Ewe Nje Ogun Wa

Ewe Nje Ogun Wa Thank you for contacting Ewe Nje we deal with any kind of spiritual problem u involved And Match making Please let us know how we can help you.

With Everything 📿 with everything you need to know about your life 🧬 and so on

OSE TIA FI NWE OWO KOWO KURO LARA.(1)Obi abata oloju meta(2) Ewe iyalode meta(3) Ewe akoko meta(4) Ose die.. Eyikeyi ose...
24/07/2026

OSE TIA FI NWE OWO KOWO KURO LARA.
(1)Obi abata oloju meta

(2) Ewe iyalode meta

(3) Ewe akoko meta

(4) Ose die.. Eyikeyi ose

SISE_RE:-

Ao pa obi yi, ao mu awe kan pelu ewe iyalode kan, ewe akoko kan ao lo kuna daada, ao wa pomo ose iwe ekan soso, ao se be lona meta, ao fi ori para ti aba fe we ni akoko, epo pupa ni ao koko fi para ti a bafe we ikeji, adin ni ao fi para ni ojo iketa, ao we ni ojo aiku, ojo aje, ati ojo isegun. (Sunday, Monday, Tuesday).. Sugbon mase alaimore tio bafe kosise fun oo. mase ko iseyi sile tabi se ise yi lai share re tori anfani elomiran kosi comment dupe lowo olorun ooo tio bafe kosise fun oo..

ENITI ISENA BAWU LATI SE SUGBON TIKO SI AYE TABI TIKO MA BI O FESE KIO MESSAGE MI LORI WHATSAPP ((09012231077)) ALE RAN YIN LOWO LATI BAYIN SE..

FUN IBEERE ABI FUN IRANLOWO LORI ISORO ABI OGUN TI OUN DOJUKO MESSAGE MI LORI WHATSAPP ((09012231077)) TIO BANI IGBAGBO

LATI OWO EWE NJE OGUN WA

ASIRI BIBO OWO TODAJU------------     Ope nifun olohun oba toseda ewe ati egbo toni komaje iwulo fun awa eda re toda say...
16/07/2026

ASIRI BIBO OWO TODAJU
------------

Ope nifun olohun oba toseda ewe ati egbo toni komaje iwulo fun awa eda re toda saye lati lelo fun eyikeyi ipenija isoro ti eda bandojuko ninu aiye.

Aseje yi dara pupo fun gbogbo eda tonsise aje boya ise owo nitie tabi onisowo niwo gbiyanju koje aseje yi, ose tio baje wadupe fun olohun ni ose yen.

Awon nkan ti aolo wa niyi
-------------------

(1) Eja aro kan

(2) Ewe onitikuti

(3) Ewe eela

(4) Ewe abamoda

(5) Ata ijosi merindilogun (16)

Bi aotise ise na niyi:- Ao lo awon ewe meteta papo mo ata ijosi yen ao wa fise eja aro yi je lepo niyo pelu isasun tuntun,ao ge eje aro na si meta sugbon ao ni geja, tobajina kaje kotutu kakoje pelu adura pelu ogo olohun ao dupe fun olohun oba toseda ewe ati egbo.

Toba salabapade iseyi gbinyanju kofi ranse si elomiran koleje anfani funwon
Follow page mi Fun Anfani mi

AGBELEPOTA Lati owo Ewe Nje Ogun Wa Fun ibere call 0r Whatsapp 09012231077Ise yi je isora lodo ota, olohun oba ti o dawa...
13/07/2026

AGBELEPOTA
Lati owo Ewe Nje Ogun Wa
Fun ibere call 0r Whatsapp 09012231077
Ise yi je isora lodo ota, olohun oba ti o dawa gan so wipe ki a wa isora lodo ota, bee, akogbodo wo ota niran ki o ni ikapa lori wa.

Lododo, kosi nkan ti olohun oba kole se, sugbon nkan ti konise lopo, olohun oba ti da Gbogbo wa si aye, o wa ni ki a dabobo ara wa ni Gbogbo ona nitoripe olohun oba pataki Emi wa gidi gan.

Ota ti da irin Ajo Aye Elomiran ru debi wipe Atije, Atimu wa di isoro, Aisan ni won fi kolu elomiran, bee, Agbana ni ti elomiran.

