Ìhìnrere Òtítọ́.

  • Home
  • Ìhìnrere Òtítọ́.

Ìhìnrere Òtítọ́. TẸMPILI (ỌKÀN) NI À ŃKỌ́,
ÒGIRI Ẹ̀SÌN KỌ. A ŃGBÉ PẸ̀LÚ ÀWỌN TÍ AYÉ KỌ̀ SÍLẸ̀. JESU KRISTI NI OLÙGBÀLÀ WỌN.

‎"Eyi ti o gbà talenti kan si wá, o ni, Oluwa, mo mọ̀ ọ pe onroro enia ni iwọ iṣe, iwọ nkore nibiti iwọ kò gbe funrugbin...
25/11/2025

‎"Eyi ti o gbà talenti kan si wá, o ni, Oluwa, mo mọ̀ ọ pe onroro enia ni iwọ iṣe, iwọ nkore nibiti iwọ kò gbe funrugbin si, iwọ si nṣà nibiti iwọ kò fẹ́ka si: Emi si bẹ̀ru, mo si lọ pa talenti rẹ mọ́ ninu ilẹ: wo o, nkan rẹ niyi. Oluwa rẹ̀ si dahùn o wi fun u pe, Iwọ ọmọ-ọdọ buburu ati onilọra, iwọ mọ̀ pe emi nkore nibiti emi kò funrugbin si, emi si nṣà nibiti emi kò fẹ́ka si: Nitorina iwọ iba fi owo mi si ọwọ́ awọn ti npowodà, nigbati emi ba de, emi iba si gbà nkan mi pẹlu elé. Nitorina ẹ gbà talenti na li ọwọ́ rẹ̀, ẹ si fifun ẹniti o ni talenti mẹwa." *¹

‎"Nitori igbati nwọn mọ̀ Ọlọrun, nwọn kò yìn i logo bi Ọlọrun, bẹ̃ni nwọn kò si dupẹ; ṣugbọn èro ọkàn wọn di asán, a si mu ọkàn òmúgọ wọn ṣókunkun." *²

‎- *¹ Mat 25:24-28 YBCV, *² Rom 1:21 YBCV

‎🔥🔥🔥🔥🔥🔥🔥

‎Ẹ ṣeun púpọ̀ tí ẹ yà sí ìhín yìí.

‎Jo̧wo̧ mase fi igbala rẹ da ọla.

‎Bi iwọ kò ba i ti ṣe bẹẹ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, tete fi aiye rẹ fun Jesu Kristi Oluwa loni yii. Nítorípé, ọla leè pẹ ju fún ọ.

‎⏪⏪⏪⏪⏩⏩⏩⏩

‎ᴵˡᵉ ᶦˢᵉ ᶦʳᵃⁿˢᵉ ʸᶦᶦ' ᵏᶦ ᶦ ˢᵉ ᶦᵈᵃˢᶦˡᵉ ᶦʲᵒ ᶠᵘⁿ ᵉˢᶦⁿ' ᵇᶦᵏᵒˢᵉ ᶦᵇᶦᵗᶦ ᵃ ᵗᶦ ⁿᶠᶦ ᶦᶠᵉ ᴼˡᵒʳᵘⁿ ᵍᵇᵉ ᵖᵉˡᵘ ᵃᵗᶦ ˢᵉ ᵃᵐᵒʲᵘᵗᵒ ᵃʷᵒⁿ ᵉⁿᶦʸᵃⁿ ᵗᶦ ᵏᵒ ʳᵒʳᵘⁿ ˡᵃᵗᶦ ᵐᵃᵃ ᵇᵃ ᵍᵇᵉ˙ ᴬʷᵒⁿ ᵉⁿᶦᵗᶦ ᵃʸᵉ' ᴱˢᵘ ᵗᵃᵇᶦ ᵉˢᵉ ⁿᵖᵒⁿ ˡᵒʲᵘ˙
‎ᴶᵉˢᵘ ᴷʳᶦˢᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵃ ⁿᶦ ᴼˡᵘᵍᵇᵃˡᵃ ᵃᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵒˢᵃⁿ ʷᵒⁿ' ⁿᶦᵖᵃˢᵉ ᵃʷᵒⁿ ᴼʳᵒ ᴿᵉ ᵇᶦ ᶦʳᵘ ᵉʸᶦ˙

‎𝙵ú𝚗 à𝚕à𝚢é 𝚝à𝚋í ì𝚋éè𝚛è, ę 𝚙è 𝚝à𝚋í 𝚝ę 𝚊𝚝ę𝚓𝚒șę 𝚢í𝚗 𝚜𝚒:

‎📱07038226570.
‎📩 [email protected]

‎̷є̣ ѕὶ ℓєє̀ кὰη ѕὶ ωα ηί:

‎IBUDO~ẸRI KRISTI
‎(ɪʟᴇ ᴍᴀᴀʏᴇ), ABÚLÉ ÒGOBÌ-ỌJÀ,
‎ʟᴇ̣ʜɪɴ ᴏ̣ɢʙᴀ ʀᴇᴅᴇᴇᴍᴇʀ'ᴤ ᴜɴɪᴠᴇʀᴤɪᴛʏ, ẸDẸ, NI IPINLẸ ỌSUN, NIGERIA.

‎Olúwa yóò máa bùkún fun yín.

‎"Nitoripe Oluwa kì yio ṣa awọn enia rẹ̀ tì, bẹ̃ni kì yio kọ̀ awọn enia-ini rẹ̀ silẹ." *¹‎‎"Nitoriti Oluwa kì yio kọ̀ aw...
23/11/2025

‎"Nitoripe Oluwa kì yio ṣa awọn enia rẹ̀ tì, bẹ̃ni kì yio kọ̀ awọn enia-ini rẹ̀ silẹ." *¹

‎"Nitoriti Oluwa kì yio kọ̀ awọn enia rẹ̀ silẹ nitori orukọ rẹ̀ nla: nitoripe o wu Oluwa lati fi nyin ṣe enia rẹ̀." *²

‎"Nitoriti Oluwa kì yio ṣá ni tì lailai: Bi o tilẹ mu ibanujẹ wá, sibẹ on o ni irọnu gẹgẹ bi ọ̀pọlọpọ ãnu rẹ̀. Nitori on kì ifẹ ipọn-ni-loju lati ọkàn rẹ̀ wá, bẹ̃ni kì ibà ọmọ enia ninu jẹ. *³

‎"Awa si mọ̀ pe ohun gbogbo li o nṣiṣẹ pọ̀ si rere fun awọn ti o fẹ Ọlọrun, ani fun awọn ẹniti a pè gẹgẹ bi ipinnu rẹ̀." *⁴

‎Ohun kan yi sa da mi loju, pe ẹniti o ti bẹ̀rẹ iṣẹ rere ninu nyin, yio ṣe aṣepe rẹ̀ t**i fi di ọjọ Jesu Kristi:
‎Ki ẹ má si jẹ ki awọn ọta dẹruba nyin li ohunkohun: eyiti iṣe àmi ti o daju fun iparun wọn, ṣugbọn ti igbala nyin, ati eyini ni lati ọwọ́ Ọlọrun wá. *⁵

‎- *¹ O. Daf 94:14, *² I. Sam 12:22, *³ Ẹk. Jer 3:31-33, *⁴ Rom 8:28, *⁵ Filp 1:6, 28 YBCV

‎🔥🔥🔥🔥🔥🔥🔥

‎Ẹ ṣeun púpọ̀ tí ẹ yà sí ìhín yìí.

