10/08/2025
( KADARA ATI SABABI)
kadara je ohun ti Olohun Oba ko mo ènìyàn Latorunwa besini tosí je ohun ti eda yóó fi Lo igbese ayé rẹ ṣugbọn Sababi Loma jeki kadara wa sí imuse....
Kadara A ma change pelu adua ati Ese, ìtumò eleyi ni wipe Elomiran gbè kadara Olowo, olola ati Elemi gigun wa sile ayé sugbon oseese ko ma se ri owo Lo igbese ayé rẹ besini Owo ṣi wa ninu kadara rẹ.
GBOGBO EDA TOBA FE RI KADARA RE LO GBODO SORA FUN NKAN META KAN
O gbodo Je Eniti O ma sora latima se gbogbo nkan, ìtumò eleyi ni wipe O gbodo ma se jeje, kio ma kun fun adua daada besini kio yago fun nkan tole se idiwo kadara re latima se wa si imuse, nitoripe Epe tabi latara iwa buruku ni elomiran ti so Ogo re nu, Kosi eniyan tiwo kole bù, Asiri re siso sita, Aijara mose (lazy) ati bebelo.
O gbodo je eniti O ma ma gbadua daada besini ko ma dunnu sí eniti Olohun gbega, Ma se ma banuje nigbati Ènìyàn ban se nkan rere, gbogbo Ẹda ton ba banuje níbi nkan rere koni sẹ rere Laelae, nkan rere koni yà ile won.
Iwadi sise lori ara rẹ se pataki, iwadi sise Loma jeki O mo nkan todara Latise fun e Lori ìrìn ajo ayé rẹ besini eleyi Loma fi Mo nkan toma se idiwo fún irawo ati ogo rẹ gẹgẹbi Eewọ jíjẹ, sise , ati bebelo besini Iwadi Loma salaye iru saara toma ma se Lati Lee fi tètè débi Ogo rẹ ati iru Obìnrin toma Fe toma se iranlowo fún e,
Nitoripe ti ọkùnrin ba ti sí iyawo fe tabi iyawo na Loba sí oko fe, 75 percent ninu Igbese ayé won ti dàrú niyen besini Oseese ki ọrọ won ma se to mo tiwon ma fi jade laye, Even kiwon fi ara won sile, kole da bi wipe ki wọn fe ènìyàn toba iseda won mu,
Eyin É Lò wò awon Ananbi (Prophet) Olohun tiwon feyawo buruku, kosi eleyi tori ise olohun je dogongo ninu won besini Obinrin tohun na fe oko buruku iya friaona(Khasia), Won pada pa nipakupa ni.
Gbogbo eda toba fẹ di ènìyàn gidi ninu Aye gbodo Sora Fun awon nkan meta Yen besini kio wa tun ri iyawo tabi Oko gidi, kosi wahala mo fún e, sugbon ti inu okò ati iyawo koba dùn sira won, tiwon kofi inú hàn ara won, ti irawo ati Akosejaye won koba papo, hmmm.... Oseese ki iru ọkùnrin bee se wahala kú láyé besini ko ma se ri Ogo rẹ Lò t**i o ma fi jade laye...
Emi koni sìn won wa sile ayé ooo (amin) ninu osu October to je osù Ojo ibi mi yìí, Gbogbo awon toman funmi ni Ẹbun, Olohun yóó bukun won ati awon toma join won Lodun yìí.
Kokoro ile Titun ati motor Titun, Olohun yóó fi Lee o lowo ninu osu yìí Pelu ìgbàgbọ se amin meta...
SE IWADI ORO AIYE ARARE KIOLE BO NINU ISORO AIYE RE