Ohun ti o bamileru ni pe, Olohun oba ni ohun koni fun Eniyan ni agbara kan, ki ohun wa sowipe ki eni na ki o ma lo agbara na, Ti o ba fun ni lagbara lati le pa, koni sowipe ki o ma pa a o, ti eda ba nwo Ota ti o fe se ni laburu niran, ti ota na fi pada pa eni na, o sese ki ota na ki o pada ronu piwada o ki olohun oba ki o si forijin na, Toripe Oba Alaforijin ni o pe Ara re, sugbon iwo si ti wani inu koto.

Fun idi eyi, Omo iya mi, mase wo ota niran ki o nikapa lori aye re o, iwo ni ki o wa iso, ki o si sa Asala fun emi ara re o, nitoripe ti ota ba pa o, o ku gbe ni yen ooo!

OHUN TI AO WA
Ejo Eyikeyi Tutu
Ewe Lefun losun
Epo obo

BI AO SESE
Ao gbe Ejo na sinu Agbada, ao ko ewe yi le lori, ao wa gbe Epo obo yi le lori, ao fi odidi atare kan lelori, ao jo.

Ao po ebu yi papo mo Eyikeyi ose ti o ba wuwa.

Lilo re
Ojo merindinlogun (16 Days) ni ao fi we ose yi.
Ti eniyan bari ose yi we pari, mofi olohun oba ti o dami se eri, ti ota ba ngbero Aburu tabi pe ori wa ni Aida, Ejo ni yi o san Ota na pa ti kobajawo!

Imoran ota koni se lori Gbogbo wa oo🙏 je Ogun wa

ABAMODA  #30000 OJOJUMO TODAJU.RIDAJU PE O PEMI KOTO SE OOO 09012231077 ko SI follow page mi  Ise ti enwo lokeyi..daju o...
10/07/2026

ABAMODA #30000 OJOJUMO TODAJU.
RIDAJU PE O PEMI KOTO SE OOO 09012231077 ko SI follow page mi
Ise ti enwo lokeyi..daju osilagbaraa dipe mmmm miofeefigbogbo enusoro jare
Ejekati ibipelebe mu òòlee(moimoi) jéé... Gbiyanju ki ose asiriyi..ki asiri ounje tiee kókó bo ninu ilé ree pelu Iwo ati famili ree...iseyi waa maa mu egbérun metaa nibee ni ojojumo...mafoju kere asiriyi raaraa.. Iwona gbiyanju rewo kolemodaju wípé kise gbogbo asiri ori Facebook ni ayederu ,erijaa ise kopo raaraa emaabamikalo.......
Eroja.. Re Reoo..
RIDAJU PE O PEMI KOTO SE OOO 09012231077
EWE ABAMODA oni gaga meta
Owo pepa to tobijulo ni ilu tawaa eyokan...pere
Eyin eyele eyokan, ayin aparo eyokan.
Eyin alapandeedee eyokan
Aojopapoo... Aorosinu ado ijamo, aogbe adoyi sinu asuwon funfun..ojumiran kogbudori...
Bi ogo se nje tolorun obami edumare.. Ti abaloye iseyiwo ni ojo keji aoti baa 30000 ninu asuwon yi...sugbon aogbodo timu owoyioo.. Aoje koto ojoketaa kato bere sinimu owoyioo
Tor kojubeeloo
09012231077
NOTE: RIDAJU PE O PEMI KOTO SE OOO 09012231077
Jowo fi emi imore han ni abee post miyi.
Fun Iwo tikobale Raye sise iseyi..boyaa fun idikan tabi idikeji kansimi maa baa oo se.
Ti ohunkohun baru o loju ninu iseyi beree madaa olohun..09012231077
Jowo mako iseyi kale lasan bamidanwo..kiomari nkan gbo bukata dieediee. Ninu famili ree.
(RODAJU PE OPEMI KOTOSE OOOO)09012231077
Fun ekunrere ibere Kandi mi Lori ero WhatsApp mi tabi kio pemi sori ero ibani soro min 09012231077

EBE AWỌN AGBA ((RIDAJU PE O PE MI KOTO SE OOO 09012231077))KOSI FOLLOW PAGE MIẹyẹ alapandede 3,Atare aja 3,Iṣasun tuntun...
28/06/2026

