
17/08/2025
Mogba Olorun Oba Olodumare gbo
Eleda orun oun aiye
Mogba Jesu Kristi gbo
Omo re nikan soso Oluwa wa
Eniti afi Emi Mimo loyun
Eniti abi 'nu Maria Wundia
Eniti o jiya l'owo Pontu Pilatu
Eniti akon mo agbelebu
Eniti o ku ti a si sin
Osokale re 'po oku
Ni ojo keta, ojinde kuro 'nu oku Or 'oke orun
Osi joko l'owo otun Baba Eledumare
Mogba Emi Mimo gbo
Ijo Apostolic Mimo
Idapo awon eniyan Mimo
Idariji ese Ajinde ara n'isa oku
Nibe, la o ti se 'dajo aye oun oku
Ati iye ti ko ni pekun (AMIN)