‎Jo̧wo̧ mase fi igbala rẹ da ọla.

‎Bi iwọ kò ba i ti ṣe bẹẹ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, tete fi aiye rẹ fun Jesu Kristi Oluwa loni yii. Nítorípé, ọla leè pẹ ju fún ọ.

‎⏪⏪⏪⏪⏩⏩⏩⏩

‎ᴵˡᵉ ᶦˢᵉ ᶦʳᵃⁿˢᵉ ʸᶦᶦ' ᵏᶦ ᶦ ˢᵉ ᶦᵈᵃˢᶦˡᵉ ᶦʲᵒ ᶠᵘⁿ ᵉˢᶦⁿ' ᵇᶦᵏᵒˢᵉ ᶦᵇᶦᵗᶦ ᵃ ᵗᶦ ⁿᶠᶦ ᶦᶠᵉ ᴼˡᵒʳᵘⁿ ᵍᵇᵉ ᵖᵉˡᵘ ᵃᵗᶦ ˢᵉ ᵃᵐᵒʲᵘᵗᵒ ᵃʷᵒⁿ ᵉⁿᶦʸᵃⁿ ᵗᶦ ᵏᵒ ʳᵒʳᵘⁿ ˡᵃᵗᶦ ᵐᵃᵃ ᵇᵃ ᵍᵇᵉ˙ ᴬʷᵒⁿ ᵉⁿᶦᵗᶦ ᵃʸᵉ' ᴱˢᵘ ᵗᵃᵇᶦ ᵉˢᵉ ⁿᵖᵒⁿ ˡᵒʲᵘ˙
‎ᴶᵉˢᵘ ᴷʳᶦˢᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵃ ⁿᶦ ᴼˡᵘᵍᵇᵃˡᵃ ᵃᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵒˢᵃⁿ ʷᵒⁿ' ⁿᶦᵖᵃˢᵉ ᵃʷᵒⁿ ᴼʳᵒ ᴿᵉ ᵇᶦ ᶦʳᵘ ᵉʸᶦ˙

‎𝙵ú𝚗 à𝚕à𝚢é 𝚝à𝚋í ì𝚋éè𝚛è, ę 𝚙è 𝚝à𝚋í 𝚝ę 𝚊𝚝ę𝚓𝚒șę 𝚢í𝚗 𝚜𝚒:

‎📱07038226570.
‎📩 [email protected]

‎̷є̣ ѕὶ ℓєє̀ кὰη ѕὶ ωα ηί:

‎IBUDO~ẸRI KRISTI
‎(ɪʟᴇ ᴍᴀᴀʏᴇ), ABÚLÉ ÒGOBÌ-ỌJÀ,
‎ʟᴇ̣ʜɪɴ ᴏ̣ɢʙᴀ ʀᴇᴅᴇᴇᴍᴇʀ'ᴤ ᴜɴɪᴠᴇʀᴤɪᴛʏ, ẸDẸ, NI IPINLẸ ỌSUN, NIGERIA.

‎Olúwa yóò máa bùkún fun yín.

‎Njẹ HANNA, ON NSỌ̀RỌ LI ỌKÀN RẸ̀; KÌKÌ ÈTÈ RẸ̀ LI O NMÌ, ṢUGBỌN A KÒ GBỌ́ OHÙN RẸ̀: nitorina ni Eli fi rò pe, o mu ọti-...
21/11/2025

‎Njẹ HANNA, ON NSỌ̀RỌ LI ỌKÀN RẸ̀; KÌKÌ ÈTÈ RẸ̀ LI O NMÌ, ṢUGBỌN A KÒ GBỌ́ OHÙN RẸ̀: nitorina ni Eli fi rò pe, o mu ọti-waini yó. [14] Eli si wi fun u pe, Iwọ o ti mu ọti-waini pẹ to? mu ọti-waini rẹ kuro lọdọ rẹ. [15] Hanna si dahun wipe, BẸ́Ẹ̀KỌ́, OLUWA MI, EMI LI OBINRIN ONIROBINUJẸ ỌKÀN: EMI KÒ MU ỌTI-WAINI TABI OTI LILE, ṢUGBỌN ỌKÀN MI LI EMI NTÚ JADE NIWAJU OLUWA. [16] Má ṣe ka iranṣẹbinrin rẹ si ọmọbinrin Beliali: nitoripe ninu ọ̀pọlọpọ irò ati ibinujẹ inu mi ni mo ti nsọ disisiyi.

‎- I. Sam 1:13-16 YBCV

‎🔥🔥🔥🔥🔥🔥🔥

‎Ẹ ṣeun púpọ̀ tí ẹ yà sí ìhín yìí.

‎Jo̧wo̧ mase fi igbala rẹ da ọla.

‎Bi iwọ kò ba i ti ṣe bẹẹ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, tete fi aiye rẹ fun Jesu Kristi Oluwa loni yii. Nítorípé, ọla leè pẹ ju fún ọ.

