NTA OYO

NTA OYO News and Current Affairs, Information, Education, Entertainment, Sports,

25/08/2026

AYEYE ODUN MAOLUD NILU OYO

Ayeye odun Maolud nilu Oyo Je Akoko ti Awon Musulumi fi n ronu jinle lori igbeaye ati agbekale eko anabi Muhammad, ti won si tun fon rere igbeaye alafia, isokan larin mutumuwa.

25/08/2026

CELEBRATION OF MAOLUD IN OYO TOWN

In the ancient city of Oyo, the celebration of Maolud is more than a religious gathering. It is a moment for Muslim faithfuls to reflect on the life and teachings of Prophet Muhammad, while strengthening bonds of brotherhood, peace and unity within the community.

Funke Amole takes a look at the significance of the day.

22/08/2026

ISE ISIN OJO ANU NILU OYO .

Oluso-agutan ti ijo ife christi , woli Peter Adeniyi, ti kesi awon omo orileede yii lati ma wa agbara Olorun, o tenumo pe, idasi Olorun lori ohun ti a pe ni agbara se pataki lati bori gbogbo ipenija ninu aiye.

Oro yi waye nibi eto pataki fun ise Isin Ojo Anu , eyi to waye ni ibi igbafe Tees nilu Oyo.

Iroyin oun re lekunrere lati enu Funke Amole

22/08/2026

OYO MERCY RAIN MANTLE SERVICE.

The Clergy of Love of Christ Chapel International Ministry, Prophet Peter Adeniyi, has called on Nigerians to seek the power of God in all affairs, stressing that divine intervention remains essential in overcoming any form difficulties.

The clergy made the call at a Mercy Rain Mantle Service held at Tee Event Centre in Oyo Town.

Here is the report.

13/08/2026

LINGUSTTICS STUDENTS TOUR NTA OYO.

As part of efforts to bridge the gap between theoretical learning and practical experience, Students of Linguistics from Emmanuel Alayande University of Education, Oyo were on a tour of operational facilities of the Nigerian Television Authority, NTA Oyo inorder to gain firsthand knowledge of broadcasting operations.

The report.

13/08/2026

AWON AKEKO EDE EMMANUEL ALAYANDE UNIVERSITY OF EDUCATION SE ABEWO SI ILESE NTA OYO.

Latari akitiyan lati ni imo kun imo, awon Akeko nipa Ede karoojire ati Ede Adulawo ni fasiti Emmanuel Alayande nilu Oyo, se abewo si Ile ise mohunmaworan ijoba apapo tilu Oyo lati ni imo tuntun lori bi iroyin se njade lori afefe.

Funke Amole wa nibe eje ka gbo siwaju.

11/08/2026

WORLD SANGO FESTIVAL OPENS IN OYO.

The ancient palace of the Alaafin of Oyo came alive with traditional rites and cultural displays of Ogun signifying the beginning of the Annual World Sango festival.takes

The report.

11/08/2026

ETO AYEYE OLODOODUN SANGO BERE L'OYO.

Aafin isenbaye tilu Oyo kun fun igbelaruge asa ati afihan bibo ogun , eyi ti o fi o ntoka si ibere ayeye sango odun yi

Iroyin oun re lekunrere lati enu Funke Amole

08/08/2026

OMOWE NIHINLOLA OLAYINKA DOSUNMU SE AYEYE OJO IBI ODUN MARUNLE-LADOTA.

Idunu subu lu ayo nigbati oga ilewe wonlewonle Omowe Nihinlola olayinka Dosunmu Se apeje ranpe eyi to fi se ayeye Ojo ibi odun marunle -ladota nibiti awon omo , ebi, ore, ati awon olufe kopa ninu ayeye Oun.

Funke Amole Se akojopo iroyin oun.

08/08/2026

Dr. NIHINLOLA OLAYINKA DOSUNMU CELEBRATES 55TH BIRTHDAY

It was a celebration of life, gratitude, and grace as family members, friends, and well-wishers gathered to honour a distinguished scholar and outstanding Academician, Dr. Nihinlola olayinka Dosunmu on the occasion of her 55th birthday.

The Report.

Address

APITIPITI GRA OYO
Oyo
211215

Telephone

+2348064835540

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when NTA OYO posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to NTA OYO:

Shortcuts

Share