Oyinladun TV

Oyinladun TV Indigenous Speaker | Yorùbá Pọ́nńbélé | Edutainer | Adverts |
(2)

Ìwúye Olúbàdàn👑👑👑 Kẹrìnlélógójì, Ọba Ràṣídì Ládọjà Adéwọ̀lú dùn, gbọ́ngbọ́n kán sí.🎉🎉🎉🎉🎉 ̀ #Àṣà
27/09/2025

Ìwúye Olúbàdàn👑👑👑 Kẹrìnlélógójì, Ọba Ràṣídì Ládọjà Adéwọ̀lú dùn, gbọ́ngbọ́n kán sí.🎉🎉🎉🎉🎉

̀
#Àṣà

Congratulations HRM Oba Rasheed Adewolu Akanmu Ladoja Arusa 1 Born in 1944 now 44th Olubadan Aku orire gbogbo omo ibadan...
26/09/2025

Congratulations HRM Oba Rasheed Adewolu Akanmu Ladoja Arusa 1
Born in 1944
now 44th Olubadan
Aku orire gbogbo omo ibadan lapapo

25/09/2025

Àyọkà láti inú OGUN ÀWÍTẸ́LẸ̀ tí Adébáyọ̀ Fálétí kọ:

“Ile Ọlọkọ Meje,
Agọ Idahọmi,
Ọjọ Jakuta.

Baba wa ọwọn,

Ki ẹ pẹ fun wa; ki ẹ gbọ, ki ẹ tọ o. Ọrọ wa si nyin ko to nkan. Ẹyin agba ni ẹ npa owe kan pe, ‘Ogun Awitẹlẹ ki i p’arọ’. Nitorina, a fẹ ki ẹ gbọ silẹ pe a ó wa ja nyin l’ole ni ọjọ meje oni. A si fẹ ki ẹ mura silẹ de wa. A ko fẹ ki ọrọ na ba nyin lojiji. Ki awọn ọdẹ nyin má jafara o.

Ọrọ wa ko ju bẹẹ lọ

Awa ni Ẹgbẹ Ọlọṣa ti o wa ni Ago Idahọmi.
Emi olori wọn ni Ajibógunsọrọ Ajani.”


25/09/2025
25/09/2025

Kọ́kọ́rọ́ ilé 🏠.
Lẹ́tà Hajj 🕋.
lẹ́tà iṣẹ́ ìdùnnú 📝✉️.
fún gbogbo ọwọ́ tó bá tẹ ✍️Àmín 🤲

25/09/2025

Greetings in YORÙBÁ

Happy Birthday to meeeeeee!😁😁😁OLÚṢỌLÁ ÀṢÀKẸ́ ARẸ́SẸ̀TẸLẸ̀!IGIOLÚGBÌN tí ò ṣeé tì ṣubú!Mo dúpẹ́ f'ÓLÙGBÉNIRÓ Tí Ńbẹ̀ l'óò...
24/09/2025

Happy Birthday to meeeeeee!
😁😁😁

OLÚṢỌLÁ ÀṢÀKẸ́ ARẸ́SẸ̀TẸLẸ̀!

IGIOLÚGBÌN tí ò ṣeé tì ṣubú!

Mo dúpẹ́ f'ÓLÙGBÉNIRÓ Tí Ńbẹ̀ l'óòró t'Ó Gbé mi ró!

OL'ÓKÙN un fàdákà tí ò jẹ́ ó já, mo dúpẹ́!

Mo dúpẹ́ pé mi ò rì sínú ìrírí!

I could have drowned! I would have drowned! I was expected to drown! Because I dare to strive for better! Ha! Because I had the courage to refuse the àbáńlẹ̀!

Mo dúpẹ́ pé'mọ́lẹ̀ mi ò kú!

Ọpẹ́ mi pọ̀!

That I can see a new year, I am grateful, immensely, eternally!

That I didn't drown in life's tribulations!

That I didn't become naked!

That I am always rescued and cared for!

That I have this privilege to be this privileged!!!

That I can be a blessing! Ohhhh! This one touches me deeply in a different way!

Even in my pain, in my imperfection, in my growth and becoming, I am being used to help others as me! 🥹🥹

Mo dúpẹ́ ooooo!
OLÚWA ỌLỌ́RUN OLÓDÙMARÈ!!!
Ìgbàfún ati Ìgbàláàyè mi!
Mo dúpẹ́!

Ha!
Story pọ̀!

These particular pictures state the state of my mind, heart and soul. I keep my gaze Upways in all ways!