‎⏪⏪⏪⏪⏩⏩⏩⏩

‎ᴵˡᵉ ᶦˢᵉ ᶦʳᵃⁿˢᵉ ʸᶦᶦ' ᵏᶦ ᶦ ˢᵉ ᶦᵈᵃˢᶦˡᵉ ᶦʲᵒ ᶠᵘⁿ ᵉˢᶦⁿ' ᵇᶦᵏᵒˢᵉ ᶦᵇᶦᵗᶦ ᵃ ᵗᶦ ⁿᶠᶦ ᶦᶠᵉ ᴼˡᵒʳᵘⁿ ᵍᵇᵉ ᵖᵉˡᵘ ᵃᵗᶦ ˢᵉ ᵃᵐᵒʲᵘᵗᵒ ᵃʷᵒⁿ ᵉⁿᶦʸᵃⁿ ᵗᶦ ᵏᵒ ʳᵒʳᵘⁿ ˡᵃᵗᶦ ᵐᵃᵃ ᵇᵃ ᵍᵇᵉ˙ ᴬʷᵒⁿ ᵉⁿᶦᵗᶦ ᵃʸᵉ' ᴱˢᵘ ᵗᵃᵇᶦ ᵉˢᵉ ⁿᵖᵒⁿ ˡᵒʲᵘ˙
‎ᴶᵉˢᵘ ᴷʳᶦˢᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵃ ⁿᶦ ᴼˡᵘᵍᵇᵃˡᵃ ᵃᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵒˢᵃⁿ ʷᵒⁿ' ⁿᶦᵖᵃˢᵉ ᵃʷᵒⁿ ᴼʳᵒ ᴿᵉ ᵇᶦ ᶦʳᵘ ᵉʸᶦ˙

‎𝙵ú𝚗 à𝚕à𝚢é 𝚝à𝚋í ì𝚋éè𝚛è, ę 𝚙è 𝚝à𝚋í 𝚝ę 𝚊𝚝ę𝚓𝚒șę 𝚢í𝚗 𝚜𝚒:

‎📱07038226570.
‎📩 [email protected]

‎̷є̣ ѕὶ ℓєє̀ кὰη ѕὶ ωα ηί:

‎IBUDO~ẸRI KRISTI
‎(ɪʟᴇ ᴍᴀᴀʏᴇ), ABÚLÉ ÒGOBÌ-ỌJÀ,
‎ʟᴇ̣ʜɪɴ ᴏ̣ɢʙᴀ ʀᴇᴅᴇᴇᴍᴇʀ'ᴤ ᴜɴɪᴠᴇʀᴤɪᴛʏ, ẸDẸ, NI IPINLẸ ỌSUN, NIGERIA.

‎Olúwa yóò máa bùkún fun yín.

‎Ṣugbọn ẹnikan yio wipe, Bawo li a o ha ji awọn okú dide? iru ara wo ni nwọn o pada si?  Iwọ alaimoye, ohun ti iwọ fọnru...
19/11/2025

‎Ṣugbọn ẹnikan yio wipe, Bawo li a o ha ji awọn okú dide? iru ara wo ni nwọn o pada si? Iwọ alaimoye, ohun ti iwọ fọnrugbin ki iyè bikoṣepe o ba kú: Ati eyiti iwọ fọnrugbin, ara ti mbọ̀ ki iwọ fọnrugbin, ṣugbọn irugbin lasan ni, ibã ṣe alikama, tabi irú miran. Ṣugbọn Ọlọrun fun u li ara bi o ti wù u, ati fun olukuluku irú ara tirẹ̀.
‎Gẹgẹ bẹ̃ si li ajinde okú. A gbìn i ni idibajẹ; a si jí i dide li aidibajẹ: A gbìn i li ainiyìn; a si jí i dide li ogo: a gbìn i li ailera, a si jí i dide li agbara: A gbìn i li ara iyara; a si jí i dide li ara ẹmí. Bi ara iyara ba mbẹ, ara ẹmí si mbẹ.

‎- I. Kor 15:35-38, 42-44 YBCV

‎🔥🔥🔥🔥🔥🔥🔥

‎Ẹ ṣeun púpọ̀ tí ẹ yà sí ìhín yìí.

‎Jo̧wo̧ mase fi igbala rẹ da ọla.

‎Bi iwọ kò ba i ti ṣe bẹẹ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, tete fi aiye rẹ fun Jesu Kristi Oluwa loni yii. Nítorípé, ọla leè pẹ ju fún ọ.

‎⏪⏪⏪⏪⏩⏩⏩⏩

‎ᴵˡᵉ ᶦˢᵉ ᶦʳᵃⁿˢᵉ ʸᶦᶦ' ᵏᶦ ᶦ ˢᵉ ᶦᵈᵃˢᶦˡᵉ ᶦʲᵒ ᶠᵘⁿ ᵉˢᶦⁿ' ᵇᶦᵏᵒˢᵉ ᶦᵇᶦᵗᶦ ᵃ ᵗᶦ ⁿᶠᶦ ᶦᶠᵉ ᴼˡᵒʳᵘⁿ ᵍᵇᵉ ᵖᵉˡᵘ ᵃᵗᶦ ˢᵉ ᵃᵐᵒʲᵘᵗᵒ ᵃʷᵒⁿ ᵉⁿᶦʸᵃⁿ ᵗᶦ ᵏᵒ ʳᵒʳᵘⁿ ˡᵃᵗᶦ ᵐᵃᵃ ᵇᵃ ᵍᵇᵉ˙ ᴬʷᵒⁿ ᵉⁿᶦᵗᶦ ᵃʸᵉ' ᴱˢᵘ ᵗᵃᵇᶦ ᵉˢᵉ ⁿᵖᵒⁿ ˡᵒʲᵘ˙
‎ᴶᵉˢᵘ ᴷʳᶦˢᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵃ ⁿᶦ ᴼˡᵘᵍᵇᵃˡᵃ ᵃᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵒˢᵃⁿ ʷᵒⁿ' ⁿᶦᵖᵃˢᵉ ᵃʷᵒⁿ ᴼʳᵒ ᴿᵉ ᵇᶦ ᶦʳᵘ ᵉʸᶦ˙

‎𝙵ú𝚗 à𝚕à𝚢é 𝚝à𝚋í ì𝚋éè𝚛è, ę 𝚙è 𝚝à𝚋í 𝚝ę 𝚊𝚝ę𝚓𝚒șę 𝚢í𝚗 𝚜𝚒:

‎📱07038226570.
‎📩 [email protected]

‎̷є̣ ѕὶ ℓєє̀ кὰη ѕὶ ωα ηί:

‎IBUDO~ẸRI KRISTI
‎(ɪʟᴇ ᴍᴀᴀʏᴇ), ABÚLÉ ÒGOBÌ-ỌJÀ,
‎ʟᴇ̣ʜɪɴ ᴏ̣ɢʙᴀ ʀᴇᴅᴇᴇᴍᴇʀ'ᴤ ᴜɴɪᴠᴇʀᴤɪᴛʏ, ẸDẸ, NI IPINLẸ ỌSUN, NIGERIA.

‎Olúwa yóò máa bùkún fun yín.

