11/06/2026
O sele! Sunday Igboho ko leta si Gomina Seyi Makinde t'ipinle Oyo
*O ni ko yonda fun awon eso aabo Iru Ekun oun lati maa d'aabo bo gbogbo ileewe ijoba n'ipinle Oyo
*Bee lo tun kan saara si akitiyan Makinde l'ori oro awon akekoo ati oluko t'awon afemisofo ji ko n'iluu Ahoro-Esinele l'Ogboomoso