Arẹmọ Apede

Arẹmọ Apede Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Arẹmọ Apede, Digital creator, Ibadan.

31/03/2025

Don't carry your yeye April fool reach my side o 🌚

Odun yii o yeBodun ba dun Bodun ba dunKa dupe lowo Adaniwaye lo toOba to da ni siEdumare to lore emi eeyanTa fi n rohun ...
31/03/2025

Odun yii o ye

Bodun ba dun
Bodun ba dun
Ka dupe lowo Adaniwaye lo to
Oba to da ni si
Edumare to lore emi eeyan
Ta fi n rohun se fulenge fulenge

Odun yii o ye
Agaga beeyan ba ni senji lapo
Beeyan rowo se fuja bo ti fe
Beeyan rowo se faari lawujo
Tori owo ni baba oge

Odun yii o ye
KEdumare ma fowo gbeyin loro mi
Ka rowo sodun baa ti fe
Kawa ma rinrin iya lese
Lojo gbogbo aye ba n dunnu
Tori ojo idunnu la n pe lojo odun
KAdaniwaye ma fi ikoro soro awa.

(C) Arẹmọ Apede looko mi

📷 Ayo Adams

Ore ree lati enu gomina ipinle Oyo- Gomina Seyi Makinde lori oro olori tele Naomi ati Alhaji Oriyomi Hamzat
07/01/2025

Ore ree lati enu gomina ipinle Oyo- Gomina Seyi Makinde lori oro olori tele Naomi ati Alhaji Oriyomi Hamzat

In between 3 months, a new Owa Obokun of Ijesa land has been appointed. It's been over 3 years and we are still waiting ...
29/12/2024

In between 3 months, a new Owa Obokun of Ijesa land has been appointed. It's been over 3 years and we are still waiting for when the new Alaafin will be appointed. Ta lo wa nidi oro Oyo?

Ademola Lookman made history yesterday. He made history as a Yoruba man the moment he greeted everyone watching the awar...
17/12/2024

Ademola Lookman made history yesterday. He made history as a Yoruba man the moment he greeted everyone watching the award ceremony globally in the Yoruba language. Yesterday was another day to be proud of being a Yoruba

O see oko mi

With Samuel Ibikunle ArugboBoisi – I'm on a streak! I've been a top fan for 3 months in a row. 🎉
07/11/2024

With Samuel Ibikunle ArugboBoisi – I'm on a streak! I've been a top fan for 3 months in a row. 🎉

The part this man takes in preserving the Yoruba language can not be forgotten Do you know his name?
07/11/2024

The part this man takes in preserving the Yoruba language can not be forgotten

Do you know his name?

21/10/2024

Eni ba le gunyan san iyan o gbodo beru okele

E ku ojumo o

Ayé, àyèyéèyeAyé àkámaràAyé àká-ìkátán bí ẹní àrà n'ífẹ̀Ayé ḿbẹ níbi tí wọ́n ti ń fi igbá Ògún rọ̀'gúnWọ́n ḿbẹ Ní’bi w...
15/10/2024

Ayé, àyèyéèye
Ayé àkámarà
Ayé àká-ìkátán bí ẹní àrà n'ífẹ̀
Ayé ḿbẹ níbi tí wọ́n ti ń fi igbá Ògún rọ̀'gún
Wọ́n ḿbẹ Ní’bi wọ́n gbé ń f’àwò Òrìṣà á rọ̀’rìṣà
Wọ́n jókǒ ní Ìmẹ̀sí Àyúnpunrẹ́n.
Wọ́n nàró ní Ìmọ̀rẹ̀ Àgbádà
Wọ́n wá fì’kàlẹ̀ sí Oríta-mẹ́ta Àgbáǹsáálá

Tótó Ayé, ayé tótó
Mo júbà ẹ̀yin tíí na ọmọ tí ìyá ẹ̀ ò gbọ́dọ̀ gbin!

We have dropped our moral values and embrace immorality as a way of life. The elderly ones were expected to be guardians...
10/10/2024

We have dropped our moral values and embrace immorality as a way of life. The elderly ones were expected to be guardians guiding the young ones to the right path in life, but the reverse is the case nowadays

O maa se o 🥲

Se agba naa lawon eyi saa?

Address

Ibadan

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Arẹmọ Apede posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Arẹmọ Apede:

Share