13/08/2026
🔔 Awọn ilé iṣẹ́ ọlọpaa ti pe Senator Fadahunsi lori ọrọ to sọ wípé ó ń gbà àwọn ènìyàn ní ìmọ̀ràn lati "pa awọn ọmọ ẹgbẹ Accord" ṣaaju idibo gomina ipinle Osun.
Wọn ní kó wá sọ nkan tó rí nínú ọ̀bẹ tó fi wá irú sì ọwọ́
Ṣáájú ni Senator Fadunsi tí so ni ibo ìpolongo ibo egbe APC fún idibo Gomina losun pé kí wọ́n máa paa gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ accord tiwọn ba tiri nínú fídíò kan tó gbà ojú ayélujára.
Ẹ ka ẹkùnrẹ́rẹ́ ìròyìn yí ni WhatsApp Channel Ojukaye Tv 👇👇👇👇👇👇🤣 https://whatsapp.com/channel/0029VbCAIBdF1YlZHekzMo2g