03/10/2024
E ku ale o, e kaabo si eto Iwe Iroyin pelu Samuel, lori gbogbo ero ibanisoro to wa l'ori ayelujara. Loni a ni awon iroyin to gbona gbona, iroyin to ni ipa lori aye wa pelu awon idagbasoke tuntun ni agbaye. E so gbogbo eti si, ki e le mo ohun to n sele laye wa.
Good evening, welcome to Iwe Iroyin with Samuel on all social media platforms. Today, we have hot news and updates that affect our world and new developments around the globe. Stay tuned to stay informed.