Maami Ile Alayo

Maami Ile Alayo don’t allow enemies of progress in your family

I maami ile alayo We are here to build a lovely and beautiful home together by sharing an story that we help us to build a strong 💪 marriage and family together our home 🏡 we stand in good foundation.

Huuuuuuuuu owe Yoruba kan so pe sürü a ma se okuta jina, be pelu ni owe emiran so pe sürü ki poju afi ti ko ba ni to.  A...
12/08/2026

Huuuuuuuuu owe Yoruba kan so pe sürü a ma se okuta jina, be pelu ni owe emiran so pe sürü ki poju afi ti ko ba ni to.

Ahhhhhhh gbakogbin ni oro arabinrin yi.
Olotu mo se alabapade oko mi, ni ikan bi odun melo şeyin, o si so fun pe single mother ni oun pe oun ni omo obinrin bi omo odun meta ati osu meji lowo, Mo si bi pe ki lo se okufa ija larin won, oko mi ni ni osan ojo kan ni oun Bo lati ibi ise ti oun si de ba oko oun pelu ale ni Ori ibusu awon, pe idi niyi ti awon mejeeji fi pinya, pe lati igbana ni oun ti to omo naa, huuuuuu Mo si gba omo naa bi omo mi ti Mo si toju re bi omo bibi inu mi, lehin bi odun keji ti Mo fe oko mi ni Mo bi omo okunrin kan fun oko mi, bi omo oko mi se bere si ni Wu awon iwa ti ko da niyi nigba ti olo omo oko mi lo ata ti o mu omi ni oju mi hummmmmmm enikan kan ko gbo
Omo oko mi da omi gbingbona si omo mi Lara ni igbati omo mi wa ni omo odun kan koda die lokun ki omo naa ku, oko mi Be mi Mo si gbo si oko mi lenu, Mo si pada lo si odo oko mi, köpe kojuna ni Mo ba loyun 🫃🫃🫃le omo mi, ti ti ti mo fi bi omo naa awon iwa omo oko mi si omo mi ko Dara rara ti Mo si gba Mo ra, Amo Yoruba ni ti won ba so pe su su ti eniyan ba ti şu kan o gırı eniyan ma bohun, lehin ti Mo bi omo keji le omo mi tan, Mo si doju gbogbo won Bi omo mi, Amo awon iwa omo naa koda si awon omo mi mejeeji rara, ni ojo kan ni Mo ni ki enikan ni adugbo wa ba mi ti ile kun ni ita ki won fun awon omo mi ti won ba de, Mo si su sinu yara mi ti Mo si ti ile kun yara mi lati ehin, huuuuuu bi awon omo mi se wole ni moti fi camera kekere kan sinu yara isere won bi omo oko mi se gbe omi gbona kana ti o si bere si ni le omo mi kiri lati da omi naa si omo mi Lara ni Mo ba yara kankan jade lati inu yara mi bi Mo se fe gba omi naa lowo re ni omi naa ba da si omo oko mi Lara ti osi po gidi gan, bi oko mi se de ti o fi ake Kori pe emi ni Mo Mo Mo da omo gbona naa si omo oun Lara niyi. Hummmmm olotu oko mi ni ika ni Mo se fun omo oun pe afi ki fi oju ba ile Ejo ooooo. Egbami oooo olotu ki ni Mo le se nitori oko mi ko gbo oro mi rara koda ti ba si ninu ile lojo naa omo mi ni ko da omi naa si Lara, Sugbon oko mi ko gbo ki so oro.
Olotu Ejo se emi ni Mo jebi oro yi. Ati pe ki ni ki se ni ikorita ti Mo wa yi.



HUUUUU MEWA NSELE NI DUNIYAN APA KERIN. Lehin ti baba mi ran Ejo siwa ti ASIRI won tun, won tun wa gbe a*o fun mi pe ki ...
11/08/2026

