Alaroye tuntun

Alaroye tuntun IWEEROYIN TO N ṢOJU ỌMỌ YORUBA NIBI GBOGBO

25/01/2025

Ibdahim Alagunmu, Ilọrin Agbọ-sọgba-nu ni iku ọkunrin olorin Sẹnwẹlẹ to n ṣe daadaa nidii orin naa, Mukaila Sẹnwẹlẹ, ẹni ti awọn eeyan deede gbọ iku rẹ lojiji. T**i di ba a ṣe n sọ yii ni

24/12/2024

Monisọla Saka Asiko yii ki i ṣe eyi to daa rara fun arẹwa obinrin to tun jẹ Olori laafin Ọọni Ileefẹ, Ọba Adeyẹye Ogunwusi tẹlẹ, ati oludari ileeṣẹ redio Agidigbo, Alaaji Oriyọmi Hamzat, pẹlu bi Onidaajọ

24/12/2024

Monisọla Saka Ileeṣẹ ifọpo Dangote, iyẹn Dangote Refinery, ti kede pe awọn ti ni ajọsọ ọrọ ati ifọwọsowọpọ pẹlu ileepo MRS, kaakiri orilẹ-ede Naijiria, lati maa ta bẹntiroolu fawọn eeyan ni ojileniẹẹdẹgbẹrun o din Naira marun-un

24/12/2024

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Inu idaamu ati iporuuru ọkan ni awọn eeyan Agboolé Igbẹdẹ, niluu Odó-Ọwá, nijọba Ibilẹ Oke-Ẹrọ, nipinlẹ Kwara, wa bayìí. Eyi ko sẹyin bi awọn agbebon kan ṣe ji marun-un nínú mọlẹbi wọn gbe

24/12/2024

Adewale Adeoye ‘Ba a ba ju abẹbẹ soke nigba igba, ibi pẹlẹbẹ kan naa lo maa fi lelẹ, dandan ni ki atunṣe ati atunto de ba ọrọ owo-ori tuntun ti mo gbe siwaju awọn aṣofin agba

24/12/2024

Adewale adeoye ‘Ko sibi ti iṣe ko si, ko sorileede kankan lagbaaye lasiko yii, t**i kan orileede Gẹẹsi ati Amerika, ti ko si talaka nibẹ, kaluku wọn n dọgbọn si i ni. Ki i ṣe nitori

20/12/2024

Surdiq Taofeek, Ado-Ekiti   Fọfọọfọ ni ile-ẹjọ Majisireeti kan niluu Ado-Ekiti, nipinlẹ Ekiti, nibi ti igbẹjọ ti waye lori ẹsun ibanilorukọ jẹ ti wọn fi kan lọọya to tun jẹ ajafẹtọọ ọmọniyan nni, Dele Farotimi, lori awọn

19/12/2024

Ọrẹoluwa Adedeji Ba a ti n sọ yii, ileewosan kan ti wọn ko darukọ ni Oludasilẹ ileeṣẹ redio Agidigbo to wa niluu Ibadan, Alagba Hamzat Oriyọmi, wa bayii. Nibi t’ọrọ naa le de, ALAROYE gbọ pe

19/12/2024

Adewale adeoye Meje lara awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun Aye kan ti wọn n da omi alaafia ilu Ijẹbu-Ode, nipinlẹ Ogun ru, lọwọ ikọ akanṣe ọlọpaa kan ti wọn n pe ni ‘Special Weapon And Tactical Team

19/12/2024

Jọkẹ Amọri Asiko yii ki i ṣe eyi to daa rara fun arẹwa Olori Ọọni Ileefẹ tẹlẹ nni, Queen Ṣilẹkunọla Ogunwusi. Eyi ko ṣẹyin bi oore ti obinrin to jẹ ajihinrere yii fẹẹ ṣe fawọn ọmọ

18/12/2024

Adewale adeoye Awọn aṣoju ajọ eleto idibo orileede Benin Commission Electoral Nationale Autonomie’ (CENA) ti de sorileede Naijiria lati waa kọ ẹkọ lọwọ ajọ eleto idibo ilẹ wa, Mationla Electoral Commission (INEC), lori bi wọn yoo

Address

Ketu

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Alaroye tuntun posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Alaroye tuntun:

Share