22/09/2025
ÀPÈJỌ ÀWỌN ỌMỌ IGBEJI
Èyí ni ìpè sí gbogbo ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin ìlú Igbeji pé kí wọ́n wá sí àpéjọ àgbà tó máa wáyé ní:
ỌJỌ́: Ṣátidé, Ọjọ́ 27, Oṣù Kẹsán, Ọdún 2025
ÀKÓKÒ: Agọ́ méjì osan (2:00pm)
IBÌKAN: Ìlú Igbeji
Àpéjọ yìí ṣe pàtàkì gidigidi nítorí ọ̀pọ̀ ọ̀ràn nípa ìdàgbàsókè ìlú Igbeji yóò jẹ́ kókó ìjíròrò.
Ẹ jẹ́ ká ṣáájú láti sọ fún àwọn ará wa tí kò sí lórí pẹpẹ yìí.
ITESIWAJU ILU IGBEJI, AJUMOSE GBỌGBỌ WA NI!!!