Lawujo Wa

Lawujo Wa Lawujo wa which simply means in our community, is a talk show combining news, social commentary, human interest interviews, religion talks and lots more...

live streaming and documentary

07/07/2025

Ǹjẹ́ Ẹ sì rántí Èmi Lo kan

06/07/2025

Ikunlẹ Abiyamọ 😭😭😭😭

Ìdàrúdàpọ̀ gẹ́gẹ́ bí Alaga APC, Ganduje ti kọ̀wé fipò sílẹ̀  Alaga lorilẹede fun ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress AP...
05/07/2025

Ìdàrúdàpọ̀ gẹ́gẹ́ bí Alaga APC, Ganduje ti kọ̀wé fipò sílẹ̀

Alaga lorilẹede fun ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress APC, Dokita Abdullahi Ganduje ti fi ipo silẹ, Satidee Vanguard ti gbọ.

Bi o tile je wi pe awon nnkan to wa ninu ifiposile re ko han t**i di asiko iroyin, osise agba egbe kan so fun Vanguard lasan pe, “ beeni, looto ni. O ti fipo sile”.

Ile Ẹjọ́ Giga Ipinle Oyo Ibadan da ejò tí Aare Ona Kakanfo Gani Adam pé Oloye Sunday Igboho nù pelu Onidajo O.T. Ademola...
05/07/2025

Ile Ẹjọ́ Giga Ipinle Oyo Ibadan da ejò tí Aare Ona Kakanfo Gani Adam pé Oloye Sunday Igboho nù pelu Onidajo O.T. Ademola Salami ni ki Kakanfo san N500k fún Igboho

04/07/2025
04/07/2025
03/07/2025

Baba Ìjẹ̀sà ó ti jáde oooo, èyí gbé sùnmọ̀mí buburu, ṣùgbọ́n lágbára Ọlọ́run yóò jáde layọ

Video Credit to Kunle Ologundudu Oba Akorin

01/07/2025

Ẹni tí ó rí Aya fẹ́ rí ojú rere




























23/06/2025

Hmmmmm

23/06/2025
21/06/2025

Did God against Polygamy?

Address

Fagbewesa
Osogbo
230231

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Lawujo Wa posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Lawujo Wa:

Share