‎OBIRIN kan ninu awọn obinrin ọmọ awọn woli ke ba Eliṣa wipe, Iranṣẹ rẹ, ọkọ mi kú; iwọ si mọ̀ pe iranṣẹ rẹ bẹ̀ru Oluwa:...
16/11/2025

‎OBIRIN kan ninu awọn obinrin ọmọ awọn woli ke ba Eliṣa wipe, Iranṣẹ rẹ, ọkọ mi kú; iwọ si mọ̀ pe iranṣẹ rẹ bẹ̀ru Oluwa: awọn onigbèse si wá lati mu awọn ọmọ mi mejeji li ẹrú. Eliṣa si wi fun u pe, Kini emi o ṣe fun ọ? Wi fun mi, KINI IWỌ NI NINU ILE? ON SI WIPE, IRANṢẸBINRIN RẸ KÒ NI NKANKAN NI ILE, BIKÒṢE IKÒKO ORORO KAN. ON SI WIPE, LỌ, KI IWỌ KI O YÁ ÌKÒKÒ LỌWỌ ÀWỌN ALADUGBO RẸ KAKIRI, ÀNÍ ÌKÒKÒ OFO; YÁ WỌN, KÌ IṢE DIẸ. Nigbati iwọ ba si wọle, ki iwọ ki o se ilẹ̀kun mọ ara rẹ, ati mọ awọn ọmọ rẹ, ki o si dà a sinu gbogbo ikòko wọnni, ki iwọ ki o si fi eyiti o kún si apakan. O si lọ kuro lọdọ rẹ̀, o si se ilẹ̀kun mọ ara rẹ̀ ati mọ awọn ọmọ rẹ̀, ti ngbe ikòko fun u wá; on si dà a. O si ṣe, nigbati awọn ikòko kún, o wi fun ọmọ rẹ̀ pe, Tun mu ikòko kan fun mi wá. On si wi fun u pe, Kò si ikòko kan mọ. Ororo na si da. Nigbana li o wá, o si sọ fun enia Ọlọrun na. On si wipe, Lọ, tà ororo na, ki o si san gbèse rẹ, ki iwọ ati awọn ọmọ rẹ ki o si jẹ eyi ti o kù. *¹

‎"Peteru wipe, Fadakà ati wura emi kò ni; ṣugbọn ohun ti mo ni eyini ni mo fifun ọ: Li orukọ Jesu Kristi ti Nasareti, dide ki o si mã rin." *²

‎"Jesu si wi fun wọn pe, Nitori aigbagbọ́ nyin ni: lõtọ ni mo sá wi fun nyin, Bi ẹnyin ba ni igbagbọ́ bi wóro irúgbin mustardi, ẹnyin o wi fun òke yi pe, Ṣi nihin lọ si ọ̀hun, yio si ṣi; kò si si nkan ti ẹ ki yio le ṣe." *³

‎- *¹ II. A. Ọba 4:1-7, *² Iṣe Apo 3:6, *³ Mat 17:20 YBCV

‎🔥🔥🔥🔥🔥🔥🔥

‎Ẹ ṣeun púpọ̀ tí ẹ yà sí ìhín yìí.

‎Jo̧wo̧ mase fi igbala rẹ da ọla.

‎Bi iwọ kò ba i ti ṣe bẹẹ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, tete fi aiye rẹ fun Jesu Kristi Oluwa loni yii. Nítorípé, ọla leè pẹ ju fún ọ.

‎⏪⏪⏪⏪⏩⏩⏩⏩

‎ᴵˡᵉ ᶦˢᵉ ᶦʳᵃⁿˢᵉ ʸᶦᶦ' ᵏᶦ ᶦ ˢᵉ ᶦᵈᵃˢᶦˡᵉ ᶦʲᵒ ᶠᵘⁿ ᵉˢᶦⁿ' ᵇᶦᵏᵒˢᵉ ᶦᵇᶦᵗᶦ ᵃ ᵗᶦ ⁿᶠᶦ ᶦᶠᵉ ᴼˡᵒʳᵘⁿ ᵍᵇᵉ ᵖᵉˡᵘ ᵃᵗᶦ ˢᵉ ᵃᵐᵒʲᵘᵗᵒ ᵃʷᵒⁿ ᵉⁿᶦʸᵃⁿ ᵗᶦ ᵏᵒ ʳᵒʳᵘⁿ ˡᵃᵗᶦ ᵐᵃᵃ ᵇᵃ ᵍᵇᵉ˙ ᴬʷᵒⁿ ᵉⁿᶦᵗᶦ ᵃʸᵉ' ᴱˢᵘ ᵗᵃᵇᶦ ᵉˢᵉ ⁿᵖᵒⁿ ˡᵒʲᵘ˙
‎ᴶᵉˢᵘ ᴷʳᶦˢᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵃ ⁿᶦ ᴼˡᵘᵍᵇᵃˡᵃ ᵃᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵒˢᵃⁿ ʷᵒⁿ' ⁿᶦᵖᵃˢᵉ ᵃʷᵒⁿ ᴼʳᵒ ᴿᵉ ᵇᶦ ᶦʳᵘ ᵉʸᶦ˙

‎𝙵ú𝚗 à𝚕à𝚢é 𝚝à𝚋í ì𝚋éè𝚛è, ę 𝚙è 𝚝à𝚋í 𝚝ę 𝚊𝚝ę𝚓𝚒șę 𝚢í𝚗 𝚜𝚒:

‎📱07038226570.
‎📩 [email protected]

‎̷є̣ ѕὶ ℓєє̀ кὰη ѕὶ ωα ηί:

‎IBUDO~ẸRI KRISTI
‎(ɪʟᴇ ᴍᴀᴀʏᴇ), ABÚLÉ ÒGOBÌ-ỌJÀ,
‎ʟᴇ̣ʜɪɴ ᴏ̣ɢʙᴀ ʀᴇᴅᴇᴇᴍᴇʀ'ᴤ ᴜɴɪᴠᴇʀᴤɪᴛʏ, ẸDẸ, NI IPINLẸ ỌSUN, NIGERIA.

‎Olúwa yóò máa bùkún fun yín.