EBE AWỌN AGBA
((RIDAJU PE O PE MI KOTO SE OOO 09012231077))
KOSI FOLLOW PAGE MI
ẹyẹ alapandede 3,
Atare aja 3,
Iṣasun tuntun kekere 3,
Ao jo atare aja kan pelu alapandede kan ninu iṣasun akọkọ,
Atare kan alapandede kan ninu iṣasun keji,
Atare kan alapandede kan ninu iṣasun kẹta,
Ao lọ awọn nkan yi ninu isasun olukuluku won
(Akilọ lori ọlọ o, idi awọn iṣasun yi kosi gbodo kanle,)
Ào gbe awọn ikoko meteta yi pamo si ibi ti oma ni ọ̀wọ̀,
Ti oba di agogo mejila oru ọjọ àkọkọ ti aba fe lo ao gbe iṣasun kan, ao bo eko elewe odindi kan sinu rẹ ,aofi ọwọ fọ ẹkọ naa pẹlu etu to ńbẹ ninu rẹ
Note..(ese wa ko gbọdọ kan ilẹ ni asiko ti aba fẹ ṣe nkan yio, ale joko sori bed ,tabi nkan miran ki ẹsẹ wa ṣa ti ma kan ilẹ t**i aofi ṣetan,
Ao fi omi si agbe eko inu ikoko naa mu,
Aolo fọ ikoko naa mọ oríta ni owurọ
((Ridaju pe O pemi koto seoo 09012231077))
Ti oba di oru ọjọ keji,aotun gbe iṣasun keji ao ṣe bii ati ṣe ti akọkọ,
Ti oba tun di oru ọjọ kẹta aotun ṣe bẹẹ,
Odaju
Gbogbo ohun ti oju ba ri kọ ni ẹnu nsọ o
Tokunrin tobinrin ni iṣẹ yi wa fun
Ao ri iyọnu lati ọdọ àwọn agba
Wọn yio si jọwọ wa si dáadáa
Adura kan lati enu rẹ
Follow page Yi fun anfani mi
Ridaju pe O pemi koto se ise Yi ooo 09012231077

FUN ANFANI AWON TI WON SESE DARAPO MON WA NINU PAGE YII IWO NA SARE LO GBIYANJU ASIRI YI NI KIA KIA     ITUWO AYE KIA KI...
27/06/2026

FUN ANFANI AWON TI WON SESE DARAPO MON WA NINU PAGE YII

IWO NA SARE LO GBIYANJU ASIRI YI NI KIA KIA

ITUWO AYE KIA KIA

ao wa ewe onitikuti (ewe tomatoes) die , ao gun papo Mon ose dudu iwe ekan pere , ao fi epo pupa para ki ato we ose yen ,

Wiwere,,,,, alewe ni ile iwe tabi odo toba un San , ni igbakugba toba wuwa ni wiwe re o

Opolopo awon eniyan ma nsope iseyi ma n ba ise je ninu ile, iro nii, ti ise koba confirmed ni oo, opolopo igba ni emi ma n we ninu ile daada, ti kosiba nkan kan je ninu ise towa ninu ile rara , eje kalo wa imon kun imon kato masoro ooo, k**a ma si awon eniyan lona oo

(09012231077)

Comments kobaleje fun e oo
Ko follow page MI OOO

AWẸNU IJAKULE PROMISE AND FAIL ATI FUN EMI IKORIRA FOLLOW PAGE MI  09012231077Gbomiye òpòlòpò awon eniyan ni wonfi òwò a...
20/06/2026

AWẸNU IJAKULE PROMISE AND FAIL ATI FUN EMI IKORIRA FOLLOW PAGE MI
09012231077
Gbomiye òpòlòpò awon eniyan ni wonfi òwò arawon kobarawon ti wonsi mon bè amon kinikan ni mofèki èma daju wipe gbogbo inkan ti obatijè iwosan eyan kokin fi ojudi ooo asiri yiyi damiloju amon mofi èlèdua ti nidi

