20/07/2025
Àsà Ìjesu Titun: Ìhòhò ni mo máa ngún ìyan, Bí Oba ò bá tíì je isu titun, Ewò ni fún enikéni láti je'su... Deaconess Adedayo Theresa Ayo Deji, Akòwé Egbé Olójà isu, Ìpínlè Èkìtì àti Akòwé Egbé Olójà isu, Ìkòlé L.G.A