Ayekooto Agbaye

Ayekooto Agbaye Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Ayekooto Agbaye, Media/News Company, Ibadan.

03/05/2026
18/06/2024
Ó tún ti zẹ̀h! Adupe fun Olohun Habeeb Okikiola tí ọ̀pọ̀ mọ̀ sí Portable Zazoo bimo titun.Lára ohun tó fi sójú òpó Insta...
11/12/2022

Ó tún ti zẹ̀h! Adupe fun Olohun

Habeeb Okikiola tí ọ̀pọ̀ mọ̀ sí Portable Zazoo bimo titun.

Lára ohun tó fi sójú òpó Instagram rẹ̀, Portable ni òun dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run fún oore tuntun tó wọlé tọ̀ọ́ wá.

📸: Instagram/ Portable

Owo Ile ise ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ogun tẹ ọmọ ‘Yahoo’ tó lu ọ̀rẹ́bìnrin rẹ̀ pa nítorí owó ‘maga’
02/12/2022

Owo Ile ise ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ogun tẹ ọmọ ‘Yahoo’ tó lu ọ̀rẹ́bìnrin rẹ̀ pa nítorí owó ‘maga’

Lotito ni: Gbèsè tí iye rẹ̀ tó ₦76b ni ijoba Oyetola fi sílẹ̀ fùn wa – Ìjọ̀ba Osun
02/12/2022

Lotito ni: Gbèsè tí iye rẹ̀ tó ₦76b ni ijoba Oyetola fi sílẹ̀ fùn wa – Ìjọ̀ba Osun

Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara, Abdul Rahman AbdulRazaq ti fi Abdulgafar Abiola tí ọ̀pọ̀ mọ̀ sí Cute Abiola jẹ olùrànlọ́wọ́ pàtàkì...
05/11/2022

Gómìnà ìpínlẹ̀ Kwara, Abdul Rahman AbdulRazaq ti fi Abdulgafar Abiola tí ọ̀pọ̀ mọ̀ sí Cute Abiola jẹ olùrànlọ́wọ́ pàtàkì.
Orí ìkànní Twitter ti ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara ni wọ́n ti kéde ipò tí wọ́n fún Cute Abiola tó jẹ́ gbajúgbajà adẹ́rínpòsónú .

Mínísítà fún ọ̀rọ̀ abẹ́lé, Rauf Aregbesola ló ṣe ìkéde yìí ☺️
29/09/2022

Mínísítà fún ọ̀rọ̀ abẹ́lé, Rauf Aregbesola ló ṣe ìkéde yìí ☺️

Èèyàn méje jóná níbi ìjàmbá ọkọ̀ nílùú EkoÌṣẹ̀lẹ́ burúkú yìí ṣẹlẹ̀ ní òpópónà Iyana Oworo lánàá tó sì mú ẹ̀mí èèyàn méje...
27/09/2022

Èèyàn méje jóná níbi ìjàmbá ọkọ̀ nílùú Eko
Ìṣẹ̀lẹ́ burúkú yìí ṣẹlẹ̀ ní òpópónà Iyana Oworo lánàá tó sì mú ẹ̀mí èèyàn méje lọ.
Lára wọn ni obìnrin mẹ́rin, ọkùnrin mẹ́ta àti ọmọ kékeré ọkùnrin kan.
Gẹ́gẹ́ bí ohun tí àjọ LASTMA Eko sọ, ọkọ̀ èrò bọ́ọ̀sì ọ̀hún gbaná látara ìwàkuwà dírẹ́bà ọkọ̀ náà.
Wọ́n dóòlà èmí obìnrin mẹ́ta tí dírẹ́bà sì rọ́nà jáde ṣùgbọ́n òun náà farapa.

Address

Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ayekooto Agbaye posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share