Ile Eko Omoleyin Jesu ni ede Yoruba

Ile Eko Omoleyin Jesu ni ede Yoruba Eko Bibeli ni ede Yoruba fun awon Omoleyin Jesu Kristi.

A wa nibi lati ko eniyan di Omoleyin tootọ, lati gbe won dide lati sise papo pelu Olorun ninu itankale Ihinrere si gbogbo orile-ede.

18/02/2026

Ṣùgbọ́n ẹ̀yin yóò gba agbára, nígbà tí Ẹ̀mí Mímọ́ bá bà lé e yín; ẹ̀yin yóò sì máa ṣe ẹlẹ́rìí mi ni Jerusalẹmu, àti ní g...
09/02/2026

Ṣùgbọ́n ẹ̀yin yóò gba agbára, nígbà tí Ẹ̀mí Mímọ́ bá bà lé e yín; ẹ̀yin yóò sì máa ṣe ẹlẹ́rìí mi ni Jerusalẹmu, àti ní gbogbo Judea, àti ní Samaria, àti títí dé òpin ilẹ̀ ayé.
Ìṣe àwọn Aposteli 1:8

08/02/2026

...Oore-ọ̀fẹ́ àti àlàáfíà fún yín láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Baba wa àti láti ọ̀dọ̀ Olúwa wa Jesu Kristi.
Romu 1:7

08/02/2026

Jesu Kristi ni Oba awon Oba.

07/02/2026

Esra ti fi ara rẹ̀ jì fún kíkọ́ àti pípa òfin Olúwa mọ́, ó sì ń kọ́ òfin àti ìlànà Mose ní Israẹli.
Esra 7:10

07/02/2026

07/02/2026

Full video here.
゚viralシviralシfypシ゚viralシalシ

07/02/2026

Gbọ́ ohùn Jesu lọ́jọ́ọ̀jọ́.

06/02/2026

Bi o sele gbo ohun Jesu ninu Bibeli kika re.

https://youtube.com/?si=Pph54dIt5UMZ6QfOTẸLÉ WA LÓRI YOUTUBE. KI O SUBSCRIBE SI CHANNEL WA LATI MỌ SII.
06/02/2026

https://youtube.com/?si=Pph54dIt5UMZ6QfO

TẸLÉ WA LÓRI YOUTUBE. KI O SUBSCRIBE SI CHANNEL WA LATI MỌ SII.

Ile-Ẹ̀kọ́ Omoleyin Jesu (Yorùbá) jẹ́ pẹpẹ ikẹ́kọ̀ọ́ Bibeli àti ọmọ-ẹ̀yìn tí a dá sílẹ̀ fún ìjọ Yorùbá. A gbagbọ́ pé Kristẹni kì í ṣe ẹni tí ó kan ń lọ sí ìjọ nìkan, ṣùgbọ́n ẹni tí ń tẹ̀lé Jesu Kristi gidi. Nínú ikanni...

Address

Mayomi Street, Off Cannan Land Road, Davog. Ijoka
Akure
340001

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ile Eko Omoleyin Jesu ni ede Yoruba posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share