14/11/2025
‎Nigbati awọn enia si ri ohun ti Paulu ṣe, nwọn gbé ohùn wọn soke li ède Likaonia, wipe, Awọn oriṣa sọkalẹ tọ̀ wa wá ni ...
11/11/2025

‎Nigbati awọn enia si ri ohun ti Paulu ṣe, nwọn gbé ohùn wọn soke li ède Likaonia, wipe, Awọn oriṣa sọkalẹ tọ̀ wa wá ni àwọ enia. Nwọn si pè Barnaba ni Jupiteri ati Paulu ni Herme nitori on li olori ọ̀rọ isọ. Alufa Jupiteri ti ile oriṣa rẹ̀ wà niwaju ilu wọn, si mu malu ati màriwo wá si ẹnubode, on iba si rubọ pẹlu awọn enia. Ṣugbọn nigbati awọn aposteli Barnaba on Paulu gbọ́, nwọn fà aṣọ wọn ya, nwọn si sure wọ̀ inu awujọ, nwọn nke rara. Nwọn si nwipe, Ará, ẽṣe ti ẹnyin fi nṣe nkan wọnyi? Enia oniru ìwa kanna bi ẹnyin li awa pẹlu ti a nwasu ihinrere fun nyin, ki ẹnyin ki o yipada kuro ninu ohun asan wọnyi si Ọlọrun alãye, ti o da ọrun on aiye, ati okun, ati ohun gbogbo ti mbẹ ninu wọn:

‎- Iṣe Apo 14:11-15 YBCV

‎🔥🔥🔥🔥🔥🔥🔥

‎Ẹ ṣeun púpọ̀ tí ẹ yà sí ìhín yìí.

‎Jo̧wo̧ mase fi igbala rẹ da ọla.

‎Bi iwọ kò ba i ti ṣe bẹẹ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, tete fi aiye rẹ fun Jesu Kristi Oluwa loni yii. Nítorípé, ọla leè pẹ ju fún ọ.

‎⏪⏪⏪⏪⏩⏩⏩⏩

‎ᴵˡᵉ ᶦˢᵉ ᶦʳᵃⁿˢᵉ ʸᶦᶦ' ᵏᶦ ᶦ ˢᵉ ᶦᵈᵃˢᶦˡᵉ ᶦʲᵒ ᶠᵘⁿ ᵉˢᶦⁿ' ᵇᶦᵏᵒˢᵉ ᶦᵇᶦᵗᶦ ᵃ ᵗᶦ ⁿᶠᶦ ᶦᶠᵉ ᴼˡᵒʳᵘⁿ ᵍᵇᵉ ᵖᵉˡᵘ ᵃᵗᶦ ˢᵉ ᵃᵐᵒʲᵘᵗᵒ ᵃʷᵒⁿ ᵉⁿᶦʸᵃⁿ ᵗᶦ ᵏᵒ ʳᵒʳᵘⁿ ˡᵃᵗᶦ ᵐᵃᵃ ᵇᵃ ᵍᵇᵉ˙ ᴬʷᵒⁿ ᵉⁿᶦᵗᶦ ᵃʸᵉ' ᴱˢᵘ ᵗᵃᵇᶦ ᵉˢᵉ ⁿᵖᵒⁿ ˡᵒʲᵘ˙
‎ᴶᵉˢᵘ ᴷʳᶦˢᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵃ ⁿᶦ ᴼˡᵘᵍᵇᵃˡᵃ ᵃᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵒˢᵃⁿ ʷᵒⁿ' ⁿᶦᵖᵃˢᵉ ᵃʷᵒⁿ ᴼʳᵒ ᴿᵉ ᵇᶦ ᶦʳᵘ ᵉʸᶦ˙

‎𝙵ú𝚗 à𝚕à𝚢é 𝚝à𝚋í ì𝚋éè𝚛è, ę 𝚙è 𝚝à𝚋í 𝚝ę 𝚊𝚝ę𝚓𝚒șę 𝚢í𝚗 𝚜𝚒:

‎📱07038226570.
‎📩 [email protected]

‎̷є̣ ѕὶ ℓєє̀ кὰη ѕὶ ωα ηί:

‎IBUDO~ẸRI KRISTI
‎(ɪʟᴇ ᴍᴀᴀʏᴇ), ABÚLÉ ÒGOBÌ-ỌJÀ,
‎ʟᴇ̣ʜɪɴ ᴏ̣ɢʙᴀ ʀᴇᴅᴇᴇᴍᴇʀ'ᴤ ᴜɴɪᴠᴇʀᴤɪᴛʏ, ẸDẸ, NI IPINLẸ ỌSUN, NIGERIA.

‎Olúwa yóò máa bùkún fun yín.

‎‎"Bẹ̃li o tọ́ ki awọn ọkunrin ki o mã fẹràn awọn aya wọn gẹgẹ bi ara awọn tikarawọn. Ẹniti o ba fẹran aya rẹ̀, o fẹran ...
08/11/2025

‎"Bẹ̃li o tọ́ ki awọn ọkunrin ki o mã fẹràn awọn aya wọn gẹgẹ bi ara awọn tikarawọn. Ẹniti o ba fẹran aya rẹ̀, o fẹran on tikararẹ̀. Nitori kò si ẹnikan ti o ti korira ara rẹ̀; bikoṣepe ki o mã bọ́ ọ ki o si mã ṣikẹ rẹ̀ gẹgẹ bi Kristi si ti nṣe si ìjọ."

‎- Efesu 5:28-29 YBCV

‎🔥🔥🔥🔥🔥🔥🔥

‎Ẹ ṣeun púpọ̀ tí ẹ yà sí ìhín yìí.

‎Jo̧wo̧ mase fi igbala rẹ da ọla.

‎Bi iwọ kò ba i ti ṣe bẹẹ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, tete fi aiye rẹ fun Jesu Kristi Oluwa loni yii. Nítorípé, ọla leè pẹ ju fún ọ.

‎⏪⏪⏪⏪⏩⏩⏩⏩

‎ᴵˡᵉ ᶦˢᵉ ᶦʳᵃⁿˢᵉ ʸᶦᶦ' ᵏᶦ ᶦ ˢᵉ ᶦᵈᵃˢᶦˡᵉ ᶦʲᵒ ᶠᵘⁿ ᵉˢᶦⁿ' ᵇᶦᵏᵒˢᵉ ᶦᵇᶦᵗᶦ ᵃ ᵗᶦ ⁿᶠᶦ ᶦᶠᵉ ᴼˡᵒʳᵘⁿ ᵍᵇᵉ ᵖᵉˡᵘ ᵃᵗᶦ ˢᵉ ᵃᵐᵒʲᵘᵗᵒ ᵃʷᵒⁿ ᵉⁿᶦʸᵃⁿ ᵗᶦ ᵏᵒ ʳᵒʳᵘⁿ ˡᵃᵗᶦ ᵐᵃᵃ ᵇᵃ ᵍᵇᵉ˙ ᴬʷᵒⁿ ᵉⁿᶦᵗᶦ ᵃʸᵉ' ᴱˢᵘ ᵗᵃᵇᶦ ᵉˢᵉ ⁿᵖᵒⁿ ˡᵒʲᵘ˙
‎ᴶᵉˢᵘ ᴷʳᶦˢᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵃ ⁿᶦ ᴼˡᵘᵍᵇᵃˡᵃ ᵃᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵒˢᵃⁿ ʷᵒⁿ' ⁿᶦᵖᵃˢᵉ ᵃʷᵒⁿ ᴼʳᵒ ᴿᵉ ᵇᶦ ᶦʳᵘ ᵉʸᶦ˙

