
07/04/2025
Ọdọọdún ni Sápó ń rúwé
Ọdọọdún lèrùwà ń wà
Ọdún ò ní jọ́ kí pèrègún má máwọ̀ tuntun wọ̀
Ẹ ṣe ọdún òní, ọdún ayọ̀ lẹ ó máa ṣe.
Àṣèyí ṣàmọ́dún, àṣàmọ́dún ṣẹ̀míì láṣẹ Èdùmàrè
Happy birthday to you mummy
Thanks for being a good Mother.
Your talent, creativity and versatility is indeed unexplainable.
Thanks for loving and supporting my acting career. I appreciate deeply, mum.
You’re loved and cherished ma.