Isénaniyi oo 👇👇👇

Aoja ewe akoko ojọ ewe iyalode pupa ati funfun ojọ a o fi omi odo ti o nṣàn tabi omi konga ti a ji pọn larọ kutu gbo ewe mẹtẹta yi, a o yo idọti rẹ danu. A o wa gbe omi yi pa mọ fun wakati mẹfa amon siwaju ki èto dawole otidi dandan funyin oo ki èbami share réna tori kini kankan ko tori anfani awon èlomiran nani kiwon lebaje anfani isénani ooo Kosi igbati a kole gbo ewe yi, boya aarọ, ọsàn tabi irọlẹ. A o fi omi yen sanra tabi fiwe òse awenu or tude to gina

ANFANI SIWAFUN ÈYINTI ÈKOLÈSÈ ASIRI YI YI FUN ARAYIN ALERANYIN LOWO LORI RÈ CALL MY NUMBER OR MSG ME ON WHATSAPP 09012231077

FOLLOW MY PAGE LATI LEJE AWON ANFANI ISÉMIRAN

👉Fún ibẹrẹ Abi ọna abayọ lórí èyíkéyìí ogun TODOJU ko ooo
Call-:: 09012231077

ASEJE ASINA ANU OWO NI KIAKIA..Ridaju pe O follow mi koba fije ju botilero loOna abayo kan tun re ooo...tia le fi ri Anu...
15/06/2026

ASEJE ASINA ANU OWO NI KIAKIA..
Ridaju pe O follow mi koba fije ju botilero lo
Ona abayo kan tun re ooo...tia le fi ri Anu gba....nibikibi...ti olohun oba bani Anu re wa

Aseje yiii dara pupo fun Anu riri gba nibikibi

Konaa yan lowo pupo... Gbiyanju re wo

Pelu ogo olohun.... Anu a wae ri tomotomo

ISENA RE:-
Edo malu tio womi
Ao gesi 16
Ewe onitikuti tutu
Ewe aje tutu tabi gbigbe
Ewe ola die
Ataijosi 16
Epo pupa
Ape aseje tuntun


SISE RE:-
Ao lo awon ewe yiii papo....ao fise Edo malu yen lepo niyo

Ao sosi ori osuka kan tabii anything

Ao se adua siii daaada....ao waje

Pelu ogo olohun.....MA RI ANU GBA.. Tio bafe kosise fun oo daadaa koko share si opolopo group, kio si fi comment re se adura fun mi kio to dawo le...

ENITI ISENA BAWU LATI SE SUGBON TIO FE KIA BA OHUN SE KIO CALL MI 09012231077

FUN IBEERE ABI FUN IRANLOWO LORI ISORO ABI OGUN TI OUN DOJUKO PEMI LORI 09012231077 TIO BANI IGBAGBO.

IMULE AWON AGBA TODAJU BIIKU. Follow page mi koto se ise Yi Ao lo get eye ega ako ati abo.ado ijamon meta.odidi atare nl...
10/06/2026

IMULE AWON AGBA TODAJU BIIKU.
Follow page mi koto se ise Yi
Ao lo get eye ega ako ati abo.ado ijamon meta.odidi atare nla kan.ao wa jo eye mejeji pelu ado eyokan pelu atare yen papo. Leyina ao ro sinu ado miran .ao tun jo papo .ao lo tio kuna dada .ao wa ro sinu ado keta .ao so okun si ao mon gbe ko .abi ka gbe pamon ko gbodo kan ile mo rara oh.

OFORE .......
eye wonu eye.ado wonu ado.emi lagbaja omo lagbaja moti di eye olukotun lati oni lo.ati oso ati aje ati emere ati gbogbo eyin alagbara aye pata..e gbodo di emi lagbaja omo lagbaja lowo lori gbogbo ikan ti mobase .gbogbo ise ti moba si lo.eje koma dahun lara mi.gbogbo ikan ti moba si da owo✋mi le e je ko ma yori si dada.leyina ao da aniyan si dada.ao wa bu die ninu ogun yen ao fi ro ekuru funfun je.ekan soso larin ose.once in a week. .bi abawa ri ekuru funfun kafi fo eko tutu mu.
ENIKENI TOBA SHARE ISE MI LOSI ANOTHER GROUP,KONI SISE FUN OH.
AMIN ASE NTEDUMARE.
fun ibere 09012231077

Address

Ikorodu

Telephone

+2349012231077

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ewe Nje Ogun Wa posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Ewe Nje Ogun Wa:

Shortcuts

Share

Category