‎𝙵ú𝚗 à𝚕à𝚢é 𝚝à𝚋í ì𝚋éè𝚛è, ę 𝚙è 𝚝à𝚋í 𝚝ę 𝚊𝚝ę𝚓𝚒șę 𝚢í𝚗 𝚜𝚒:

‎📱07038226570.
‎📩 [email protected]

‎̷є̣ ѕὶ ℓєє̀ кὰη ѕὶ ωα ηί:

‎IBUDO~ẸRI KRISTI
‎(ɪʟᴇ ᴍᴀᴀʏᴇ), ABÚLÉ ÒGOBÌ-ỌJÀ,
‎ʟᴇ̣ʜɪɴ ᴏ̣ɢʙᴀ ʀᴇᴅᴇᴇᴍᴇʀ'ᴤ ᴜɴɪᴠᴇʀᴤɪᴛʏ, ẸDẸ, NI IPINLẸ ỌSUN, NIGERIA.

‎Olúwa yóò máa bùkún fun yín.

‎‎Bákan náà ni kí ẹ̀yin aya máa bọ̀wọ̀ fún àwọn ọkọ yín. Ìdí rẹ̀ ni pé bí a bá rí ninu àwọn ọkọ tí kò jẹ́ onigbagbọ, wọ́...
04/11/2025

‎Bákan náà ni kí ẹ̀yin aya máa bọ̀wọ̀ fún àwọn ọkọ yín. Ìdí rẹ̀ ni pé bí a bá rí ninu àwọn ọkọ tí kò jẹ́ onigbagbọ, wọ́n lè yipada nípa ìwà ẹ̀yin aya wọn láìjẹ́ pé ẹ bá wọn sọ gbolohun kan nípa ẹ̀sìn igbagbọ, nígbà tí wọ́n bá ṣe akiyesi ìwà mímọ́ ati ìwà ọmọlúwàbí yín. Ẹwà yín kò gbọdọ̀ jẹ́ ti òde ara nìkan bíi ti irun-dídì, ati nǹkan ọ̀ṣọ́ wúrà tí ẹ kó sára ati aṣọ-ìgbà. Ṣugbọn kí ẹwà yín jẹ́ ti ọkàn tí kò hàn sóde, ọkàn ìrẹ̀lẹ̀ ati ìwà pẹ̀lẹ́. Èyí ni ẹwà tí kò lè ṣá, èyí tí ó ṣe iyebíye lójú Ọlọrun. Nítorí ní ìgbà àtijọ́ irú ẹwà báyìí ni àwọn aya tí a yà sọ́tọ̀, àwọn tí wọ́n ní ìrètí ninu Ọlọrun, fi ṣe ara wọn lọ́ṣọ̀ọ́. Wọ́n bọ̀wọ̀ fún ọkọ wọn. Irú wọn ni Sara tí ó gbọ́ràn sí Abrahamu lẹ́nu tí ó pè é ní “Oluwa mi.” Ọmọ Sara ni yín, tí ẹ bá ń ṣe dáradára, tí ẹ kò jẹ́ kí nǹkankan bà yín lẹ́rù tabi kí ó mú ìpayà ba yín.

‎- PETERU KINNI 3:1-6 YCE

‎🔥🔥🔥🔥🔥🔥🔥

‎Ẹ ṣeun púpọ̀ tí ẹ yà sí ìhín yìí.

‎Jo̧wo̧ mase fi igbala rẹ da ọla.

‎Bi iwọ kò ba i ti ṣe bẹẹ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, tete fi aiye rẹ fun Jesu Kristi Oluwa loni yii. Nítorípé, ọla leè pẹ ju fún ọ.

‎⏪⏪⏪⏪⏩⏩⏩⏩

‎ᴵˡᵉ ᶦˢᵉ ᶦʳᵃⁿˢᵉ ʸᶦᶦ' ᵏᶦ ᶦ ˢᵉ ᶦᵈᵃˢᶦˡᵉ ᶦʲᵒ ᶠᵘⁿ ᵉˢᶦⁿ' ᵇᶦᵏᵒˢᵉ ᶦᵇᶦᵗᶦ ᵃ ᵗᶦ ⁿᶠᶦ ᶦᶠᵉ ᴼˡᵒʳᵘⁿ ᵍᵇᵉ ᵖᵉˡᵘ ᵃᵗᶦ ˢᵉ ᵃᵐᵒʲᵘᵗᵒ ᵃʷᵒⁿ ᵉⁿᶦʸᵃⁿ ᵗᶦ ᵏᵒ ʳᵒʳᵘⁿ ˡᵃᵗᶦ ᵐᵃᵃ ᵇᵃ ᵍᵇᵉ˙ ᴬʷᵒⁿ ᵉⁿᶦᵗᶦ ᵃʸᵉ' ᴱˢᵘ ᵗᵃᵇᶦ ᵉˢᵉ ⁿᵖᵒⁿ ˡᵒʲᵘ˙
‎ᴶᵉˢᵘ ᴷʳᶦˢᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵃ ⁿᶦ ᴼˡᵘᵍᵇᵃˡᵃ ᵃᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵒˢᵃⁿ ʷᵒⁿ' ⁿᶦᵖᵃˢᵉ ᵃʷᵒⁿ ᴼʳᵒ ᴿᵉ ᵇᶦ ᶦʳᵘ ᵉʸᶦ˙

‎𝙵ú𝚗 à𝚕à𝚢é 𝚝à𝚋í ì𝚋éè𝚛è, ę 𝚙è 𝚝à𝚋í 𝚝ę 𝚊𝚝ę𝚓𝚒șę 𝚢í𝚗 𝚜𝚒:

‎📱07038226570.
‎📩 [email protected]

‎̷є̣ ѕὶ ℓєє̀ кὰη ѕὶ ωα ηί:

‎IBUDO~ẸRI KRISTI
‎(ɪʟᴇ ᴍᴀᴀʏᴇ), ABÚLÉ ÒGOBÌ-ỌJÀ,
‎ʟᴇ̣ʜɪɴ ᴏ̣ɢʙᴀ ʀᴇᴅᴇᴇᴍᴇʀ'ᴤ ᴜɴɪᴠᴇʀᴤɪᴛʏ, ẸDẸ, NI IPINLẸ ỌSUN, NIGERIA.