HUUUUU MEWA NSELE NI DUNIYAN APA KERIN.
Lehin ti baba mi ran Ejo siwa ti ASIRI won tun, won tun wa gbe a*o fun mi pe ki lo ran bi won se gbe a*o naa fun mi ni ojo keji ti Mo jade lo ni Mo se alabapade were kan, lo bani enikan gbe a*o Funmi pe mi gbodo ran a*o naa Debi ti Mo ma wo Ahhhhhh mewa nsele ni duniyan oooo ase bi won se fi baba mi köye ni won ti mu won wonu Egbe, iyawo oye ti baba mi fe ti mu baba mi mule ninu Egbe iboji 😭😭😭😭😭😭💙💙bi olorun se ranse si Iya mi niyi pe ku Iya mi klyesara nitori baba mi ati iyawo oye ti won se fun ti wonu imule to lagbara koda ko si eni to le tu won ka afi ti oku ba yawon, ni baba Woli ba ni ki iyami sora ni gbogbo Ona pelu awon omo won nitori wa gbe ohun jije fun awon omo won pe ki won ma je oooo, huuu ti won ba je olorun lailai ni oooo. Lehin bi osupa keta ti Woli jise fun Iya mi ni baba mi ba de ni osan ojo kan won si gbe garı ijebu lowo wa fun wa, ahhhh😂😂😂olotu Amo Iya mi ti gbagbe ohun ti baba Woli so fun won Bi Iya mi se gba garı ti gbogbo wa mu garı niyi oo. Lehin ti a mu garı tan mewa nsele si gbogbo wa! Ahhhhhh ki lo tun sele si awon iranse yi bayi ooooo. Eyi temi mawa nsele ni duniyan ooo ki olorun gbawa lowo eniti a so to so wa ooo, ka ma teni tika tomotomo wa ooo. Amin 🙏, Bi o ba gbadun eto yi Jo bami like, share ki osi follow mi fun awon ipele toku ki o le Mo ohun to tun nsele si awon idile na. Te mi ni abala Ariwisi.




08/08/2026

IGBẸ́YÁWỌ MI ÁPA KINI 😡🎁💗🍾🤗💗😍😃😃😱🧑‍🎓😭😓🤗🤔📨.
Ẹ́ bámi wá nkán fidile e maa bami kalo.
* Oruko Mi oluwTomiwá Mo je omo bi ilu isagamu emi ati oko mi se igbeyawo wa ni odun 2000 , Mo wa bi omo Ogun odun ni akoko naa leyin bi odun meje ti a se igbeyawo Mo bi omokunrin kan fun, leyin ti omokunrin naa pe odun meji ni Ona ilu oyinbo se fun oko mi, o si fi owo ounje sowo si ni orikori, Sugbon sadede ni leyin odun kan to de ilu oyinbo ni a ba gbo ikan kan Mo lati odo re. Ati jeun ati mu wa di ikan fun emi ati omo mi, ni Ojo kan ni omo naa ba bere aisan raape kan ni Mo ba ke si ore oko mi ni a Jo se itoju omo naa leyin ti Ara omo mi bale, ni ikan ba pa emi ati ore oko mi po. Hummmm ajosepo ti o wa larin emi ati ore oko mi ba di oyun ni Mo ba fi bi Ibeji fun ore oko mi, ni Ojo ti ase isomoloruko ni oko mi ba pemi pe ohun ti wa ni ile ti agbe ki o to lo si ilu oyinbo. Oro yin ko ye mi Mo ooo e gbami ki ni ki se oooo





05/08/2026

KAYEFI NLA GBA NI ORO YI APA KEJI. 💙💙💜❤️❤️❤️💜💜😭🙏🙏🙏🙏😭😭😭😭😭🙆‍♂️🙆‍♂️🙆‍♂️🙆‍♂️🙆‍♂️🙆‍♂️

Bi Mose de odo baba ti Mo lo ni baba ba bi mi pe kilode ti Mo ri oko ni oko emo ti Mo gbin epa si huuuuu olorun ma je ka fi owo ara wa se ara wa ooo🙏🙏🙏🙏 Bi Mose bi baba pe ki ni igbese ti Mo le gbe ati pe ki ni Ona abayo ti oyun o fi ni wale Lara mi Mo ni baba ba ni afi ki Mo bi Mose ma tun oko mi sile ninu yara okunrin ti won fi oko mi si ooooo yara okunrin bi ti Bawo sir ni baba bani ogun emi ni Mo ni nkanmi lo ba oko mi ja pe kosi iyawo to le duro ni odo oko mi 😭🙆‍♂️🙆‍♂️🙆‍♂️🙆‍♂️😭😭😭😭😭😭😭😭😭Bo ti hun komo pe afi ki wa Ona ti Mo fi le Bo kuro lowo arakunrin yin ko ma je pe gbogbo omo to ye ki bi ni Iya oko mi ma baje tan Mo mi Lara. Ahhhhhhhh oro yi ko ti wa ye mi Mo rara bi Mo se 😭😭😭😭😭😭😭de ile ni Mo ba iya oko mi ati omo ti won ni oko mi bi tele ninu yara ti emi pelu oko mi su bi Mo se ba won ninu yara na
Eru bami gidi gidi koda oju ese ni Mo ti dakun lo ahhhhh ni gba ye ni Mo se wa gba owe ti awon baba wa ma pa pe omo de ode ibi eru ni eru oba ase ti omo de ba Debi eru eru ma ba bi Mo se laju pade ni Iya oko mi ni Mo ka Bo se ode dun ati pe ojo wo ni Mo pinu pe Mo fe ko iru mi, larin bi wakatı kan mi le fesi si oro ti won so rara nitori gbogbo ara mi ti fe di omi tan, ki lo wa nsele lehin ti mi le fesi si oro iya oko mi yi. 😳😤😳😳😳😳😳😳😳😳Ahhhhh eyi temi kayefi nla gba ni oro yi, Ejo bi awon omo wa ba fe loko eje ka ran won lowo ninu Adura ati awe ka ri daju pe eri meji si mate fi idi re mule pe ki won fe ara won ko to ti ese Bo oro ife won ooo. Loruko Jesu awon omo wa oni sele yaşı o Amin 🙏. Bi o ba gbadun eto yi lo Jo ma like, share, ki o si bami follow page
. Ese pup. E bami wa ikan fidile e ma bami kalo




