22/11/2024
HYMN 431
1. Oluwa, awa omo re de,
Lati gbohun ebe wa soke
Gegebi o ti gbo adura Elijah,
Jowo gbo adura wa.
2. O gbadura kojo mase ro,
Fun odun meta, on osu mefa
Gegebi o ti gbo adura Elijah,
Jowo gbo adura wa.
3. O si tun gbadura lekeji,
Ojo ro, ile si meso wa,
Gegebi o ti gbo adura Elijah,
Jowo gbo adura wa.
4. Adura lo n silekun anu,
Adura lo si Anna ninu,
Gegebi o ti gbo adura Elijah,
Jowo gbo adura wa. Amin
Celestial de quotient