Xclusive Music Entertainment

Xclusive Music Entertainment Bringing out the stars in you.... And making your way into the Nigerian music industry

23/02/2023

Oro ree egbe ye wo.....

23/02/2023

Eka San gbogbo eyin Omo biibii ile yoruba, Nile loko ati leyin odi, Aku Deede asiko yii, A de ku ipalemo ibo ton bo lona, e jowo, Akiyesi ranpe kan ni mo muwa fun wa, lori oro idibo ton bo lona yii, mi oni ki e ma dibo fun eniti okan yin mu, Ra ra ooo, Sugbon eje kia ranti Baba waa Olongbe Oloye Awolowo, won fe lati du ipo aare orile ede wa naijiria, ki ohun gbogbo ledi irorun fun wa ni orile ede yii, sugbon won ko debe, gege bi Omo ile yoruba, nigbati o pe Aadoota odun (30yrs), Olongbe Baba wa Moshood Abiola naa du ipo yen, Awon naa kode ibe, Ni bayii Aadoota odun (30yrs) Miran ree oo, Ti Baba waa Asiwaju Bola Ahmeed Tinubu naa fee du ipo Aare orile ede yii, Se ki a fi Owo leran ki eleyii na bo ni Owo wa, Omo Eni kole se idi bebeere, ki a fi ileke si idi lomo elomiran, Omo Yoruba eje kia ronu oo, Omo buruku na ni ojo rere tire, Omo Eni kole buru t**i kale fun ekun paje, imoran mi ni eyi si gbogbo eyin Omo Yoruba lapaapo, e ronu si, idibo ku ojo meji pere, asi le yi ipinu wapada koi to bo oo, Ire oooo.

03/02/2022
03/02/2022

Address

Alagbe Road, Igwe Bus/Stop
Atan Ota

Telephone

+2349138497397

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Xclusive Music Entertainment posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Xclusive Music Entertainment:

Share

Category