Wise Fm Ile-Ife Live

Wise Fm Ile-Ife Live Wise Fm Live Ile-Ife is an online radio where you get updates on news broadcast and empowerments

18/08/2026

WOLI EMMANUEL FALOLA ATI ERO CRYING SESIN AWORO.

18/08/2026

Nkan dee! Ilé ìwòsàn kọ Taiwo Hassan Ogogo láti tọ́jú, nítorí pé òní Àìsàn jẹjẹrẹ (Cancer), ọmọ rẹ bù ṣẹkún.

Ọ̀kan lára àwọn oṣèré Nollywood olókìkí ní Nàìjíríà, Hassan Taiwo, ẹni tí a mọ̀ sí Ogogo, ti ní àyẹ̀wò tí ó fi hàn pé ó ní àrùn jẹjẹrẹ (Cancer) tí ó sì ti dé ipele kẹrin.

Ọmọ Ọmọbìnrin rẹ̀, Kira Taiwo, ló fi ọ̀rọ̀ náà hàn ni gbangba nínú fídíò kan tó tan káàkiri lórí ayélujára ní ọjọ́ Mọ́ndé, níbi tó ti bẹ àwọn ọmọ Nàìjíríà pé kí wọ́n ràn baba rẹ̀ lọ́wọ́.

Kira ṣàlàyé pé ìrànlọ́wọ́ tí wọ́n ń wá kì í ṣe owó, ṣùgbọ́n ohun tí wọ́n nílò ni ìrànlọ́wọ́ láti mọ ibi tó yẹ kí wọ́n ti gba ìtọ́jú tó péye fún baba rẹ̀.
Ó ní ilé ìwòsàn tí Ogogo ti ń gba ìtọ́jú tẹ́lẹ̀ ti kọ̀ láti tẹ̀síwájú pẹ̀lú ìtọ́jú rẹ̀. Nítorí náà, wọ́n ń wá ibo míràn tí wọ́n lè ti tọ́jú rẹ̀, bóyá ní ilé ìwòsàn tàbí nípasẹ̀ ìtọ́jú ìbílẹ̀.

Kira tún sọ pé ìkùn baba oun ti wú, èyí sì ti mú kí àìsàn na lágbára si.

Ó tún ṣàfihàn pé Senator Olamilekan Adeola, ẹni tí wọ́n mọ̀ sí Yayi, tó jẹ́ olùdíje fún ipò gómìnà Ogun State lábẹ́ APC nínú ìdìbò ọdún 2027, ti ń san owó ìtọ́jú Ogogo.

Gẹ́gẹ́ bí ìròyìn náà ṣe sọ, àwọn ìgbìmọ̀ láti gbé Ogogo lọ sí ilẹ òkèèrè fún ìtọ́jú, kò ṣàṣeyọrí, nítorí pé àwọn dókítà ti sọ pé kò yẹ fún un láti rìnrìn-àjò jáde kúrò ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ipò tí ara rẹ̀ wà báyìí.

Kira bẹ̀bẹ̀ pé bí ẹnikẹ́ni bá mọ̀ ilé ìwòsàn, ẹgbẹ́ dókítà, àjọ tàbí ẹni kọọkan tó lè pèsè ìrànlọ́wọ́ fún baba oun, kí irú ẹni bẹ́ẹ̀ jáde wá.

Ó ní gbogbo ìrànlọ́wọ́, àdúrà àti àtìlẹ́yìn ẹyin olólùfẹ́ baba oun ṣe pàtàkì fún wọn.

“Kí Ọlọ́run fún un ní ìwòsàn àti agbára.” Àmín

16/08/2026

Mr Tibetan is not a man of God.
Shame on you iya Ero Arike
Congratulations to My governor Ademola Adeleke for second time .

11/08/2026

IAY ERO ARIKE NEED MEDICAL DOCTOR ATTENTION. OSUN PEOPLE LET US VOTE ACCORDINGLY. Osun State University, Osogbo, Nigeria ADEMOLA ADELEKE CAMPAIN GROUP PDP OSUN

11/08/2026
30/07/2026

HISTORY OF OSARA IN ILE IFE ON WISE ONLINE RADIO TV. STUDUIO LINE 07031857277.


Ooni Adeyeye Enitan Babatunde Ogunwusi - Ojaja II
Ooni Adeyeye Enitan Ogunwusi, Ojaja ll
Agbala Gabriel International
Kwara State Government

With Pro Segun Arolejp – I just got recognized as one of their top fans! 🎉
19/07/2026

With Pro Segun Arolejp – I just got recognized as one of their top fans! 🎉

13/07/2026

For your different kind of advertisement, birthday greetings, jingle productions call mc wise on 07031857277. Or Whatsapp me ok this number +2347031857277. Thanks happy New week. Wise Fm Ile-Ife Live Agbala Gabriel International Prophet Odedoyin Olawumi Ezekiel Ooni Adeyeye Enitan Babatunde Ogunwusi - Ojaja II

10/07/2026

GOODNEWS: Finally, all the kidnapped pupils and teachers in Orire, Oyo have been rescued by our security agencies.❤️❤️💃🏿💃🏿

Address

Akure
Akure

Telephone

+2348113757650

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Wise Fm Ile-Ife Live posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share