
10/10/2025
★ ★
Bíi ẹdá koba nii àkíyèsí nipa ile 🏠 tii òùn gbe awọn orisirisi ijakule nii omaba pade besini opolopo eda nii ìgbésí Ayewon ti di radarada latara ile tii wọn ùn gbe
Púpọ nínú àwọn ìyàwó nii oma ùn fa wàhálà sinu Aye ọkọ latara ile gbigba nitoripe taste won high gan ṣugbọn latara ife odidandan kii ọkọ gbasiwon lẹnu
Ile ti aba ungbe fún ọdún kan bíi kobasi ayipada réré fún wà tàbí aori nkọn pàtó tọka sí láti ìgbà ti àti dé ibè ọmọ ìyàmi tètè tún ero àrà rẹ pa.
Ṣugbọn Aini akiyesi àti akakun lórí ọrọ ayé ti sí ọpọ ọmọ ologo di olofo Nah God Nah God ni iwọ npariwo t**i ti ọrọ ayé rẹ fí dàrú débi tí kòní àtúnṣe mọ.
Ọmọ ìyàmi mio sọ wípé kosi sí ọlọrun sugbon ọlọrun kìí se ìka bi ebaun lo igbesi Aye ti òkú diẹ kààto eleyii kìí se ọlọrun iwọ niki imojuto ọrọ ayé rẹ.
Ọnà miran tún wà tí ijakule ma ungba wọ inú Aye ẹdá latara ile gbigbe ninu àlá
gẹgẹ bíi àpẹẹrẹ;
Bíi obalala pé owá ninu ile ti otigberi nipo pé òun gbé ibe
Ìtumọ:- Ifaseyin ni
Bíi obalala pé igi wò lulẹ sori ile tuntun ti osese gba
Ìtumọ:- kuro nibe kosi òun réré kan ninu ilé yìí fún ee.
Bíi obalala pé okunkun su bo ee loju níwájú ilé
Ìtumọ:- àìsàn tó lágbára nbọ fún ẹ́ tètè múra.
Bíi obalala pé landlord tabi landlady wa sin ee níí owó 💰 ile laijẹ jẹ nii owo ile.
Ìtumọ:- gbàdúrà kii gbese máṣe yoju síi ee ninu ile ti òùngbẹ
*ỌNÀ LÁTI GBÀ MỌ ILÉ TI AUN GBÉ TI KO DARA*
Púpọ eda nii ilé tii oun gbe tii sọ dii ẹni ẹyin tàbí ẹni yẹpẹrẹ
Njẹ iwọ mọ pé ilé tii oun gbe kii ùn se ilé tii oti le laluyo tabi ṣe Orire
Bíi oba wa ùn se àkíyèsí bayii tètè kúrò nínú ilé tii oun gbe
*Bíi aba ùn jẹ gbese ju nínú ilé tii oùn gbe tii eyi kosi ṣẹlẹ tẹlẹ ki oto gbà Ile yi.
* Ti Àwọn ọmọ bíbí inú ee ba ùn se àìsàn ju nínú ilé tii osese gba
*Lati igba tii oti ungbe ilé tii osese gba nii ala buruku yi tii ma ùn waye
Gbìyànjú kii okuro níbẹ kii omaba ta nkan ini ee jeun
*Rántí iyeti iwọ ati ọkọ ee kò wọ inu ile tii esese gba gbese nii epade jẹ gbeyin kuro níbẹ
Gbogbo ile tii àbá ùn gbe tii ati ùn ta ikan ini wa property
Kii se ilé gidi
Lati mo iru ile tii oyeki agba Gbìyànjú kii oto awan oni mimo tojẹ eni ododo lo fun itoni sona
Bi ose bami share post yi irin ajo aye e koni daru amin.
Call/07015993868