
07/12/2023
ASALAM ALEIKUM..... Ise ti mo mu wa yi ,, eniba laya ni kowo faa ,,ti ota ba po ju fun eyan ti ota na baya were gan , ti won ni oku ibiti ao gbe gba ,, ti aba joko ti ise walai adanwo nla ni opolopo won yuo ba kuro laye ,, ise ti mo fi kale yi,, opolopo wa ni ota da lamu gidi ,, iye lofa ti mo se fi kale ,, walai kose ise toye ki gbe kale any how ,,tori wahala gidi lemi na se kito gba faa ,, Lati eko losi ilu kan ti won peni irawo legbe saki ko easy faa ,, amo olohun yio san gbogbo wa ni Esan dada ..... Ise na LAGBARA Debi wipe teyan oba mura dada ,,ebi yio pa denden siyan lara ,, ona owo yio ko di na ,,mio sa fun ra mi faa ,,amo eniti mo sa fun wa ninu ebi bayi ,,emi ti mo ba eyan sa na nbe ninu ebi lowo lowo bayi ,, Kolohun jeki ona si ni pa ,,amo ise tude lao fi gbe ajaga ye kuro lara ,, eyi baba mi ki address ma po ju letter lo .... Ise ti oki sise omode faa ,, kode se ise ole eyan .... Leyin aluwala eje ka ti a*o wa si odi ,sokoto odi ,ite ikirun odi ,fila odi , koni si oruka lowo wa ,koni si chain lorun wa fun awa ti ama fi chain si orun ,, ao wa yan nafila merin, fatia ati surat filli 21 21 lao ka ,, leyin salamo ,, ao se awon mukodimot,, leyin re ao wa bere ise Gangan
Surat kahf lao ka ,, surat kahf ti afeka yio yio je 110 ,,ao parire larin ojo meje ,, ojo meje lao fi sa gbogbo 110 ,, ojo kankan lao ma fi ka dafiu 72 t**i ojo yen yio fi pe ,, toba wa pe ojo keje ,,ao wa akuko adie ti pupa po lara re to tobi dada ,, ao pa ao wa fi epo pupa din ,, ao wa ha fun awon oni bara ,,tabi ka gbe fun eyan kafi owo si ,, akiyesi to wa nibe ni wipe ,,a*o ti aba fi bere ise yen na lao fi pari re ,,odi odi lao ma yi a*o na si ti aba fe se adua naa ,, Kolohun bawa fi alubarika si
πππππππ