Iree Alalubosa Reporters TV

Iree Alalubosa Reporters TV Reporting Facts From Grassroots� �

02/10/2025
ÌRÒYÌN: Ẹgbẹ́ Miyetti Allah takú pé wọn kò gbọdọ̀ ti àwọn ọjà Kara pa ní KwaraẸgbẹ adaranjẹ ti a mọ si Miyetti Allah Cat...
02/10/2025

ÌRÒYÌN: Ẹgbẹ́ Miyetti Allah takú pé wọn kò gbọdọ̀ ti àwọn ọjà Kara pa ní Kwara

Ẹgbẹ adaranjẹ ti a mọ si Miyetti Allah Cattle Breeders Association of Nigeria (MACBAN) ẹka ti Ipinlẹ Kwara, ti ke si ijọba ipinlẹ náà ati awọn agbofinro lati kilọ fun awọn ti wọn n pe awọn ni agbébọn, pe ki wọn tọwọ ọmọ wọn bọsọ.

Alaga ẹgbẹ naa, Alhaji Shehu Garba sọ eyi di mimọ ninu atẹjade to fi lede ni ọgbọnjọ osu yii nilu Ilorin.

Garba sọ pe bi wọn ṣe n ro isẹ laabi ni ipinlẹ náà mọ ẹya Fulani, ti wọn si n pe wọn ni agbébọn, jẹ ohun to lewu fun ẹya naa lapapọ.

Alaga naa sọ pe, ẹgbẹ Miyetti Allah kọ lo n sokunfa eto abo to mẹhẹ ni awọn apa ibikan ni ipinlẹ naa.

Alhaji Garba sọ pe awọn Fulani ni wọn n jẹya isẹ ọwọ awọn agbebọn ju nitori pe, àwọn ni wọn n gba ounjẹ oojọ lọwọ wọn.

O ni awọn ọmọ ẹgbẹ Miyetti kan n ran ikọ̀ ológun ti wọn n pe ni "operation Lafiya Dole", ti ijọba apaapọ gbe kalẹ lọwọ ni, ati awọn ikọ fijilante lati gbogun ti iwa ibi ni ipinlẹ Kwara.

Alaga Miyetti Allah naa wa rọ ijọba lati dẹkun isẹ ọwọ àwọn eeyan kan, to ni wọn ko ara wọn jọ lati da rogbodiyan silẹ laarin awọn olugbe Ipinlẹ Kwara, fun ere tara wọn nikan.

O sọ pe ki ijọba kọ eti ikun si ipe wọn pe ki wọn ti awọn ọja ẹran kara pa, wi pe, ipe naa jẹ ipe eke ati aburu.

Garba wa fọwọ sọya pe, ẹgbẹ naa yoo tẹsiwaju lati ma satilẹyin fun ijọba Kwara ninu igbiyanju rẹ lati kọjú ija si awọn agbebọn ati awọn iwa ibi mii.

🟡 Olupo ti Ajase-Ipo fèsì lórí ìpè fún títí ọjà kara nílẹ̀ Ìgbómìnà pa

Bí àwọn èèyàn ilẹ̀ Ìgbómìnà ṣe ń pè fún títí ọjà kara làwọn agbegbe naa pa, BBC News Yoruba kan si Olupo ti ilu Ajase-Ipo, Ọba Ismail Yahaya Alebiosu lori aago lati mọ ero rẹ lórí ọ̀rọ̀ náà.

Nígbà tó ń sọ̀rọ̀, ọba Alebiosu sọ pe oun ko fẹ sọrọ lori awuyewuye naa nitori pe oun ko fẹ ki ọrọ naa tun le ju bayi lọ.

Ọba Alebiosu fi kun-un pe oun le dahun si awọn ibeere mii sugbọn ti oun ba fesi si awuyewuye náà, o le tun hu awọn nnkan míì to ti rodo lee mumi síta.

