OJB MEDIA HUB

  • Home
  • OJB MEDIA HUB

OJB MEDIA HUB Welcome to OJB MEDIA'S HUB — your go-to space for creativity, entertainment, media updates, and digital storytelling. From media

We bring engaging content, fresh ideas, trending topics, and quality visuals designed to inform, inspire, and entertain.

Nibi a ṣe ń kó ìròyìn yìí síta àjọ NSA ni Nuhu Ribadu tí kò lẹ́yìn lọ sí ìpàdé ètò àbò tí yóò wàye láàárín orile-ede Ame...
13/08/2026

Nibi a ṣe ń kó ìròyìn yìí síta àjọ NSA ni Nuhu Ribadu tí kò lẹ́yìn lọ sí ìpàdé ètò àbò tí yóò wàye láàárín orile-ede Amerika àti Nàìjíríà nilu Washington DC.
Te asopo ìsàlẹ̀ yìí láti kaa síwájú àti síwájú sí nípa ọrọ ìpàdé ètò àbò láàárín orile-ede Amerika àti Nàìjíríà

Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Olalekan Akanji Ademeto, Abuja | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ́rú, 6, Oṣù Kẹjọ 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410   Nàìjíríà àti Amẹ́ríkà wà ní ìpàdé pàtàkì ní Washington lórí ọ̀rọ̀ àà...

Ileese Olopaa lórílẹ̀ èdè yìí tí ṣe kilo kilo fún ara ìlú àti àwọn ẹgbẹ́ alaabo labele láti yàgò níbi ètò ìdìbò ni ipinl...
13/08/2026

Ileese Olopaa lórílẹ̀ èdè yìí tí ṣe kilo kilo fún ara ìlú àti àwọn ẹgbẹ́ alaabo labele láti yàgò níbi ètò ìdìbò ni ipinlẹ Ọṣun

Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Olalekan Akanji Ademeto, Abújá | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ́rú, 6, Oṣù Kẹjọ 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410     Agbófinró Ọlọ́pàá Nàìjíríà (NPF), lábẹ́ olórí Inspector-General of Police...

Kàyéfì ńlá gbaa lọrọ ọmọ ẹgbẹ agbaboolu Katsina United nígbà tí wọn ti kọkọ́ kéde ikú rẹ lórí pápá tí ó sì tún padà jí d...
13/08/2026

Kàyéfì ńlá gbaa lọrọ ọmọ ẹgbẹ agbaboolu Katsina United nígbà tí wọn ti kọkọ́ kéde ikú rẹ lórí pápá tí ó sì tún padà jí dìde, báwo ló ṣe ṣẹlẹ̀, kaa lórí ìkànnì ayelujara OJB Medias Hub, tẹ asopo ìsàlẹ̀ yìí láti kaa síwájú àti síwájú sí....

Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Olalekan Akanji Ademeto, Katsina| Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọbọ, 13, Oṣù Kẹjọ 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410   *Iṣẹlẹ kayeefi kan ti ṣẹlẹ ni Ìpínlẹ̀ Katsina. ÌRÒYÌN ÌṢÁÁJÚ Ikú tí p...

Ayé tótó, ilé ayé akamara ni ó, ṣe ìwọ náà lè ṣe, kí ó fún ọkùnrin abarapá bí ti ẹ ní owo iyebíye láti fún ìyàwó ilé rẹ ...
13/08/2026

Ayé tótó, ilé ayé akamara ni ó, ṣe ìwọ náà lè ṣe, kí ó fún ọkùnrin abarapá bí ti ẹ ní owo iyebíye láti fún ìyàwó ilé rẹ lóyún.

Hmm, ọrọ yí Àbí omin-in, ẹ ka ṣíwájú àti síwájú sí nípa ìtàn arákùnrin kan pẹlu ìyàwó l'anloodu rẹ, àti Baba onílé gan-an fún ra rẹ.....

Orísun: OJB News Yoruba | Onkotan:Lekan Lawal | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọbọ, 13, Oṣù Kẹjọ 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410 *Ṣé ẹ gbàgbé pé lásìkò tí mo wà lórí ibùsùn pẹlu Mrs Cole yí tí a jọ ní asepo lọ́wọ́ ni ọd.....

