Egbe awon obinrin ni ipinle Ebonyi fesun kan Gomina Umahi pe o n fi iko eso re dunkooko mo awon.== DBC.Africa.Television
24/08/2022
Aregbesola fi okan awon ara ilu bale pe ipenija aabo yoo dopin laipe.== DBC.Africa.Television
24/08/2022
Egbe Arewa gbena wioju ijoba lori ise akanse opa-epo-robi ti won gbe fun Tompolo ni ekun Niger Delta.== DBC.Africa.Television
24/08/2022
Ajo NDLEA gba oogun oloro ti owo re to bi milionu meji aabo naira lowo awon oloogun oloro to fe gbe oogun oloro wo ekun Ariwa ti won si ti mu won.== DBC.Africa.Television
24/08/2022
Awon afurasi afemisofo pa oloye egbe oselu APC ti won si ko awon oloye egbe oselu naa lo si ahamo won.== DBC.Africa.Television
24/08/2022
Ile Asofin ipinle oyo fowo si eyawo oni Bilionu meje aabo le die naira ti Gomina Seyi Makinde beere fun nitori akanse ise agbe.== DBC.Africa.Television
24/08/2022
Awon omo ogun ijoba gba agbara lowo awon alakatakiti Al-Shabab lorile-ede Somalia.== DBC.Africa.Television
24/08/2022
Owo ba awon afurasi to sekolu si awon akekoo ni fasiti ipinle Ekiti (EKSU).== DBC.Africa.Television
24/08/2022
Fasiti kan gbe ile ekowon kuro nibi to wa tele ni ilu kaduna lataari bi won se padanu akekoo marun-un lowo ikolu awon agbebon.== DBC.Africa.Television
Be the first to know and let us send you an email when DBC.Africa.Television posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.