Larubawa TV

Larubawa TV Live stream video, advert, programs, entertainment, interview, news, etc

26/08/2025

Scholarships for ÒKÈ OGÚN Indigenous From Dr Oriyomi Hamzat...

In-Person Voter Registration Kicks Off Nationwide Today!In-person  Continuous Voter Registration (CVR) starts today, Tim...
25/08/2025

In-Person Voter Registration Kicks Off Nationwide Today!

In-person Continuous Voter Registration (CVR) starts today,
Time: 9:00 AM – 3:00 PM (Monday to Friday).

Note: If you have already completed your online pre-registration, kindly proceed to the INEC State Head Office or the INEC LGA office in your place of residence to complete your registration.

✅ View registration centres near you here: wp1.inecnigeria.org/wp-content/upl…

🗳 Don’t wait; take action today!


Direct any complaint to
https://CVR.inecnigeria.org/Public/getStarted

📞 Call INEC for enquiries:
09050858629 | 09050858675 | 09050858649rlllaiary

21/08/2025

Ọrẹ Aralu
Alanu mekunu
ỌMỌLÚWÀBÍ PONBELE

May Dr Oriyomi Hamzat succeed beyond our expectations...

*LỌ́ GBA KÁÀDÌ ÌDÌBO RẸ* Káàdì ìdìbò kíì ṣe ike lásán, ohun tó lè tún kádárá ṣe ni.Ba bá ń p'ariwo kò s'íná, kó s'ómi, t...
11/08/2025

*LỌ́ GBA KÁÀDÌ ÌDÌBO RẸ*

Káàdì ìdìbò kíì ṣe ike lásán, ohun tó lè tún kádárá ṣe ni.

Ba bá ń p'ariwo kò s'íná, kó s'ómi, títì ọ̀ dára, káàdì ìdìbò ló lè ṣe é.

Ba bá p'ariwo p'áwọn 'lé' wé wa ó da àt'àwọn 'lé' wòsàn wa, káàdì ìdìbò ló lè ṣe é.

Ba bá p'ariwo p'ébi ọ̀p'àgbà f'ọ́wọ́mẹ́kẹ̀ ń pa wá, òṣì mú wá dódó, káàdì ìdìbò ló lè ṣe é.

T'ọ́mọ́dé t'àgbà, ba bá fẹ́ k'ọ́mọ Òkèògùn ó ṣe Gómìnà l'átọdún 2027, káàdì ìdìbò ló lè ṣe é.

T'orí náà, lát'ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹjọ s'ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n ọdún ta wà nínú rẹ̀ yí (August 18 and 31, 2025), l'ọ́mọdé, l'ágbà, l'ọ́kùnrin, l'óbìnrin, é tú yáyá, ẹ tú yàyà, jáde lá lọ́ gba káàdì ìdìbò.

Ẹní tó l'ẹ́tọ̀ọ́ láti gba káàdì ìdìbò l'ẹni tó bá ti t'ọ́mọ ọ̀dún méjìdínlógún, ì bà ṣ'ọkùnrin tàb'óbìnrin.

Ẹni tó tún tọ́ sí láti gba káàdì ìdìbò l'ẹni tó bá ti sọ káàdì ìdìbò rẹ̀ nù.

Ẹ má gbàgbé, káàdì ló f'ẹ́nìkọ̀ọ̀kan wa l'ẹ́tọ̀ọ́ bí ọmọ orile-ede láti d'ìbò yanni tó wù wá l'ọ́jọ ìdìbò ká má bà ma wá ma ṣ'àróyé tàbí kùn tó bá yá p'éjọba ń f'ìyà jẹ wá.

Béèrè ilé iṣẹ́ INEC tó wà n'ílùú tàbí l'ágbègbè rẹ kó lọ́ gba káàdì ìdìbò lásìkò k'ọ́jọ́ tó lọ.

HON Sulaiman olaitan Larubawa

The Citizen of Oyo State need a leader who is willing to stand up for them, to fight for their rights, and to champion t...
24/07/2025

The Citizen of Oyo State need a leader who is willing to stand up for them, to fight for their rights, and to champion the issues that matter most. Our State deserves a leader who is passionate, dedicated, and ready to tackle the challenges ahead. Please consider taking this important step for our community and for the future of Oyo State.

22/07/2025

Ọ̀YỌ́ Ń PÈ O 2027.

MAY DR ORIYOMI HAMZAT SUCCEED BEYOND OUR EXPECTATIONS.

13/07/2025

May Dr Oriyomi Hamzat succeed beyond our expectations...

Pls Share, comment and like after watching..

GOD BLESS YOU ALL....

12/05/2025

Someone is interested in dating you .
Just ask who pls.
He or She will chat u up. No allow pride finish you🌹

𝐈’𝐦 𝐚 𝐛𝐨𝐧𝐚𝐟𝐢𝐝𝐞 𝐦𝐞𝐦𝐛𝐞𝐫 𝐨𝐟 𝐜𝐞𝐥𝐞𝐬𝐭𝐢𝐚𝐥 𝐜𝐡𝐮𝐫𝐜𝐡, 𝐈 𝐛𝐮𝐢𝐥𝐭 𝐚 𝐩𝐚𝐫𝐢𝐬𝐡 — 𝐊𝟏 𝐃𝐞 𝐔𝐥𝐭𝐢𝐦𝐚𝐭𝐞 Fuji icon, Wasiu Ayinde Marshal, popularly ...
24/04/2025

𝐈’𝐦 𝐚 𝐛𝐨𝐧𝐚𝐟𝐢𝐝𝐞 𝐦𝐞𝐦𝐛𝐞𝐫 𝐨𝐟 𝐜𝐞𝐥𝐞𝐬𝐭𝐢𝐚𝐥 𝐜𝐡𝐮𝐫𝐜𝐡, 𝐈 𝐛𝐮𝐢𝐥𝐭 𝐚 𝐩𝐚𝐫𝐢𝐬𝐡 — 𝐊𝟏 𝐃𝐞 𝐔𝐥𝐭𝐢𝐦𝐚𝐭𝐞

Fuji icon, Wasiu Ayinde Marshal, popularly known as K1 De Ultimate has exuded his love for the Celestial Church of Christ, admitting that he is a bonafide and proud member of the ministry.

ọmọ Yorùbá àtàtà..PA òwe kan tó jẹ́ mọ́ tí ewurẹ
21/04/2025

ọmọ Yorùbá àtàtà..

PA òwe kan tó jẹ́ mọ́ tí ewurẹ

PA òwe kan tó jẹ́ mọ́ Adìẹ.
20/04/2025

PA òwe kan tó jẹ́ mọ́ Adìẹ.

Big shout out to my newest top fans! 💎 Hameenah Abdul Lateef, Wf RuhdeDrop a comment to welcome them to our community,  ...
25/01/2025

Big shout out to my newest top fans! 💎 Hameenah Abdul Lateef, Wf Ruhde

Drop a comment to welcome them to our community, fans

Address

Saki

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Larubawa TV posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category