Oríkì Elédùmarè

Oríkì Elédùmarè Tali o dabi iwọ, OLUWA, ninu awọn alagbara? tali o dabi iwọ, ologo ni mimọ́, ẹlẹru ni iyìn, ti nṣe ohun iyanu?

18/02/2026

Alleluya sí Ẹni t'oni Ayé àti Ọ̀run ni ikawọ

17/02/2026

‭Eks 15:9-12

Ọtá wipe, Emi o lepa, emi o bá wọn, emi o pín ikogun: a o tẹ́ ifẹkufẹ mi lọrùn lara wọn; emi o fà dà mi yọ, ọwọ́ mi ni yio pa wọn run.

Iwọ si mu afẹfẹ rẹ fẹ́, okun bò wọn mọlẹ: nwọn rì bi ojé ninu omi nla.

Tali o dabi iwọ, OLUWA, ninu awọn alagbara? tali o dabi iwọ, ologo ni mimọ́, ẹlẹru ni iyìn, ti nṣe ohun iyanu?

Iwọ nà ọwọ́ ọtún rẹ, ilẹ gbe wọn mì.

14/07/2025

The Battle is Over

13/07/2025

Follow God's Leading

13/07/2025

God Never Leads Backwards | Bishop David Oyedepo

Address

Ibadan
100212

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Oríkì Elédùmarè posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Oríkì Elédùmarè:

Shortcuts

Share