Kabiyesi ṣe e lalaye pe, lootọ ni wọn ti fi ọrọ naa to ou

Perfect description of werey la fi n wo werey!!Influencer Mandykiss has been appointed as an ambassador for LASKADA, Lag...
02/10/2025

Perfect description of werey la fi n wo werey!!

Influencer Mandykiss has been appointed as an ambassador for LASKADA, Lagos State Kick against Drug & Substance Abuse. It’s a drug/substance abuse awareness, prevention, and control initiative under the Lagos State Ministry of Youth and Social Development.

Its focus is on youths, schools, communities — trying to reduce and prevent drug misuse in Lagos. Congratulations to Mandy 🙌

02/10/2025
Out of the 2 kings in Iree who are we going to pay salaries to from the LGA.Hope you self know the answer already.....
02/10/2025

Out of the 2 kings in Iree who are we going to pay salaries to from the LGA.
Hope you self know the answer already.....

Ọ̀ṢUN LG SAGA: LET’S DISCUSS Since February 22, 2025, Local Government administration in Ọ̀ṣun State has been paralyzed ...
02/10/2025

Ọ̀ṢUN LG SAGA: LET’S DISCUSS

Since February 22, 2025, Local Government administration in Ọ̀ṣun State has been paralyzed due to the ongoing legal tussle fueled by both the All Progressives Congress and the People’s Democratic Party in the State, bordering on the authenticity of the leadership of the Local Councils.

The developments around the ongoing saga in the State have stirred mixed reactions across the State and beyond.

i. Do you think the current situation is in the best interest of the people?

ii. What solutions do you suggest moving forward?

Let’s hear from you.

Iree Alalubosa Reporters TV

Olohun foro Temi ati iwona SE iyanu ,,Oba lailai Na loun sebe , congratulations 👏🎉 Kabiesi and PBAT Wallahu yasimuka min...
02/10/2025

Olohun foro Temi ati iwona SE iyanu ,,Oba lailai Na loun sebe , congratulations 👏🎉 Kabiesi and PBAT Wallahu yasimuka mina nasi Aminn.

‎‎Tragedy of Trust in a Town Ruled by Monarchs‎‎In a town where tradition and power still hold away, the Osun Security N...
02/10/2025


‎Tragedy of Trust in a Town Ruled by Monarchs

‎In a town where tradition and power still hold away, the Osun Security Network, Amontekun were once seen as protectors. They were meant to safeguard the lives and property of the people, especially in a community where leaders hold significant influence.

‎However, their actions have turned tragic. Instead of protecting, they have become instruments of violence. A recent incident in Akinlalu area of Ife North Local Government, Osun State revealed the dark side of Osun Amontekun. When they were supposed to ensure safety, they opened fire on innocent people, calling them hoodlums.

‎The town, steeped in monarchy and chiefdom, was left in shock. The victims, ordinary citizens, were not threats but individuals who had no idea they were in danger. This tragedy emphasis on a deeper issue: the failure of institutions meant to serve the people. In a world where trust is hard to come by, the actions of these groups have shattered the faith of the community. The people of Akinlalu now live in fear, questioning the very systems meant to protect them.

‎It calls for accountability, for a reevaluation of who truly holds power, and for a renewed commitment to justice. The people of Akinlalu, Ife North generally must rise, not in anger, but in unity, to demand a future where security is not a tool for massacre, but a promise of safety.

I'm Afeez Ogungbemi

25/09/2025
This guy here is Timi, a shoemaker based in Abeokuta. He’s very active on Twitter, and people used to patronize him beca...
25/09/2025

This guy here is Timi, a shoemaker based in Abeokuta. He’s very active on Twitter, and people used to patronize him because of his condition. Unknown to us, this same guy is also a yahoo boy. Here’s what he does: he saves ladies’ pictures from Instagram, sends out fake n**es, and collects money. He creates fake Instagram accounts, uploads pictures of beautiful ladies, and then sells n**e photos of other women as if they were theirs.

Well, he was apprehended yesterday and has issued a public apology.

Me wa n sele (things are truly happening)

Address

Iree
Ire

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Iree Alalubosa Reporters TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share