12/08/2026

Visit our website for more information, news and many more @ ojbmediahub.com.ng

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Muritala Mujeeb Opeyemi, Arobany Sulaiman, Olutola Atolay...
12/08/2026

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Muritala Mujeeb Opeyemi, Arobany Sulaiman, Olutola Atolaye, Isiaka Alabi, Jimo Babaola, Akanmu Gybson, Adegbenle Nurudeen Adeoye, Surprise Ladys Club, Fadebi Moruf Imam, Prince Abiodun Oluwaseun, Oluwa Seun Sh*ttu, Mallo Ishaku, Motunrayo Olubiyi, Peter Adekoya, Dan Square, Gbenga Badmus, Lanre Hammed, Afees Adebayo Dauda, Kwara Voice

N je ìwọ ti ẹ gbọ́ rí tàbí ó mọ ẹni tí wọn ń pè ní Alaaji Rafiu Bakare Jafojo, ọkàn nínú àwọn ọmọ bibi ìlú ilé-ìfẹ́ ni n...
12/08/2026

N je ìwọ ti ẹ gbọ́ rí tàbí ó mọ ẹni tí wọn ń pè ní Alaaji Rafiu Bakare Jafojo, ọkàn nínú àwọn ọmọ bibi ìlú ilé-ìfẹ́ ni n se, bẹẹ sire e, igbakeji Gómìnà ni ni ipinlẹ Èkó, bí ó bá fẹ́ mọ sì nípa olóògbé Rafiu Jafojo.

Te asopo ìsàlẹ̀ yìí láti kaa síwájú àti síwájú sí nípa ìtàn ìgbésí ayé olóògbé Rafiu Jafojo to jẹ ọmọ bibi ìlú ilé-ìfẹ́ tó ní agboolé ńlá kan nilu Agege tí wọn ń pè ní Jafojo.

Orísun: OJB News Yoruba | Onkotan: Lekan Lawal, Sango-Ọta | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ́rú, 12, Oṣù Kẹjọ 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410     Chief Rafiu Bakare Adeyefa Jafojo ni a bi ni December 6, 1936. Baba rẹ ni Late Bakare Adeyefa Jafojo,...

Ikú tí tún wo agbo oṣere báyìí, nile àwọn akọrin ẹ̀mí lo gba lọ, nibẹ loti pá Gbajumọ olórin ẹ̀mí nnì, Ajinnrere G.A Awo...
12/08/2026

Ikú tí tún wo agbo oṣere báyìí, nile àwọn akọrin ẹ̀mí lo gba lọ, nibẹ loti pá Gbajumọ olórin ẹ̀mí nnì, Ajinnrere G.A Aworinde, afoju to n tán imole Kristi kiri agbanla ayé.
Te asopo ìsàlẹ̀ yìí láti kaa síwájú àti síwájú sí nípa G. A. Aworinde

Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Bolarinwa Wasiu, Ọṣun | Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ́rú, 12, Oṣù Kẹjọ 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410     Ikú ti tún kán mọ́lé ijọsin ni Nàìjíríà. Evangelist G. A. Idowu Aworinde, ti a tun m....

Ibrahim Ma'aji sọpe mi ò kabamo pé mo fẹ́ gbà jọba mo Tinubu lọ́wọ́,
10/08/2026

Ibrahim Ma'aji sọpe mi ò kabamo pé mo fẹ́ gbà jọba mo Tinubu lọ́wọ́,

Orísun: OJB News Yoruba | Akọroyin: Olalekan Akanji Ademeto, Abújá| Olootu: Lekan Lawal | Ojú-òpó: OJB Media Hub | Ọjọ́rú, 6, Oṣù Kẹjọ 2026 | ojbmediashub.com.ng | +2348066952410   Nàìjíríà fẹrẹ wọlẹ, mo ṣe ohun tí mo ṣe nitori ifẹ orilẹ-ede – Kọ́lọ...

Thanks for being a top engager and making it onto my weekly engagement list! 🎉 Asamu Okomoh, Shuraju Akintunde, Joseph O...
10/08/2026

Thanks for being a top engager and making it onto my weekly engagement list! 🎉 Asamu Okomoh, Shuraju Akintunde, Joseph Oluwaseyi, Surajudeen Amusa, Sholly Ewulo, Tope Arike

Address

324, Kofo Abayomi Street

110243

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when OJB MEDIA HUB posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

  • Want your business to be the top-listed Media Company?

Share