11/12/2023
NJẸ O MỌ ẸNI TÍ NJẸ KÌNÌÚN ẸYÀ JUDA..??
Oya ẹ jẹ a kì, ki a dúpẹ fún un l'owurọ ọjọ ajé yìí.
Oya sọ wípé;
Modupẹ Oluwa pe mo ni ọ lati ma sa ba ..
modupẹ Oluwa pe mo ni ọ lati ma f'ọrọ lọ ..
ọpẹ l'ọpẹ rẹ ayé ì bá ti k'ẹru mi s'igbo, ọpẹ l'ọpẹ rẹ, ayé ì bá ti k'ẹru mi danu, mo yin ọ o Jesu, pẹ mo ni ọ lati ma sa ba,
mo yin ọ o Jesu pẹ mo ni ọ lati ma f'ọọrọ lọ...........................
A kú ojúmó ire o gbogbo ẹyin ololufẹ wa, Ohun gbogbo aa túba, aa túṣe fún yín loni, l'ose yi, l'oṣù yi, ati l'ọdun Titun to mbọ.
Our God is Glorious, Marvelous,..Wonderful.
Ohun ni KÌNÌÚN ẸYÀ JUDA...
Jọwọ, bami fi ọrọ iyin tire náà kún eyi lédè tó wù ọ.
Bàbá wa gbọ gbogbo rẹ..
Ọlọrun fẹràn orin iyin idupe yi gan ni.
Njẹ o le pẹlu mi kọ orin yìí sì Ọlọrun ni owurọ yi.
Halleluyah..!!!.
Tẹ Halleluyah sí ori fọran yii ki ọ fi se àfihàn rẹ pe lóòtọ lo fẹràn Ọlọrun, ati wipe ohun ọpẹ rẹ pọ púpọ síi.
Aatu., Aarọ ooo... Amin.