10/09/2025
EBE AWỌN AGBA TO DAJU.
Igbin Apinnu Kan,
Asin Kan,
Enu Opiri,
Epo Obo.
Ao Gun gbogbo re Papo Mo Ose Dudu,
Ao Fi Iyere Osun Tefa Ejiogbe,
Ao Ma Fi We Lekan Losu Lalale.
GBOLOHUN RE:
Asadi 3x
Arinyadi 3x
Oganranmu Ganranmu 3x,
Iru Ekun, Awon Lodifa Fun Orunmila Nijo Ti Nsawo Re Ilu Awon Aje, Yio Fe Emiri Omo Ewi Ado, Yio Fe Itale Gudugba Omo Awujale, Yio Fe Yanmu Yamun Omo Osun Merin, Emiri Omo Ewi Ado A Fun Ni Iyan Oni Oun Ko Je, Itale Gudugba Omo Awujale Afun Ni Oka Oni Oun Ko Je, Yanmu Yanmu Omo Osun Merin Afun Leko Oni Oun Ko Je, Awon Meteeta Ni Eje Eyan Lawon Yio Mu, Orunmila Bo Sigbo O Jawe Ifa, Oni Aje Ile Ki Gboju Ko Je Asin, Aje Ile Ki Gboju Ko Je Epo Obo, Aje Ile Ki Gboju Ko Je Enu Opiri, Babalawo, Alfa, Woli, Olokunrin, Olobinrin Etc, To Ba Nperi Emi L - L Nibi, Bolo Nito Igbin Nyo Bolo.
WhatsApp
07067630726.
𝐃𝐎𝐍'𝐓 𝐅𝐎𝐑𝐆𝐄𝐓
𝐉𝐔𝐒𝐓 𝐅𝐎𝐋𝐋𝐎𝐖 𝐌𝐄 𝐔𝐏 🙋🏻
𝐖𝐈𝐓𝐇 𝐓𝐇𝐈𝐒 𝐌𝐘 𝐀𝐂𝐂𝐎𝐔𝐍𝐓
𝐅𝐎𝐑 𝐌𝐎𝐑𝐄 𝐔𝐏𝐃𝐀𝐓𝐄𝐒 𝐘𝐎𝐔
𝐂𝐀𝐍 𝐁𝐄𝐍𝐄𝐅𝐈𝐓 𝐅𝐑𝐎𝐌 𝐌𝐄