‎Olúwa yóò máa bùkún fun yín.

"Oluwa si wi fun mi pe, iwọ riran rere, nitori ti emi o kiye si ọ̀rọ mi lati mu u ṣẹ." *¹"Nitori gẹgẹ bi òjo ati ojo-did...
02/11/2025

"Oluwa si wi fun mi pe, iwọ riran rere, nitori ti emi o kiye si ọ̀rọ mi lati mu u ṣẹ." *¹

"Nitori gẹgẹ bi òjo ati ojo-didì ti iti ọrun wá ilẹ, ti kì isi tun pada sọhun, ṣugbọn ti o nrin ilẹ, ti o si nmu nkan hù jade ki o si rudi, ki o le fi irú fun awọn afúnrúgbìn, ati onjẹ fun ọjẹun: Bẹ̃ni ọ̀rọ mi ti o ti ẹnu mi jade yio ri: kì yio pada sọdọ mi lofo, ṣugbọn yio ṣe eyiti o wù mi, yio si ma ṣe rere ninu ohun ti mo rán a." *²

"RÁN MI LETI: KI A JUMỌ SỌ Ọ; IWỌ RÒ, KÍ A LE DA Ọ LÁRE." *³

- *¹ Jer 1:12, *² Isa 55:10-11, *³ Isa 43:26 YBCV

🔥🔥🔥🔥🔥🔥🔥

Ẹ ṣeun púpọ̀ tí ẹ yà sí ìhín yìí.

Jo̧wo̧ mase fi igbala rẹ da ọla.

Bi iwọ kò ba i ti ṣe bẹẹ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, tete fi aiye rẹ fun Jesu Kristi Oluwa loni yii. Nítorípé, ọla leè pẹ ju fún ọ.

⏪⏪⏪⏪⏩⏩⏩⏩

ᴵˡᵉ ᶦˢᵉ ᶦʳᵃⁿˢᵉ ʸᶦᶦ' ᵏᶦ ᶦ ˢᵉ ᶦᵈᵃˢᶦˡᵉ ᶦʲᵒ ᶠᵘⁿ ᵉˢᶦⁿ' ᵇᶦᵏᵒˢᵉ ᶦᵇᶦᵗᶦ ᵃ ᵗᶦ ⁿᶠᶦ ᶦᶠᵉ ᴼˡᵒʳᵘⁿ ᵍᵇᵉ ᵖᵉˡᵘ ᵃᵗᶦ ˢᵉ ᵃᵐᵒʲᵘᵗᵒ ᵃʷᵒⁿ ᵉⁿᶦʸᵃⁿ ᵗᶦ ᵏᵒ ʳᵒʳᵘⁿ ˡᵃᵗᶦ ᵐᵃᵃ ᵇᵃ ᵍᵇᵉ˙ ᴬʷᵒⁿ ᵉⁿᶦᵗᶦ ᵃʸᵉ' ᴱˢᵘ ᵗᵃᵇᶦ ᵉˢᵉ ⁿᵖᵒⁿ ˡᵒʲᵘ˙
ᴶᵉˢᵘ ᴷʳᶦˢᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵃ ⁿᶦ ᴼˡᵘᵍᵇᵃˡᵃ ᵃᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵒˢᵃⁿ ʷᵒⁿ' ⁿᶦᵖᵃˢᵉ ᵃʷᵒⁿ ᴼʳᵒ ᴿᵉ ᵇᶦ ᶦʳᵘ ᵉʸᶦ˙

𝙵ú𝚗 à𝚕à𝚢é 𝚝à𝚋í ì𝚋éè𝚛è, ę 𝚙è 𝚝à𝚋í 𝚝ę 𝚊𝚝ę𝚓𝚒șę 𝚢í𝚗 𝚜𝚒:

📱07038226570.
📩 [email protected]

̷є̣ ѕὶ ℓєє̀ кὰη ѕὶ ωα ηί:

IBUDO~ẸRI KRISTI
(ɪʟᴇ ᴍᴀᴀʏᴇ), ABÚLÉ ÒGOBÌ-ỌJÀ,
ʟᴇ̣ʜɪɴ ᴏ̣ɢʙᴀ ʀᴇᴅᴇᴇᴍᴇʀ'ᴤ ᴜɴɪᴠᴇʀᴤɪᴛʏ, ẸDẸ, NI IPINLẸ ỌSUN, NIGERIA.

Olúwa yóò máa bùkún fun yín.

Ohun kan yi sa da mi loju, pe ẹniti o ti bẹ̀rẹ iṣẹ rere ninu nyin, yio ṣe aṣepe rẹ̀ t**i fi di ọjọ Jesu Kristi: *¹"Ẹ máṣ...
31/10/2025

Ohun kan yi sa da mi loju, pe ẹniti o ti bẹ̀rẹ iṣẹ rere ninu nyin, yio ṣe aṣepe rẹ̀ t**i fi di ọjọ Jesu Kristi: *¹

"Ẹ máṣe ranti nkan ti iṣaju mọ, ati nkan ti atijọ, ẹ máṣe rò wọn. Kiyesi i, emi o ṣe ohun titun kan; nisisiyi ni yio hù jade; ẹnyin ki yio mọ̀ ọ bi? lõtọ, emi o là ọ̀na kan ninu aginju, ati odò li aṣalẹ̀." *²

- *¹ Filipi 1:6 YBCV, *² Isa 43:18-19 YBCV

🔥🔥🔥🔥🔥🔥🔥

Ẹ ṣeun púpọ̀ tí ẹ yà sí ìhín yìí.

Jo̧wo̧ mase fi igbala rẹ da ọla.

Bi iwọ kò ba i ti ṣe bẹẹ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, tete fi aiye rẹ fun Jesu Kristi Oluwa loni yii. Nítorípé, ọla leè pẹ ju fún ọ.