04/08/2026

KAYEFI NLA GBA NI ORO YIN.💗💗💗💗💗💗💗💜💜💜💜💜💕💕💙💙💙💙💙🎁🎁🥰🥰APA KIINI.
Ni kan bi mẹlọ sehin ni mo pade omokunrin kan mo nife omokunrin na gan ni,💗💗💗💗💗bi emi pẹlu omokunrin yin. Ko pẹ ni arakunrin náà dá enu ifẹ ko mi bi ẹmi pẹlu arakunrin yin sẹ bẹrẹ ife wa bo werewere niyi. ni ojo kan ni arakunrin yin mu mi lo si odo awon obi re bi mose de odo iya ti o bi lomo mo kiwon terin toyaya awon naa si kimi pade pẹlu ife ko pẹ kojina ni iya re ba pẹ wole larin bi iseju marun si ni awon mejeji ba pade de bi awon mejeji se de ni iya oko mi semi ni alajo mo si fi oyaya pẹlu ife gba lowo won sugbon bi won se salejo mi tan ni iya oko mi ni se oko mi so fun pẹ oun ti ni iyawo kan ri tele, huuuuuuuu🙆‍♂️🙆‍♂️🙆‍♂️🙆‍♂️❤️🙆‍♂️mo da won lọhun pẹ be ni ma ni iya oko mi ba ni ti emi pẹlu oko mi ba ti se igbeyawo tan pẹ omo na ma wa ma gbẹ ni odo wa mo ni ko buru rara. Ahhhhhhh Ko pẹ ko jina ni emi pẹlu oko mi se igbeyawo bi ase se igbeyawo tan ni iya oko mi mu omo ti oko mi bi tele wa gẹgẹ bi oro ajo so wa ahhhhh ile aye ile ogun huuuuuu😭😭😭😭😭😭😭😭😭 bi mose bere sini toju omo re gege bi omo mi niyi ooo ahhhh ase iya oko mi wa fi omo na sọọ mi ni lehin osupa keta ti ase igbeyawo tan, bi iya oko mi se bere sini pẹ omo náà lori erọ ☎️☎️☎️☎️☎️☎️☎️📞📞📞📞ibani soro rẹ niyi ti wọn si bẹrẹ sini bẹrẹ nkan ti omo náà jẹ ati gbogbo ikan to nsele larin ẹmi pẹlu oko mi gbogbo pata ni iya oko mi mo lati igba ye bayi mi ni ifokanbale nile oko mi ooo, eleyi ko tie wa dun mi rara bi ko se pẹ bi mo se loyun ni oyun wale lara mi oyun mafa lo ti wale lara mi to si je pẹ pẹlu inira ni oyun na fi wale lara mi, ahhh bi o se di ojo kan ni mo ba jade si oro ara mi bi mo se de odo baba ti mo lo ni baba bani ki lo de ti mori oko ni oko emo ti mo lo gbin epa si huuu 😭😭😭😭😭😭😭😭😭olotu o da bi pẹ mo ti ki ori ara mi bo jakolọ mi mọ bi mọ ṣẹ ma yo mo ooo. mo ba bere lo baba pẹ kini mo le se ti ma fi bo ninu ogun ti mo ko ara mi si bayi bi baba se so pẹ ona abayo oyokan pẹrẹ lo wa funmi niyi oo. Ahhhhh aye mo ju ba ooo eni bani ko si aye korofo lasun ni iru eni be eyi temi ejo ebami like,share, ki e si follow mi, bi oba gbadun itan arabinrin ti mọ muwá lọsẹ yi lo ti o si fe lati ri awon ipele toku ẹ bami tele page yi . Loruko Jesu aye oni ri wa mu tomotomo ooo Amin 🙏







02/08/2026
02/08/2026

Marriage is sweet if you found your missing rob congratulations 🎉 to mr$mrs perjar

Address

Ibadan
Egbeda
236

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Maami Ile Alayo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share