OMO Akanni FUNNY

OMO Akanni FUNNY Digital creator, comedian, funny,laugh,

Se Àmín Adua yí koto jáde nílé laarọ yi.
27/08/2026

Se Àmín Adua yí koto jáde nílé laarọ yi.

Mo fẹ ra garri ati sugar lọdọ aunty yi ni, sugbon mobawon tiwọn ti sun lọ,mioni da órun mọ wọn lójú maduro kiwọn fi ji n...
26/08/2026

Mo fẹ ra garri ati sugar lọdọ aunty yi ni, sugbon mobawon tiwọn ti sun lọ,mioni da órun mọ wọn lójú maduro kiwọn fi ji ni, ebi npami sugbon mamu mọ ra tiwọn O fi ji,mio like ki nmo da orun mọ eniyan lójú,mo like style orun wọn yi.

Iwọ gẹgẹ bí abiamo ti o ba ju ọmọ rẹ si òkè bayi ti iro idi rẹ wa tuu bayi laiwọ awotẹlẹ kankan si idi,ewo lo ma kọkọ ni...
26/08/2026

Iwọ gẹgẹ bí abiamo ti o ba ju ọmọ rẹ si òkè bayi ti iro idi rẹ wa tuu bayi laiwọ awotẹlẹ kankan si idi,ewo lo ma kọkọ ninu ọmọ rẹ ati iro rẹ ti awọn ọkunrin si wa níbẹ.

Njẹ iwọ la kinni yi ri? Nigbati O wa ni ilé-ìwé alakoko bẹrẹ, Emi la ri dada,atipe kinni orukọ ti ẹyin npe lodo tiyin, l...
26/08/2026

Njẹ iwọ la kinni yi ri? Nigbati O wa ni ilé-ìwé alakoko bẹrẹ, Emi la ri dada,atipe kinni orukọ ti ẹyin npe lodo tiyin, lọdọ tiwa taba taba lawa npe.
゚viralシ ゚

E karo óo, Gbogbo ẹyin ololufẹ mi nile loko,Eku ojumọ óo,Adua Gbogbo wa yo gba óo. ゚viralシ
26/08/2026

E karo óo, Gbogbo ẹyin ololufẹ mi nile loko,Eku ojumọ óo,
Adua Gbogbo wa yo gba óo.
゚viralシ

Ẹyin ọjọgbọn eniyan ẹba wa dasi ọrọ yi óo. ゚viralシ
25/08/2026

Ẹyin ọjọgbọn eniyan ẹba wa dasi ọrọ yi óo.
゚viralシ

25/08/2026

25/08/2026

I thought my situation is worse.

Talo mọ gbajugbaja osere onitiata yi,ki O sọ orúkọ wọn fun wa óo. ゚viralシfypシ゚    ゚viralシ
25/08/2026

Talo mọ gbajugbaja osere onitiata yi,ki O sọ orúkọ wọn fun wa óo.
゚viralシfypシ゚ ゚viralシ

When you destroy, someone's life with lies,take it as a loan it will come back to you with interest.     ゚
25/08/2026

When you destroy, someone's life with lies,take it as a loan it will come back to you with interest.

Address

10, Majekobaje Zone Ogbere Moradeyo Oremeji Agugu Area
Ibadan Outlying
305

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when OMO Akanni FUNNY posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share