ba gbin nipa iwa lo ma jere.

Eda keda ti o ba se ohun to to tabi toye ni Esu nse latifi baawi tabi ko ountohun logbon.

Ire ooo.

12/01/2025

Ilu kilu to ba seti ikun lati fi eranko ru'bo gbodo se ton lati padanu awon ara ilu latara ilailo afowofa ati aifowofa.

Ire ooo.

12/01/2025

Ojojumo ni mo boluji mo bolaji mo fowo soge.

Aa ye wa kalé

24/08/2023

Ifá Admonitions, is a compendium of the declarations of Ọ̀rúnmìlà through the entire 256 Odus. Ifá declarations - Iṣisẹ Ifá, are words of comfort. They are redemptive as well as restorative. Direct words of wisdom from Orunmila, in his sober, contemplative and meditative mood. It will n...

24/08/2023

Address

Abraham Adesanya Estate
Ajah

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Bólújí Radio posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category