27/08/2026
OGUN OSOLE OWO
Odidi olongbo aye kan. Ao gbe sinu apo. Ao lu mole ti yio fi ku. Ao wa gbe sinu ikoko tuntun. Ao fi tangiri kan ati odidi atare kan le ori olongbo yen ninu ikoko, ao wa ko opolopo iru isebe si ti yio bo olongbo ati awon nkan yoku ti ako ni riwon mo ao wa jopapo, ao lokuna,ao wa ro sinu igo kan, lilo re,ao ma fi fo eko tutu mu, ni ojomedogun medogun, emeji losun fun igba akoko, leyin re ao ma fi ........, lo ni ojo marun marun, pelu aniyan owo pe ki won ma gbe wa fun wa.
Pademi lori WhatsApp group 5k pere ni fum alaye lekunrere
+2348035295300
+2348022870944
OGUN AWORO
Ewe kole ologba tutu, ao gun mo ose dudu ao fi wara tutu toje toojo po papo mo ose, ao ko sinu a*o funfun ao da oyin gidi bi sibi meta lelori, ao gbe pamo fun ojo meje, leyin ojo keje ao ma......., pelu gbolohun yi, warawara ni kole ologba n se oje, warawara ni ki awon onibara mi oma rowa lomode ati agba wa bami ra oja mi, ao pele ori ose na ao ma... ..
Fun alaye lekunrere pademi lori WhatsApp group 5k pere ni owo iwole
+2348035295300
+2348022870944