ÒKÒTÓ ÒRÓ

ÒKÒTÓ ÒRÓ On Air Personality || Content Creator || Master of Ceremonies
(1)

23/02/2025

Two mansions in Lekki🏛️🏛️

₦200billion naira in your account 💰💰

3 Range Rover 🏎️🏎️🏎️

A Supermarket worth ₦300million naira 💰💰

2025 Hajj ✈️✈️.....

Would you married me if I offered you all this 😳
Se wa fẹ mi ?

23/02/2025
23/02/2025

Aanu nla to n yi itan ayé ẹni pada si rere yóò wa ọ ri tipa tikuuku kòsí yìí to pari

23/02/2025

Tænni ki n fẹ ninu àwọn ololufẹ mi Ibadi ni Sọọbu yìí 🤣🤣

23/02/2025

Ẹ bámi kí Bàbá Landlord mi ku oriire 🤣
Ìyàwó rẹ bi arẹwa ọmọkunrin lantilantin laipẹ yìí 🤣
Ọmọ náà lẹ n wo yìí...
Ẹ dakun ẹ bawa fún lórúkọ tó rẹwa kan

23/02/2025

Gbajugbaja Olorin Musulumi Alhaja Aminat Ajao ti ọpọ eniyan mọ sì Obirere ṣẹṣẹ sì ile awosifila tuntun kan towo rẹ to ẹgbẹlẹgbẹ millionu naira 🙏
Ẹ jẹka kìí ku oriire.
Ile a Tura ..
Edumare a kólé ayọ fún gbogbo wa l'ọdun yìí oo

23/02/2025
23/02/2025

Àwọn ọmọ mi 🧍
Àwọn ọmọ rẹ 🧍🧍
Àwọn ọmọ wa🧍🧍🧍

Wọn o ni saarẹ 🙏
Wọn o ni sanku 🙏
Wọn o ni yá weere 🙏
Wọn o ni d'ẹru ẹgbẹ 🙏

Wọn a dagba 🙏
Wọn a dogbo 🙏
Wọn a dọlọla 🙏
Wọn a dolokiki 🙏
Wọn a gbogo idile wa ga 🙏

Gbogbo abiyamọ to fẹ bẹẹ ko s'amin

Pls share

Follow my backup page Ogbeni Okoto Oro Presenter

23/02/2025

Se kii ṣe Ààrẹ Ologun nígbà kan ri lorilede Naijiria Ọgagun Ibrahim babangida niyi ni 🤣
Igbawo ni wọn tun di olorin juju ?
Well ọna kan ọ wọ ọjà sa .
Anyhow , jẹ ki n pari ẹmu ogurọ t'emi ko to ru danu tan 🤣
Happy Sunday

Pls follow my backup page Ogbeni Okoto Oro Presenter

Address

Ede

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when ÒKÒTÓ ÒRÓ posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share