To EVERYONE who stood by me in the tribulations of the past year, I am GRATEFUL! You all shall NEVER lack help in every way help means to you!

Olúṣọlá ìmọ́lẹ̀!
Àìlèkú n'ìmọ́lẹ̀!
Olúṣọlá ìmọ́lẹ̀
Àtàndalẹ́ n'ìmọ́lẹ̀!

A better and greater is here!
Older. Finer. Refined. Wiser. Lessons learnt!

Life, óyá bring rewards! Mine of the commonwealth in Creation! Mo ti learn àwọn lessons yẹn!

Olúṣọlá Àmọ̀káyé is the new name added to me!
General Public, take note! 😁

Àmọ́káyé l'èmi Olúṣọlá Àṣàkẹ́ Arẹ́sẹ̀tẹlẹ̀!

Kárí!

This way I'll be, in life, for life!

! ❤️

https://m.facebook.com/story.php?story_fbid=122152431272773316&id=61573199484872
23/09/2025

https://m.facebook.com/story.php?story_fbid=122152431272773316&id=61573199484872

Ẹfúnṣetán Aníwúrà, Ìyálóde Ìbàdàn jẹ́ eré oníṣe láti ọwọ́ọ Akínwùmí Ìṣọ̀lá tí University Press PLC tẹ̀ jáde ní ọdún 1970. Ìwé náà ṣe àfihàn eewu ìwà ìkà lórí àwùjọ láti ara ìgbésí ayé Ẹfúnṣetán Aníwúrà tí í ṣe Ìyálóde kejì nínú ìtàn ìṣẹ́dálẹ̀ Ìbàdàn.

Lára kókó-ọ̀rọ̀ nínú eré oníṣe yìí lati rí ìwà ìkà, ṣísi-agbára-lò, ìkonilẹ́rú, ìfẹ́, àti ìdájọ àjùmọ̀ṣe.

Bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n ti gbé eré oníṣe yìí jáde ní orí-ìtàgé ní ọ̀pọ̀ ìgbà, Túndé Kèlání ni ó ṣọ ọ́ di fíìmù àgbéléwò ní ọdún 2005. Pamela J. Smith sì túmọ̀ rẹ̀ àti eré oníṣe mìíràn tí Akínwùmí Ìṣọ̀lá kọ sí èdè Gẹ̀ẹ́sì ní ọdún tó tẹ̀ lé e gẹ́gẹ́ bíi Ẹfúnṣetán Aníwúrà, Ìyálóde Ìbàdàn and Tinúubú, Ìyálóde Ẹ̀gbá.


📢 !!!OLUBADAN CORONATION: TRAFFIC ADVISORYTraffic Diversion in Ibadan as Tinubu Attends Olubadan Coronation FridayThe Co...
23/09/2025

📢 !!!

OLUBADAN CORONATION: TRAFFIC ADVISORY
Traffic Diversion in Ibadan as Tinubu Attends Olubadan Coronation Friday

The Coronation Organising Committee for installing the 44th Olubadan of Ibadanland, Oba Rashidi Ladoja, has announced traffic diversions ahead of the ceremony scheduled for Friday, September 26, 2025, at the historic Mapo Hall.

In a traffic advisory issued on Tuesday, the security sub-committee under the general committee chaired by former CCII President, Chief Bayo Oyero, disclosed that the diversions are necessary due to the attendance of President Bola Tinubu, who has confirmed he will be present at the coronation.

According to the advisory, the affected routes will be closed from 7:00 a.m. on Friday. The routes include Beere Junction inward Mapo Hall; Born Photo Junction inward Oja’ba; Idi-Arere Junction inward Oja’ba; and Itamerin Junction inward Mapo Hall.

To ease the movement of guests, the committee designated three official parking areas: the Ibadan North Local Government car park in front of the Immigration Office, Agodi; the football field beside Yemetu Police Station; and Liberty Stadium, Oke Ado.

The committee also announced that shuttle buses will be available to convey well-wishers with valid invitation cards from the designated parks to Mapo Hall.

Food vendors and other traders were advised to arrive at the venue between 6:00 a.m. and 6:45 a.m. before the commencement of the road closures.

The committee emphasized that only the convoys of President Tinubu and Oyo State Governor, ‘Seyi Makinde, will be permitted to access the restricted routes leading directly to Mapo Hall.

