Owe Ati Asa Ile Yoruba

Owe Ati Asa Ile Yoruba To teach,learn and educate more about yoruba culture, traditions and proverbs.

25/05/2025

owe yoruba ajeji miiran


゚viralシfypシ゚viralシalシ

24/05/2025

Kabiyesi oba, Olori Temitope Adeyeye-Ogunwusi, iyawo Ooni ti Ife, sun omije ni iranti ase iya re nibi idasile ile iwe alakobere ofe ni ilu Ikorodu.

゚viralシfypシ゚viralシalシ

22/05/2025

゚viralシfypシ゚viralシalシ

20/05/2025

Oṣiṣẹ ọlọpa Naijiria ko ni ikẹkọ daadaa rara, kikuru ibon kii ṣe igbesẹ ti o tẹle lati gbe nigbati ọkọ ayọkẹlẹ ba kọja ni ọna kan. Olopa Naijiria ko se deede.😢😢😢😢😭😭😭

゚viralシfypシ゚viralシalシ

20/05/2025

Òwe , Àsamòn at àkàn èdè

゚viralシfypシ゚viralシalシ

17/05/2025

kí a má ṣe jìyà àìtọ́ sí wa

゚viralシfypシ゚viralシalシ

16/05/2025

.
..

゚viralシfypシ゚viralシalシ
#

16/05/2025

Sobia ati oluganbe

゚viralシfypシ゚viralシalシ

Ẹ wá forúkọ àti ìdánimọ̀ yín sílẹ̀ - Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá sọ fún àwọn olùfẹ̀hónúhàn*Ọga agba pata fun ileeṣẹ ọlọpaa orileede ...
27/07/2024

Ẹ wá forúkọ àti ìdánimọ̀ yín sílẹ̀ - Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá sọ fún àwọn olùfẹ̀hónúhàn*

Ọga agba pata fun ileeṣẹ ọlọpaa orileede Naijiria, Kayode Egbetokun ti pe gbogbo awọn ti wọn n gbero lati ṣe iwọde ifẹhonuhan ti yoo bẹrẹ lọjọ kinni, oṣu Kẹjọ tete wa fi orukọ ati idanimọ wọn silẹ.

Egbetokun lo sọrọ yii lọjọ Ẹti, ọsẹ yii lasiko to n ba awọn akọroyin sọrọ niluu Abuja, nibi to ti jẹ ko di mimọ pe awọn naa ti n gbaradi fun eto aabo to pe ye lori iwọde ọhun.

Ọga ọlọpaa sọ pe ki gbogbo ẹgbẹ, ajọ ati awọn to n gbero lati kopa ninu iwọde fi orukọ silẹ ni olu-ileeṣẹ ọlọpaa to ba sunmọ wọn, lati le mọ iru eeyan ti wọn jẹ.

Siwaju sii lo sọ pe ẹtọ araalu ni lati fi ẹhonu wọn han nipa kikorajọ soju kan, ati pe wọn gbọdọ ṣe ẹ pẹlu alaafia lai si iwa jagidijagan.

“Awa naa fidi ẹtọ araalu labẹ ofin mulẹ nipa iwọde ifẹhonuhan alalaafia.

“Ṣugbọn ṣa, lati le daabo bo dukia ati ẹmi araalu, a rọ gbogbo awọn ẹgbẹ ti wọn n gbero lati kopa ninu iwọde ifẹhonuhan naa lati lọ fi orukọ ati idanimọ wọn silẹ lọdọ ọga ọlọpaa to wa ni ipinlẹ wọn, nibi ti iwọde yoo ti waye.

“Lati le ṣagbatẹru iwọde ifẹhonuhan alalaafia ti ko nii mu ipalara dani, ki wọn lọ fi awọn nnkan wọnyi silẹ: ipinlẹ ti wọn ti fẹẹ ṣe e ati ibi ti wọn yoo korajọpọ si; igba ati asiko ti wọn yoo fi ṣe e; orukọ ati idanimọ awọn adari olufẹhonuhan ati awọn alagbatẹru.”

Bakan naa lo tun fi kun ọrọ rẹ pe awọn fẹẹ tete mọ awọn to n gbero lati da iwọde ọhun ru, lojuna lati le tete ko wọn pamọ.

Ọkan lara awọn aṣofin agba nilẹ igbimọ aṣofin agba lorilẹede Naijiria, Sẹnetọ Ifeanyi Ubah ti jade laye lẹni ọdun mẹtale...
27/07/2024

Ọkan lara awọn aṣofin agba nilẹ igbimọ aṣofin agba lorilẹede Naijiria, Sẹnetọ Ifeanyi Ubah ti jade laye lẹni ọdun mẹtalelaadọta.

Àwọn ohun tó yẹ́ kí o mọ̀ nípa Ifeanyi Ubah
Ifeanyi Uba jẹ gbajugbaja lẹka eto okoowo pẹlu ileeṣẹ Capital Oil Corporation.

Inu oṣu Kẹsan, ọdun 1971 ni wọn bi i, to si jẹ akọbi ninu awọn ọmọ meje ti baba rẹ, Alphonsus Ubah bi.

Ubah ti fẹ iyawo, o si ni ọmọ marun-un.

Agbegbe Otolo, ilu kekere kan nipinlẹ Anambra lo ti jade.

O lọ sile-ẹkọ Premier Academy Lugbe to wa ni Abuja, ṣugbọn ko pari rẹ nitori ailowo lọwọ awọn obi rẹ lati ran an nile ẹkọ.

O lọ si oriṣiriṣi idanilẹkọ nipa okoowo, ileeṣẹ ati ijọba.

Ọdun 2001 ni Ifeanyi da ileeṣẹ rẹ, 'Capital Oil' silẹ.

Bakan lo tun jẹ pe oun lo ni ẹgbẹ agbabọọlu Ifeanyi Ubah FC, ti wọn jẹ Gabros International Football Club, ti wọn si n kopa ninu idije ati ifẹsẹwọnsẹ ilẹ Naijiria, iyẹn Nigeria Premier League.

Ẹgbẹ oṣelu Labour Party ni Ifeanyi Ubah ba jade lati du ipo gomina ipinlẹ Anambra lọdun 2014, ṣugbọn to padanu.

Lọdun 2019, Ubah jade du ipo aṣọfin agba lati ṣoju ẹkun Anambra South Senatorial District labẹ asia ẹgbẹ oṣelu Young Democratic Party (YPP).

Ajọ eleto idibo, INEC kede rẹ lọdun 2019 gẹgẹ bi ẹni to jawe olubori pẹlu ibo ọgbọn.

AKIYESI: Minisita fun Isuna, Edun Fi Aba 'N105,000 Titun Oya Kere' Fun Tinubu.
06/06/2024

AKIYESI: Minisita fun Isuna, Edun Fi Aba 'N105,000 Titun Oya Kere' Fun Tinubu.

21/04/2024

Àwọn ọmọ ẹ̀yìn Olusola Oke ń fẹ̀hónú hàn lórí ètò ìdìbò abẹ́lé ẹgbẹ́ òṣèlú APC l’Ondo

Address

Modakeke
Oyo

Opening Hours

Monday 09:00 - 17:00
Tuesday 09:00 - 17:00
Wednesday 09:00 - 17:00
Thursday 09:00 - 17:00
Friday 09:00 - 17:00

Telephone

7036087629

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Owe Ati Asa Ile Yoruba posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share