Ojukaye Tv Backup

Ojukaye Tv Backup Ojukaye TV is a Nigerian-based media platform that offers a variety of content, including news, entertainment, and educational programs.

This page is for MTEtv to entertain people Everytime everyday, stay tuned.

25/08/2026

Oloye Sunday Igboho ṣe Bẹ̀bẹ̀ fún Olorun

25/08/2026

Wọn tí ń lọ gbé Tani Ọlọ́run,

19/08/2026

Si gbogbo eyin tí ẹ bù Are

Gomina Ademola Adeleke jawe Olubori elekeji nínú Idibo Gomina Ní Ìpínlẹ̀ OsunẸ̀jẹ̀ ká báwọn dupe
16/08/2026

Gomina Ademola Adeleke jawe Olubori elekeji nínú Idibo Gomina Ní Ìpínlẹ̀ Osun
Ẹ̀jẹ̀ ká báwọn dupe

05/08/2026

ÀWỌN OLÙGBÉ NÀ KEGBAJARE ILÉ BÚBURÚ TI WỌ́N FIRASI PÉ OJE TI ÀWỌN AJÍNIGBÉ NI OTA
​Ìfoya ńlá be sílẹ̀ ní agbègbè Baba T2 / Oko Ewe-Ijagba / Onigbin ni Ota, Ipinle Ogun lẹ́yìn tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn kó jọ sí àyíká ilé kan lórí ẹ̀sùn pé ó jẹ́ ibi tí wọ́n ti n ṣe àwọn ìgbésẹ̀ ìjínigbé.
​Àwọn pẹ́lú àṣẹ ń bọ̀wọ̀ gba àwọn olùgbé nímọ̀ràn láti wà ní àlàáfíà, láti yẹra fún idájọ́ tó lẹ́yìn òfin (jungle justice), àti láti fún àwọn àjọ àbò ní ààyè láti ṣe ìmújáde ẹ̀sùn náà.

Oya ó, Ṣe ẹyin mo wọn? Ẹ̀jẹ̀ ká daruko won
05/08/2026

Oya ó, Ṣe ẹyin mo wọn? Ẹ̀jẹ̀ ká daruko won

04/08/2026

Ìṣẹ̀lẹ̀ ìjínigbé tuntun L'Ondo

Ere idaraya dara fun agọ ara, ki-in-in iwọ ri ninu aworan yii ?
03/08/2026

Ere idaraya dara fun agọ ara, ki-in-in iwọ ri ninu aworan yii ?

🎓 Ibeere ni kiakia fun ọjọ́ Àìkú... Ṣé ẹnikẹ́ni níbí mọ ohun tí "KOS"  to wa lórí fìlà Sam Larry yìí túmọ̀ sí gan-an❓ Tí...
02/08/2026

🎓 Ibeere ni kiakia fun ọjọ́ Àìkú... Ṣé ẹnikẹ́ni níbí mọ ohun tí "KOS" to wa lórí fìlà Sam Larry yìí túmọ̀ sí gan-an❓
Tí o bá mọ̀ ọ́n, kọ ìtumọ̀ rẹ̀ sí abala àwọn ọ̀rọ̀ àlàyé (comments section).

28/07/2026

Ilé alájà méjì kan wọ ilẹ̀ tó sì wó lulẹ̀ pẹ̀lú àwọn èèyàn tó sẹ̀mọ́ inú rẹ̀ ní Ọ̀nà Baale, Ajuwon, Ajọ Agbègbè Ifo, Ìpínlẹ̀ Ògùn.

Address

Iwo Road
Ibadan
10100

Telephone

+2349136963687

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ojukaye Tv Backup posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Ojukaye Tv Backup:

Shortcuts

Share