
31/05/2024
Olúwa Ọlọrun, bí á tí ń wọlé oṣù Òkúdù(June ) , à bẹ fún ìbùkún àti àánú rẹ, fún wá ní ìlera , àṣeyọrí , àti óòrè nínú gbógbo ohùn tí à bá ń ṣe . Ṣe oṣù yìí dì orísun irè àti ìdàgbàsókè fún wá , àwọn ìdílé wá , àti àgbègbè wá.
Yorùbá lawa TV 📺 📺
Ètò ní...