CCTV.News.Yoruba

CCTV.News.Yoruba Continental Cherish Television

Gbajugbaja olorin Fuji Oloye Olasunkanmi Wasiu Ayinde Olori Omoba Akile Ijebu n se ayeye ojo ibi re lonii./CCTVNewsYorub...
05/03/2024

Gbajugbaja olorin Fuji Oloye Olasunkanmi Wasiu Ayinde Olori Omoba Akile Ijebu n se ayeye ojo ibi re lonii./CCTVNewsYoruba

Ewo bi ayeye eto adura ojo mejo fun gbajugbaja osere tiata oloogbe Tolani Oyebamiji Quadri ti opo eeyan mo si Sisi Quadr...
05/03/2024

Ewo bi ayeye eto adura ojo mejo fun gbajugbaja osere tiata oloogbe Tolani Oyebamiji Quadri ti opo eeyan mo si Sisi Quadri yoo se lo ni./CCTVNewsYoruba

Eewo aworan awon osere tiata ti won wa sibi eto isinku OmoTayo Quadri ti opo mo si Sisi Quadri  lojo jimo ose yii
03/03/2024

Eewo aworan awon osere tiata ti won wa sibi eto isinku OmoTayo Quadri ti opo mo si Sisi Quadri lojo jimo ose yii

Gbajugbaja osere tiata John Okafor ti opo eeyan mo si Mr Ibu jade laye lanaa./CCTVNews.Yoruba
03/03/2024

Gbajugbaja osere tiata John Okafor ti opo eeyan mo si Mr Ibu jade laye lanaa./CCTVNews.Yoruba

03/03/2024

CCTV.News.Yoruba

03/03/2024

CCTV.News.Yoruba

03/03/2024

CCTV.News.Yoruba

Ijoba apapo so fun egbe osise pe bi won se n da ise sile ni gbogbo igba ko boju mu rara./CCTVNewsYoruba
02/03/2024

Ijoba apapo so fun egbe osise pe bi won se n da ise sile ni gbogbo igba ko boju mu rara./CCTVNewsYoruba

Ijoba apapo ti pase fun awon onilese Simenti gbogbo pe ki won da owo simenti pade si iye owo ti won n ta tele./CCTVNewsY...
02/03/2024

Ijoba apapo ti pase fun awon onilese Simenti gbogbo pe ki won da owo simenti pade si iye owo ti won n ta tele./CCTVNewsYoruba

Owo olopaa ipinle ogun te afurasi Babalawo to n fi eya ara awon obinrin se ogun owo ti o si ti sekupa obinrin meje./CCTV...
02/03/2024

Owo olopaa ipinle ogun te afurasi Babalawo to n fi eya ara awon obinrin se ogun owo ti o si ti sekupa obinrin meje./CCTVNewsYoruba

Olamilekan Ogundipe to je  amugbalegbe Oluso Agutan ijo Celestial Grace Comfort sekupa Oluso Agutan ijo re iyen Morris F...
02/03/2024

Olamilekan Ogundipe to je amugbalegbe Oluso Agutan ijo Celestial Grace Comfort sekupa Oluso Agutan ijo re iyen Morris Fadehan niluu ile ife./CCTVNewsYoruba

Aare Bola Tinubu se ifilole oko oju irin tuntun Red Rail nilu Eko lojo ojobo ose yii/CCTVNewsYoruba
02/03/2024

Aare Bola Tinubu se ifilole oko oju irin tuntun Red Rail nilu Eko lojo ojobo ose yii
/CCTVNewsYoruba

Address

Ebute Ikorodu

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when CCTV.News.Yoruba posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to CCTV.News.Yoruba:

Share