Office Of The Grand Mufti of Yoruba Land Ogun State

Office Of The Grand Mufti of Yoruba Land Ogun State voice for humanity

20/10/2025
18/10/2025

ANU OLOHUN
GRACE
🎬 SHKIEH SOBUKOLA QOYUM CHIEF IMAM OFADA CENTRAL MOSQUE MOWE

Àjọ tó ń rí sí ètò Hajj ní Nàìjíríà ṣàlàyé pé ìjọba Saudi ti mú àdínkù bá iye èèyàn tí wọ́n máa fi ààyè gbà láti Nàìjírí...
18/10/2025

Àjọ tó ń rí sí ètò Hajj ní Nàìjíríà ṣàlàyé pé ìjọba Saudi ti mú àdínkù bá iye èèyàn tí wọ́n máa fi ààyè gbà láti Nàìjíríà níbi ètò Hajj ọdún 2026.

17/10/2025

Join our Livestream KHUTUBAR JUMAT AT OFADA CENTRAL MOSQUE MOWE
🎤IMAM QOYUM SOBUKOLA CHIEF IMAM OFADA

Ọba ni Oluwo of Iwoland Telu 1. Ọba tó ṣe wò kọ́ ṣe ni. Wọ́n yàtọ̀ sí tó ń gbé iṣẹ́ rán àwọn bloggers. Alhaji king 👑 Dr ...
17/10/2025

Ọba ni Oluwo of Iwoland Telu 1. Ọba tó ṣe wò kọ́ ṣe ni. Wọ́n yàtọ̀ sí tó ń gbé iṣẹ́ rán àwọn bloggers. Alhaji king 👑 Dr Abdu Rosheed Adewale Akanbi Telu 1. Aṣọ iyì ara yín kò ní fà ya o pẹ̀lú àṣẹ Ọlọ́hun o. Àmín ooo 👋. Ipá ọ̀tá kò ní ká yín láéláé o. Àmín ooo 👋.
ÌLÚ ÌWÓ kò ní bà jẹ́ o pẹ̀lú àṣẹ Ọlọ́hun o. Àmín ooo 👋

AKU JIMOH ONI

Address

Omulishogbe
Mowe

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Office Of The Grand Mufti of Yoruba Land Ogun State posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share