✍️OLÚBÀDAN IS A POWERFUL KING👑🤍✍️OLÚ OF ÌBÀDÀN is a powerful king as you know that the city was established by a Prince ...
22/09/2025

✍️OLÚBÀDAN IS A POWERFUL KING👑🤍✍️

OLÚ OF ÌBÀDÀN is a powerful king as you know that the city was established by a Prince from ILÉ IFẸ̀ called LÁGELÚ ORO APATAMAJA AJAGUN OSUN. He came from DALEGU COMPOUND,Ajamọpo Oke Eso in ILE IFẸ. He was a grandson from ỌRUNTO-AGA LINEAGE where ỌBALUFẸ ,the prime minister,the second in command and head of ỌỌNI OF IFẸ council comes from in ILE IFẸ. His mother is the only female ỌỌNI OF IFẸ LÚWÒÓ GBÀGÍDÁ and his father is OLOYE ỌBÁLỌ́RÀN a member of the council of ỌỌNI OF IFẸ. He is a sibling of ADEKOLA TELU who is the father of ÌWÓ OLODO ỌBA where OLU OF IWO rules today without any respect for his ancestors.

We are not ọmọ àlè,we know our history.We must know that IFẸ̀ is our ancestral home,where many warriors left to establish bigger kingdoms and empires. IBADAN ỌMỌ A JÒRO SÙN. IBADAN existed long before IBALOGUN OLUYỌLE was born but he developed the city,and his name has never been forgotten like other leaders.

IBADAN was a home for warriors from IFẸ, Ọ̀YỌ́, IJẸBU , ẸGBA AND OWU before OWU was destroyed and Ẹgba moved to Abeokuta. In 1640 LAGELU was installed as the BALOGUN Ọ̀YỌ́ EMPIRE by ALAAFIN AJAGBO,but it was not long when ALAAFIN began to order for the destruction of ÌBÀDÀN.ALAAFIN ORDERED for the destruction of IBADAN when Ọ̀YỌ́ was so powerful during the time of BAṢORUN GAHA.

IBADADAN had to take refuge when Ọ̀YỌ́ was powerful , before Ibadan was resconstructed and rebuilt later.IBADAN was ruled by warriors from YORUBALAND, and MAYẸ OKUNADE from ILE IFẸ became the leader of the Ibadan warriors,he also became the BAALE.He was attacked later by Ọ̀YỌ́ warriors,he was later killed as well as warriors were fighting for dominance. Even though the story behind the GBANAMU WAR is complicated as the Ọ̀YỌ́ WARRIORS were described as begging MAYẸ to make peace,but he did not listen,it was described as a POLITICAL war of control.

Ọ̀YỌ́ people who should support ALAAFIN OLUEWU were more interested in taking control of IBADAN,they succeded in IBADAN,but ATIBA failed to defend Ọ̀YỌ́ ILE.ATIBA promised IBA OLUYỌLE and KURUNMI IJAIYE to honour them with titles. Ọ̀YỌ́ WARRIORS had to kill MÁYẸ̀ and sent his group from ILE IFẸ out of IBADAN,so that they can gain total control after OWÙ had been destroyed too and ẸGBA had relocated to ABEOKUTA. Ẹ̀GBÁ had victory over Ọ̀YỌ́ during the time of ALAAFIN ABIODUN before the time of MÁYẸ,even though Ẹgbado used to be under Ọ̀YỌ́ when the Empire was very strong. Even though Ọ̀YỌ́ warrior gained upper hand in IBADAN,there were unable control for long because other strong warriors from ILORIN,OFFA,OGBOMỌSỌ,ỌṢUN and other town continued to rule after IBA OLUYỌLE who succeeded OLUYẸDUN and his Eight MILITARY OLIGARCHY.

OLUYỌLE established the military system which allowed war leaders to have administrative functions.He became the BAALẸ himself,and other offices followed. The system allowed everyone to ascend from low rank to the upper rank,and eventually became the BAALÈ. IBADAN was able to unite well,they were working towards how to be the next powerful EMPIRE years later when they became more powerful.

AFTER Ọ̀YỌ́ ILÉ collapsed, IBADAN and IJAIYE helped ATIBA to become ALAAFIN ÀGỌ́DỌ̀YỌ́,he was asked to leave the land of ÀGỌ́ ỌJÁ,but with the support of IBADAN,he refused to leave the Land of OGBOMỌṢỌ́. This is why Ọ̀YỌ́ ATIBA should never look down on IBADAN at all. After ATIBA became ALAAFIN,he does not want his son to die with him as the traditional custom of Ọ̀YỌ́,created by THE Ọ̀YỌ́MÈSÌ since the time of ALAAFIN ÒJÍGÍ whose son was ordered to die after he was rejected too. This issue led to the IBADAN-IJAIYE WAR where IBADAN defended ALAAFIN ATIBA,and fought his battle,so that his son ADELU AGUNLOYE can live to reign after his father. Five sons of KURUNMI IJAIYE died in this battle,and he died himself,giving IBADAN total victory over KURUNMI IJAIYE who was once an allie too.

