21/10/2025
CCC HYMN 331
CATEGORY: I-YÌN Ọ-LA
ASSIGNED KEYS SIGNATURE: F major
d d d m s: d m: r d
mm: dr: ds:sfm
dd ms dm rd
m m m: d r d t d
s l: d r d l s: f m
mm: dr: ds: sm
s s l: d r d l s:fm
m m m d r d t d
Ẹ-yin O-lù-wà e yin mí-mọ
Fun 'jo at'o-run wa mí-mọ
A-yọ taye kò lé fún ni
O-lù-wà lo fi i-le lẹ
Lá-tí fun ru-gbin lo s'ọrun
S'ọrun sọ-dọ Bà-bá mí-mọ
O-lù-wà yo Yàn oji ṣe rẹ
Sínú ìjọ mí-mọ yi.
A-min
Celestial Choristers Group TV Toluwalope Makinwa Celestial Choristers Omowumi Larry Omolara Aderemi Adeboboye