
20/06/2024
Ìtẹ́lọ́rùn ọba ìwà;
Ẹni ní ìtẹ́lọ́rùn láyé
Ohun gbogbo lóní;
Bènìyàn bá là layé
Tó ní ohun gbogbo táyé ní
Bí ò bá ní ìtẹ́lọ́rùn;
Kòtókòtó ní n gbé irú wọn rọ̀rún
Kòtò ní wọ́n yóò gbẹ̀hìn sí.
Ẹni ní ìtẹ́lọ́rùn
Irú wọ́n lọkàn wọn balẹ̀ láyé.
Alayinla Osho
Dokita Ife
AyanfeOlodumare
AdeOriOkin