AGỌDỌYỌ ATIBA is younger than IBADAN,and without IBADAN,Ọ̀YỌ́ ATIBA was powerless. IBADAN were diplomatic and more strategic in their system of collecting takex to build their economy. They appointed Ajẹlẹ to Regions where Ọ̀YỌ́ EMPIRE could not control such as EKITI REGION. IJẸṢA recorded victory over Ọ̀YỌ́ warriors during the time of ALAAFIN ỌBALOKUN,this made many to fear the IJẸṢA,but IBADAN was able to fight win IJESA in the 1850s where ILEṢA agreed to be paying trubutes to IBADAN until 1877 when KIRIJI WAR started.

Ọ̀YỌ́ HAD TO SEEK PROTECTION FROM IBADAN FROM THE FULANI ILORIN. ALAAFIN ADEYẸMI ALOWOLODU I WAS RULING FROM ÀGỌ́DỌ̀YỌ́ WITH INDEPENDENT POWER ,WHICH CAME TO AN END WHEN THE BRITISH PUT Ọ̀YỌ́ UNDER CONTROL BY SIGNING TREATY WITH THEM. Alaafin lost his independence,he had to follow the British treaty. AARE LATOOṢA was more powerful,he refused the title of BAALE,he pereffered to be AARE ỌNA KAKANFO,he appointed AJẸ́LẸ́S and was in control of power. He got rid of the notorious woman ẸFUNṢETAN ANIWURA, who was accussed of killing her slaves and maltreating them.

IBADAN still give ALAAFIN his respect,even though they knew that AGỌDỌYỌ is younger than their Land, that is respect. But Ọ̀YỌ́ ATIBA has not been thankful enough to IBADAN for protecting them from war,and helping them to save the life of their Prince ADELU. I would encourage all Ọ̀YỌ́ ATIBA people to be thankful to IBADAN for all the support given in the past.

IBADAN EMPIRE FELL,BUT THEIR MONACHY SYSTEM HAS BEEN WORKING WITHOUT ANY CONSULTATION OF IFÁ OR ANY ARGUEMENT,BECAUSE THE SYSTEM HAD BEEN STRUCTURED IN SUCH A WAY THAT THE NEXT CHIEF TO BE CROWNED IS KNOWN WHEN AS ỌTÚN OR BALOGUN,IT DEPENDS ON WHICH LINE RULED LAST. THE THIRD LINE IS IYALODE LINE,BUT ONLY MALE CAN EVER GET TO THE LEVEL OF OLUBADAN IN THIS LINE. This is the best system for a
Land where they understand that everyone is entitled to be a Leader,and this system has been preserved eversince.

BAALE WAS CHANGED TO OLU OF IBADAN IN 1936.
Even though the Baale were known as OLUBADAN,but it was officially recognised as the position of ỌBA and not only a warlord during reign of ỌBA ABASS OKUỌLA ALẸṢINLỌYẸ. He did not wear a bearded crown until the reign of OLUBADAN GBADAMỌSI AKANBI ADEBIMPE in 1976-1977 before ỌBA DANIEL TAYỌ AKINBIYI who wore it from the day of his coronation in 1977. IBADAN has been successful eversince,expanding daily. Everyone from IBADAN can become a King one day if they are one of the MOGAJI,also if they are still alive.

Congratulations to ỌBA RASIDI LADỌJA who had served as the Governor of the state,and also as senator. Congratulations to us all ỌMỌLUWABI ALẸ̀ IFẸ ,ỌMỌ IRUNMỌLẸ, ỌMỌ ALẸ̀ UFẸ̀ all over the world. OUR IBADAN PEOPLE, AKÚ ORÍRE Ò🤍👑🤍👏
ÌGBÀ ỌBA LADỌJA Á TÙ WÁ LÁRA. ÀṢẸ🙇🏽

Address

Ibadan

Telephone

+2349069021873

Website

https://instagram.com/oyinladun_eyinjueledumare?igshid=NTA5ZTk1NT

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Oyinladun TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Oyinladun TV:

Share