
15/09/2025
ASEJE CONNECTION TODAJU
●Ewe Omisinmisin
●Omi agbon
●Igbin
●Ata josi
Aseje yi dara fun iwo ti o nwa lati darapo mo awujo awon olorire, tabi iwo ti onwa ki awon eniyan nlala o magbe ise gidi fun o, tabi ki won o ma connect re mo awon eniyan nlala lati mari ise gidi gba.
BI AOSESE
Ao bo (boil) igbin na, ao yo kuro ninu Ikarahun re, ao fo ki o mo ao ge si merindinlogun (16), ao lo ewe Omisinmisin pelu ewe ola niwonba, ati ata josi (16), ao fa sinu isasun,Omi agbon ni ao fi se, ao bu epo Pupa si, ao se ki o jina dada, ao se adura si ki a to je.
Fun ibeere tabi o fe kin ba o se iseyi, message me lori WhatsApp
07067630726.