15/08/2026
Ose awenu
=========
Ope nifun olohun oba toseda ewe ati egbo toni komaje iwulo fun awa eda re toda saye lati lelo fun eyikeyi ipenija isoro ti eda bandojuko ninu aiye
Ose awenu yi dara pupo gan gbogbo eda enia ti owo bahun be ni ara boya iwo tie ripe oro aiye re koye o mo rara gbogbo ohun ti awon egbere nse ni irorun agidi ni iwo fi nse sibesibe oni aseyori oye kotimo pe owo beni ara re boya iwo tie wa gbe oja kale oja re kota gbiyanju kose ose awenu yi pelu ogo olorun oro re koniri bakanna mo.
Awon nkan ti aolo wa niyi
-------------------
Epo obo niwonba
Imi ojo
Ose dudu
Bi aotise ise na niyi:- Ao gun gbogbo awon eronja yi papo ninu odo ao wa ko ose na sinu ike funfun,emeji ni ao mo we oseyi lojumo.
Ao we akoko ni aro kutukutu bi ago marun idaji si ago mefa idaji 5am -6am, Ao we ikeji ni ago mewa ale si ago mokanla ale. 10pm-11pm.
Toba salabapade iseyi gbinyanju kofi ranse si elomiran koleje anfani funwon.
Like
Share
Follow titilayo herbal products
WhatsApp number 07043689257
Calling π 08152874685