10/06/2026
IMULE AWON AGBA TODAJU BIIKU.
Follow page mi koto se ise Yi
Ao lo get eye ega ako ati abo.ado ijamon meta.odidi atare nla kan.ao wa jo eye mejeji pelu ado eyokan pelu atare yen papo. Leyina ao ro sinu ado miran .ao tun jo papo .ao lo tio kuna dada .ao wa ro sinu ado keta .ao so okun si ao mon gbe ko .abi ka gbe pamon ko gbodo kan ile mo rara oh.
OFORE .......
eye wonu eye.ado wonu ado.emi lagbaja omo lagbaja moti di eye olukotun lati oni lo.ati oso ati aje ati emere ati gbogbo eyin alagbara aye pata..e gbodo di emi lagbaja omo lagbaja lowo lori gbogbo ikan ti mobase .gbogbo ise ti moba si lo.eje koma dahun lara mi.gbogbo ikan ti moba si da owo✋mi le e je ko ma yori si dada.leyina ao da aniyan si dada.ao wa bu die ninu ogun yen ao fi ro ekuru funfun je.ekan soso larin ose.once in a week. .bi abawa ri ekuru funfun kafi fo eko tutu mu.
ENIKENI TOBA SHARE ISE MI LOSI ANOTHER GROUP,KONI SISE FUN OH.
AMIN ASE NTEDUMARE.
fun ibere 09012231077