⏪⏪⏪⏪⏩⏩⏩⏩

ᴵˡᵉ ᶦˢᵉ ᶦʳᵃⁿˢᵉ ʸᶦᶦ' ᵏᶦ ᶦ ˢᵉ ᶦᵈᵃˢᶦˡᵉ ᶦʲᵒ ᶠᵘⁿ ᵉˢᶦⁿ' ᵇᶦᵏᵒˢᵉ ᶦᵇᶦᵗᶦ ᵃ ᵗᶦ ⁿᶠᶦ ᶦᶠᵉ ᴼˡᵒʳᵘⁿ ᵍᵇᵉ ᵖᵉˡᵘ ᵃᵗᶦ ˢᵉ ᵃᵐᵒʲᵘᵗᵒ ᵃʷᵒⁿ ᵉⁿᶦʸᵃⁿ ᵗᶦ ᵏᵒ ʳᵒʳᵘⁿ ˡᵃᵗᶦ ᵐᵃᵃ ᵇᵃ ᵍᵇᵉ˙ ᴬʷᵒⁿ ᵉⁿᶦᵗᶦ ᵃʸᵉ' ᴱˢᵘ ᵗᵃᵇᶦ ᵉˢᵉ ⁿᵖᵒⁿ ˡᵒʲᵘ˙
ᴶᵉˢᵘ ᴷʳᶦˢᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵃ ⁿᶦ ᴼˡᵘᵍᵇᵃˡᵃ ᵃᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵒˢᵃⁿ ʷᵒⁿ' ⁿᶦᵖᵃˢᵉ ᵃʷᵒⁿ ᴼʳᵒ ᴿᵉ ᵇᶦ ᶦʳᵘ ᵉʸᶦ˙

𝙵ú𝚗 à𝚕à𝚢é 𝚝à𝚋í ì𝚋éè𝚛è, ę 𝚙è 𝚝à𝚋í 𝚝ę 𝚊𝚝ę𝚓𝚒șę 𝚢í𝚗 𝚜𝚒:

📱07038226570.
📩 [email protected]

̷є̣ ѕὶ ℓєє̀ кὰη ѕὶ ωα ηί:

IBUDO~ẸRI KRISTI
(ɪʟᴇ ᴍᴀᴀʏᴇ), ABÚLÉ ÒGOBÌ-ỌJÀ,
ʟᴇ̣ʜɪɴ ᴏ̣ɢʙᴀ ʀᴇᴅᴇᴇᴍᴇʀ'ᴤ ᴜɴɪᴠᴇʀᴤɪᴛʏ, ẸDẸ, NI IPINLẸ ỌSUN, NIGERIA.

Olúwa yóò máa bùkún fun yín.

"Alufa na si wipe, idà Goliati ara Filistini ti iwọ pa li afonifoji Ela ni mbẹ, wõ, a fi aṣọ kan wé e lẹhin Efodu; bi iw...
27/10/2025

"Alufa na si wipe, idà Goliati ara Filistini ti iwọ pa li afonifoji Ela ni mbẹ, wõ, a fi aṣọ kan wé e lẹhin Efodu; bi iwọ o ba mu eyini, mu u; kò si si omiran nihin mọ bikoṣe ọkanna. Dafidi si wipe, Kò si eyiti o dabi rẹ̀, fun mi."

"Ṣugbọn oju Peteru ati ti awọn ti mbẹ lọdọ rẹ̀ wuwo fun õrun. Nigbati nwọn si tají, nwọn ri ogo rẹ̀, ati ti awọn ọkunrin mejeji ti o ba a duro. O si ṣe, nigbati nwọn lọ kuro lọdọ rẹ̀, Peteru wi fun Jesu pe, Olukọni, o dara fun wa ki a mã gbé ihinyi: jẹ ki awa ki o pa agọ́ mẹta; ọkan fun iwọ, ati ọkan fun Mose, ati ọkan fun Elijah: KÒ MỌ̀ EYI TI O NWI."

- *¹ I. Sam 21:9 YBCV, *² Luku 9:32-33 YBCV.

🔥🔥🔥🔥🔥🔥🔥

Ẹ ṣeun púpọ̀ tí ẹ yà sí ìhín yìí.

Jo̧wo̧ mase fi igbala rẹ da ọla.

Bi iwọ kò ba i ti ṣe bẹẹ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀, tete fi aiye rẹ fun Jesu Kristi Oluwa loni yii. Nítorípé, ọla leè pẹ ju fún ọ.

⏪⏪⏪⏪⏩⏩⏩⏩

ᴵˡᵉ ᶦˢᵉ ᶦʳᵃⁿˢᵉ ʸᶦᶦ' ᵏᶦ ᶦ ˢᵉ ᶦᵈᵃˢᶦˡᵉ ᶦʲᵒ ᶠᵘⁿ ᵉˢᶦⁿ' ᵇᶦᵏᵒˢᵉ ᶦᵇᶦᵗᶦ ᵃ ᵗᶦ ⁿᶠᶦ ᶦᶠᵉ ᴼˡᵒʳᵘⁿ ᵍᵇᵉ ᵖᵉˡᵘ ᵃᵗᶦ ˢᵉ ᵃᵐᵒʲᵘᵗᵒ ᵃʷᵒⁿ ᵉⁿᶦʸᵃⁿ ᵗᶦ ᵏᵒ ʳᵒʳᵘⁿ ˡᵃᵗᶦ ᵐᵃᵃ ᵇᵃ ᵍᵇᵉ˙ ᴬʷᵒⁿ ᵉⁿᶦᵗᶦ ᵃʸᵉ' ᴱˢᵘ ᵗᵃᵇᶦ ᵉˢᵉ ⁿᵖᵒⁿ ˡᵒʲᵘ˙
ᴶᵉˢᵘ ᴷʳᶦˢᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵃ ⁿᶦ ᴼˡᵘᵍᵇᵃˡᵃ ᵃᵗᶦ ᴼˡᵘʷᵒˢᵃⁿ ʷᵒⁿ' ⁿᶦᵖᵃˢᵉ ᵃʷᵒⁿ ᴼʳᵒ ᴿᵉ ᵇᶦ ᶦʳᵘ ᵉʸᶦ˙

𝙵ú𝚗 à𝚕à𝚢é 𝚝à𝚋í ì𝚋éè𝚛è, ę 𝚙è 𝚝à𝚋í 𝚝ę 𝚊𝚝ę𝚓𝚒șę 𝚢í𝚗 𝚜𝚒:

📱07038226570.
📩 [email protected]

̷є̣ ѕὶ ℓєє̀ кὰη ѕὶ ωα ηί:

IBUDO~ẸRI KRISTI
(ɪʟᴇ ᴍᴀᴀʏᴇ), ABÚLÉ ÒGOBÌ-ỌJÀ,
ʟᴇ̣ʜɪɴ ᴏ̣ɢʙᴀ ʀᴇᴅᴇᴇᴍᴇʀ'ᴤ ᴜɴɪᴠᴇʀᴤɪᴛʏ, ẸDẸ, NI IPINLẸ ỌSUN, NIGERIA.

Olúwa yóò máa bùkún fun yín.

Address

OLOGOBI VILLAGE, OGOBI-OJA

Telephone

+2348052081016

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ìhìnrere Òtítọ́. posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Ìhìnrere Òtítọ́.:

  • Want your business to be the top-listed Media Company?

Share