Baba Be n Decking

Baba Be n Decking This is where you can watch best movies, music videos, hilarious skits, educative and motivational videos

If you think of mother's agonyand consider father's pain you won't hurt their childIf you think of wife's lonelinessyou ...
17/09/2023

If you think of mother's agony
and consider father's pain
you won't hurt their child

If you think of wife's loneliness
you won't hurt her husband

If you pity this innocent son
and consider that unborn daughter
you won't took their father's life

If you think of brother's tears
and consider sister's trauma
you won't shorten the life of their sibling

If you think of family's grieve
and consider real friend's sadness
you won't hurt their loved one

If you think of fan's heartbreak
and consider music industry's rare talent lost
you won't killed their favorite

But if you're here in 2100, I wrote this in 2023
on 12th of September precisely
because it was a black day in description

If you're reading this anywhere
around the world, I wrote this in Nigeria🇳🇬
for it's a lawless country
because some people are above the law

If you're reading this for any purpose,
I wrote this with tears in my eyes
because no one deserves to die this way

If you're reading this and wondering
whose pen is this
help me tell the world that it's Golden Pen✍️
and I did it for Promise Oladimeji Aloba a.k.a
Mohbad

IMỌLẸ💡IS FINALLY AT PEACE
🕊️🕊️🕊️

©️ẸNIỌBANKẸ✍️

Ti wọn ba ṣèlérí pé àwọn o fún ọ ní   ti o ba jẹ ẹyọkan ekute pie yi, melo lo ma jẹ ninu ẹ?If you ask to eat these for  ...
07/09/2023

Ti wọn ba ṣèlérí pé àwọn o fún ọ ní ti o ba jẹ ẹyọkan ekute pie yi, melo lo ma jẹ ninu ẹ?

If you ask to eat these for each, how many will you eat?

06/09/2023

PLEASE WATCH THE FULL VIDEO ON MY YOUTUBE CHANNEL WITH THIS LINK BELOW 👇👇👇👇
https://youtu.be/Q9znoaUNgDc?si=8wnSfGLS9RYcGQZ1

Whoever trusts on hopes for inheritance, exposes himself to poverty.
Only a fool is always ready to kill his siblings because of properties and only a naive is always plan on how to rob her siblings of their birth rights
Agbójú lógún fi ara rẹ̀ fósì ta ni.

GOLDEN PEN✍️ PRODUCTIONS IS WARNING AGAINST GREEDINESS🙏🙏

Ẹ dákun o ta lo jọ Sola Sobowale ju nínú àwọn méjèèjì yí ooo Toyin Abraham Ajeyemi ati Bimbo Ademoye?              🤔🤔🤔🤔🤔...
04/09/2023

Ẹ dákun o ta lo jọ Sola Sobowale ju nínú àwọn méjèèjì yí ooo Toyin Abraham Ajeyemi ati Bimbo Ademoye?

🤔🤔🤔🤔🤔🤔🤔🤔🤔

TÍO BÁ LE RÍ AMIN SE, MO GBÀDÚRÀ FÚN Ọ PÉ AYÉ O NÍ KAN OGO RẸ MỌ'GI TỌMỌTỌMỌ LASẸ ỌLỌRUN 🙏.
02/09/2023

TÍO BÁ LE RÍ AMIN SE, MO GBÀDÚRÀ FÚN Ọ PÉ AYÉ O NÍ KAN OGO RẸ MỌ'GI TỌMỌTỌMỌ LASẸ ỌLỌRUN 🙏.

Ẹyin témi kilẹ lero pe o le fa ija larin awọn mejeeji🤔?    O da se ki a lawọn àbí kí wọn o ma ja lọ 🙄?
26/08/2023

Ẹyin témi kilẹ lero pe o le fa ija larin awọn mejeeji🤔?

O da se ki a lawọn àbí kí wọn o ma ja lọ 🙄?

Baba Be n Decking o ya mo fẹ sọko sọja, ẹyin témi se ki n sọ ati wipe taa gan lẹ fẹ kí n foko mi sun ninu awọn àgbààgbà ...
26/08/2023

Baba Be n Decking o ya mo fẹ sọko sọja, ẹyin témi se ki n sọ ati wipe taa gan lẹ fẹ kí n foko mi sun ninu awọn àgbààgbà ọjẹlu yi gan?

Wọn ti gbe palliative owo ori epo yin ti wọn yọ de ooo     Se o ti gba tiẹ 🙄🙄?Ah tani Nigeria wa sẹ bayi Ọlọrun 😰😰😰😰😰
25/08/2023

Wọn ti gbe palliative owo ori epo yin ti wọn yọ de ooo
Se o ti gba tiẹ 🙄🙄?

Ah tani Nigeria wa sẹ bayi Ọlọrun 😰😰😰😰😰

Njẹ o mọ wipe infection le s'okunfa airi oyun ni fún Obìnrin?Njẹ o mọ wipe infection le ma mu nkan osu Obinrin se sege-s...
25/08/2023

Njẹ o mọ wipe infection le s'okunfa airi oyun ni fún Obìnrin?

Njẹ o mọ wipe infection le ma mu nkan osu Obinrin se sege-sege?

Njẹ o mọ wipe bi infection ba pẹ la pẹ ju lara Ọkunrin o le fa atọ sisan?

Njẹ o mọ wipe apọju infection le yi ṣi orísirísi àìsàn míràn lagọ ara rẹ?

Kilode ti owo tó níye yíó ma fi alafia rẹ ṣe awada nigbati o le kan sí Golden Pen✍️ lori awọn ẹrọ ibanisọrọ wọnyi 09079040423 tabi 08148294460 lati ra Natural Antibiotics Infection Crusher ti Ile-isẹ Warrah Centre For Natural Herbal Medicines se.

ÀJỌ NAFDAC LU LOUN TẸ

LILO RẸ KO NI ÌPALÁRA KANKAN FUN ẸNI TO BA LO

EWE ATI EGBO NIWỌN FI SE NI ILANA IGBALODE

IBIKIBI TI O BA WA NI AGBO YI TI LE TẸ Ọ LỌWỌ

Address

Ibadan

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Baba Be n Decking posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Baba Be n Decking:

Share