AlaroyeTv

AlaroyeTv AlaroyeOnlineTv is an indigenous broadcasting organization for promotion, retention and preservation of Yoruba language, culture and history.
(2)

15/10/2025

APC FA OYEBANJI KALẸ LATI DUPO GOMINA LORUKỌ ẸGBẸ WỌN

15/10/2025

ETO IDIBO LE MA WAYE LỌDUN 2027

15/10/2025

OṢIṢẸ RELUWEE DERO ẸWỌN, OHUN TO ṢE BURU JAI

15/10/2025

PETER OBI TI SỌRỌ LORI IPADE OUN ATI GOODLUCK JONATHAN

15/10/2025

EYI LOHUN TILEEWE GIGA FASITI YII ṢE FUN OLUWOO ILẸ IWO

14/10/2025

FUN IGBA AKỌKỌ, SUNKANMI ỌMỌBỌLANLE SỌRỌ NIPA ỌMỌ PEJU OGUNMỌLA TO KU, EYI LOHUN TO SỌ
*Ẹ WAA GBỌ TUNTUN O, TỌPẸ ALABI TU AṢIRI NLA NIPA ỌKUNRIN TO BI AKỌBI Ẹ FUN
*PORTABLE TUN TU AṢIRI NLA NIPA AṢABI SIMPLE ATI AAFAA YII
*ṢẸ Ẹ TI GBỌ OHUN TI OṢERE YII SỌ NIPA WASIU AYINDE

14/10/2025

EYI NI BI FULANI DARANDARAN ṢE KỌJU IJA SAWỌN AKẸKỌỌ ATI OLUKỌ ILEEWE GIRAMA NIPINLẸ ỌYỌ

O MA ṢE O, GRACE AWOJỌBI, OṢERE TIATA TI WỌN N PE NI IYA ILE-ỌỌKAN,  TI KU O
14/10/2025

O MA ṢE O, GRACE AWOJỌBI, OṢERE TIATA TI WỌN N PE NI IYA ILE-ỌỌKAN, TI KU O

IYAWO DUN LỌṢINGIN, ỌKỌ TUN MI GBE. ADENIYI JOHNSON ATI ṢEYI EDUN, IYA IBEJI, TUN ARA WỌN GBE NIYAWO. AṢỌ IGBEYAWO TUNTU...
14/10/2025

IYAWO DUN LỌṢINGIN, ỌKỌ TUN MI GBE. ADENIYI JOHNSON ATI ṢEYI EDUN, IYA IBEJI, TUN ARA WỌN GBE NIYAWO. AṢỌ IGBEYAWO TUNTUN NI WỌN KO SI, NI ṢEYI NAA N DA GỌJỌGỌJỌ BII IYAWO AṢẸṢẸGBẸ

14/10/2025

AWỌN ARAALU KO NIGBAGBỌ NINU AMỌTẸKUN ỌṢUN MỌ, AFI KI ADELEKE YỌ ỌMỌYẸLE-SH*TTU

14/10/2025

YOO RỌRUN FUN ẸGBẸ APC LATI GBAJOBA LỌWỌ GOMINA ADELEKE TI WỌN BA ṢE KINNI YII-APC

14/10/2025

KADARA LO GBE MI DEDII IṢẸ TIATA* BAYII NI EMI, JACOB, PAPALOLO ṢE PADE-ADERUPỌKỌ

Address

15 Love All Street
Ikosi

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when AlaroyeTv posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to AlaroyeTv:

Share